Jokes Etc › Re: Working On Saturdays picture by farotika(m): 4:00pm On Dec 18, 2008 |
tytylayor: i dey wait o u go wait tire  |
Jokes Etc › Re: Mathematical Proof That Girls Are Evil! by farotika(m): 3:42pm On Dec 18, 2008 |
@ poster I'll give u 100% in this course. Up u  |
Culture › Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by farotika(m): 2:58pm On Dec 18, 2008 |
debosky: Iwa olodo wa lara tie no ogbeni goodaasi to pa jesu oyingbo nitori obo 
pepa ni won pe, kii se beba. se oro obo naa lo wa fa ki e ma soro bii dindirin ni? 
Kini itumo 'primary' ni ede Yoruba? E je ki n'fi to yi n'leti
Primary = ile iwe akeko ese keji.
Ti a ba fe juwe 'primary 4' nkan ti a o so ni ile iwe akeko ese keji apa kerin.
Oya e patewo fun mi.
Ogbeni Farotika, ko da ki e pe Alagba Sitivini ni Oponu o, ara n'yun won ni, won si fe f'owo pa omidan lara ni. Kii se ese fun agbalagba lati fe gbadun ara won. Eemo!  Emi ma ro pe goodaasi to pa Jesu ti ku ni; emi o mo pe o tun maa farahan ninu tireedi yii o. Yeeeepa! Nje mi o ti soro koja aye mi bayi. E joooooooo buroda Goodaasi, ti nba ti bu yin, e ma binu si mi o, omode lo nse mi. E jowo e ma pa mi be se pa Jesu o.  Buroda Ogbufo, E jowo, e tan imole die si itumo ti e fun puramari yen. Ko mu ogbon wa rara. Ni paapaa ese ikeji ti o wa ninu itumo yin ohun. Ewo ni ese kin ni  Yoruba o ni itumo fun primary. Ayalo ede ni won maa npe. Nitorinaa, won a maa lo ede yoruba lati pee bi oyinbo se npe. Fun apeere: Bread ni ede Yoruba a je: Buredi. Se o ye eyin omo mi? |
Culture › Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by farotika(m): 9:17am On Dec 18, 2008 |
goodass: mo n gbiyanju lati ranti ikan lara awon poem JF Odunjo ti mo ka ni Alawiye pamari 1, e jowo eni ti o ba moo ki o ran mi leti o:
Tepa mose ore mi ise ni a fi n deni giga bi a ko ba reni fehinti bi ole laa ri bi a ko ba reni gbekele a tera mose eni iya re le lowo lowor ki baba re lesin leekan bi o ba gboju le won o te tan ni mo sor fun o eko si tun n soni doga mura ki o kor or dara dara bi o si ri opo eniyan ti won n fi eko serin rin dakun mase fara we won iya n bor fomo ti ko gbon ekun n be fomo ti n sa kiri ma fowuro sere ore mi mura sise ojo n lo
Ibi kan wa ti o ti so pe
'baye ba n fe o loni . . .(can't rmbr again). . je ki o deni n rago ki o rii baye ti n yinmu si e. .
eni ti o ba moo, ki o sor e jowo  O gbiyanju gan ni o. Emi naa a ronu jinle lati le ranti awon ewi inu alawiye ti puramari. Je kin ronu ikan ooooooooooo, Iyan funfun balau owo bata egunsi aje boko doweke aje digbo loko aje boko rerin ofofo , gbegiri nikan lewo re , ati bee bee lo. |
Culture › Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by farotika(m): 9:12am On Dec 18, 2008 |
goodass: o gbiyanju gan ni Moyo, pamari 4 kweshun lasan ni o gbe lugi yen. patewo fun ra e!  Olodo rabata ni iwo alara. O ye ko so bayii: Ibeere ile iwe kerin puramari ni o gbe lugi. |
Family › Re: Absent Father: What Surname To Give A Child. by farotika(m): 7:31am On Dec 18, 2008 |
@ post, The kids should be allowed to bear their father's name whether is there or not. For God's sake, he is their father. Except the lady is not sure of the kids father. What about if the kids start asking questions 2morrow because of one thing or the other  |
Culture › Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by farotika(m): 4:02pm On Dec 17, 2008 |
chamotex: Ese modupe, ti e bale bami fi shepe ati opa eyin gan ranse simi, inu mi adun gan ni.
