Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / NewStats: 3,160,825 members, 7,844,666 topics. Date: Thursday, 30 May 2024 at 05:04 AM |
Nairaland Forum / Ifankaleluya's Profile / Ifankaleluya's Posts
(1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) (of 10 pages)
Culture / Re: .. by Ifankaleluya: 10:32am On Mar 09, 2016 |
wale259: E LE PO KO PO DADA. SUGBON KIISE OHUN TI AO MA WE NIGBA GBOGBO OO. BI EEKAN LOSU-META NI