Gbogbo ibadi mi kan romi ni, bi eni wipe mo gbe irin ni . . . . . . . . Ese modupe! O ye mi ju bo se so lo. Kii se sepe ati opa eyin nikan ni mo maa fi ranse, sungbalaja ati sagbadiwere maa pelu komubinesan (combination) awon nkan ti mo maa fi ranse  Joo mo fi Olorun be o; ma do awon omo olomo pa ti ogun yi ba bere si sise o  Ti o ba si do ado fadiya, jowo mase daruko mi fun awon olopa o. O dabi wipe o fe wale fun odun Keresi; bi o ba jebe iwo saa ti fi adiresi re sowo simi  |
Culture › Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by farotika(m): 3:53pm On Dec 17, 2008 |
debosky: farotika
eebu o wa poju? Agbalagba ma ni ogbeni steven ti o nba soro bayen o! Ma je ki o fi enu agba sepe fun e o. Oya kunle ko toro idariji lowo alagba steven ki o ba le dara fun e lojo iwaju.  Buroda gbewudani, ewo ni tie naa. Won ni ki gbogbo eranko to niwo jade; igbin na sare bo sita. Se iru tie la wa nwi. Se iwo o mo pe alagba sitivini nse langba langba ni; agba to ba nse langba langba, orisirisi iwosi ni o ma nwo iru won. Nitorina, emi o le kunle be oponu agba kankan o. O je bo se je |
Family › Re: Married Men and Flirting by farotika(m): 11:55am On Dec 17, 2008 |
finemocha: this is a very stupid thread, don't u guys get tired of people asking themselves the same questions over and over again. Both sexes will cheat if the opportunity arises, especially if they can get away with it. The only reason y men do it more or should i say MORE OPENLY is because society looks down on women if they are too promiscious finish. Gbam!!! |
|
Culture › Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by farotika(m): 9:00am On Dec 17, 2008 |
steve4fait: se ori gbogbo yin ti daru ni. gbogbo yin soro bi asiere. ewo eje ki eri wa pe ni ibi ti awa yii o. mo fe kii gbogbo yin pe mi sor n. yii 07057407220, kin ba le ko tin bi won sen soro. Ode ni iwo omo yi. Oniranu buruku si ni e. Ti o ba nise, o se so fun mi kin ba le ba e wase. Gbogbo eeyan ni o ro pe o ri bi tie, ti won o ni ri nkan se ju ki won maa pe e. Dajudaju asewo, oniranu ati alaini laakaye ni e.  |
Culture › Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by farotika(m): 8:50am On Dec 17, 2008 |
Si A-40,
Ki lode ti iwo nfi owo osi juwe ile baba tie? Je ki a mo ibi ti o ti wa now |
Culture › Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by farotika(m): 8:45am On Dec 17, 2008 |
Si Chamotex, Ore wa, ti ibadi ba ndun e; iwo saa ti kan simi ti o ba wale kin le ba e ki agbo jedi ti o lagbara. Emi fi da e loju wipe ti o ba muu fun ojo meji pere, nkan omokunrin re a kan maa gberi ni gbogbo igba ni.  |
Culture › Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by farotika(m): 8:40am On Dec 17, 2008 |
Si Ebony ati Chamotex,
Ibadi ni eleebo maa npe ni waist nigbati won a maa pe Ileke idi ni waist beads |
Culture › Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by farotika(m): 8:37am On Dec 17, 2008 |
Si Ebony-Silk,
Bawo ni ore. Se o n gbadun ibi ti o wa lohun ni, ti o ba je bee, ope ni fun Olorun. Emi kan ni kin fi to e leti wipe Okunrin lanti lanti nimi; emi kii se obirin rara. Nitorina, eru Chamotex o bami rara.
Lafikun, mo wo aworan re mo si rii pe omo to rewa ni o. Tubo maa toju ara re o. O digba kan naa |
Culture › Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by farotika(m): 8:32am On Dec 17, 2008 |
Si Chamotex,
O se omo daadaa. O ti mo owo we loni o si di dandan ki o ba agba jeun. Iwo maa jeun soke ko si ma paro lo.
Siwajusii, Ebony-Silk so wipe onisekuse nie, emi o koko fe gbagbo sugbon nigba ti iwo naa tun bere sii wa bi o se maa mu oyan re ni mo wa rii pe Ebony o paro mo e. Imoran mi ni eyi, Isekuse o daa rara. Ete ati itiju lo maa nmu ba eeyan. Awon agba lo maa nso wipe oju kan ni ada maa n ni; ti o ba ti ni meji o di ida niyen Nitorina, fi oyan Ebony sile fun orekunrin re ki iwo si mu ikan ninu awon ti o nko kiri. |
Culture › Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by farotika(m): 12:43pm On Dec 16, 2008 |
MrCrackles: Mo fe mu oyan to ni omi ninu  Je ki nfun o ni amoran kan, pe ikan ninu awon orebirin re, mu abefele ki o si fi ge ori omu re. Emi nfi da e loju pe omi maa jade ti wa le mu. Oleeeeeeeeeeeee. Onimukumu |
Culture › Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by farotika(m): 12:37pm On Dec 16, 2008 |
chamotex: o de fe ma fi style se mi Rara o! mo n sakitiyan ati to e sono ni o. Yoruba bo won ni: "agba kii wa loja ki ori omotitun o wo". Mu eyi ti o se koko ninu oro mi ki o si mu lo. Ki Olorun o wa pelu re. Amin |
Culture › Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by farotika(m): 12:28pm On Dec 16, 2008 |
argent: @ farotika,
o baje, enu tigbo tigbo yen. Se ebu loye ko ma bu. oniranu oponu osi. Bawo lo se ma de thread to de ma koko bu ebu. shior Ti oju tie o ba fo, iranu to jade lati enu e yen iba ma ti jade. Ni ile Kaaro o Jiire, awon baba nla wa maa nkowa bi won se nbowo fun agba ni. Ti o bajepe bobo ti won npe ni Charcoal yen ba ni eko ile ni, ki ba ma ti so oro buruku si baba yen pelu ise takun takun ti o se fun asa Yooba. Awon agba ni: aibowo fun agba ni o je ki aye o gun. Ki Olorun oba o fori ji eyin omode wonyi. Amin. |
Culture › Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by farotika(m): 12:38pm On Dec 15, 2008 |
chamotex: Fagunwa ko, Fijabi ni Iwo bobo ti won npe ni chamatex abi chacoal yii, kini wahala tie naa? Se baba Fagunwa loun soro kungba kungbe si beyen. O dabi wipe o oni agba nile rara. Oniranu, ole, aboju tonto. |
Culture › Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by farotika(m): 12:23pm On Dec 15, 2008 |
goodass: e gbagbe JF Odunjo ati Diran Ajijedidun.
baba Fagunwa ku ise o. shey awon klasics yen wa lori net sha abi ko si enit ti o n wo side yen rara? Ooto ma ni eyin omo Yooba rere, se ko si bi a se le ri awon iwe aiye atijo ti baba Fagunwa ko lori itaneeti ni? E jowo eni keni ti o ba mo bi a se le rii ki o ma sai je ki a mo nipa re. E se o, e si ku ise |
|
|
|
|
|
|
Romance › Re: Y Play Wit My Feelings? by farotika(m): 12:52pm On Dec 05, 2008 |
Pick her calls and hear her out. She most probably wants to apologize for not taking u serious. U KNOW WOMEN ARE LIKE SHADOW. |
|
|
Politics › Re: Choose Between Obasanjo, Abacha Or Babangida by farotika(m): 4:02pm On Dec 04, 2008 |
I'll choose Gen Saaaannnnniii Aba,cha.
Reason: HE IS DEAD!!! |
Romance › Re: This Goes To The Ladies new by farotika(m): 11:55am On Dec 04, 2008 |
BabeX: hmmmmm. if I'm not married to him, il reconsider our relationship. If I am, then il go with the flow and be nice to the kid. Afterall its not the kids fault O se o jee. |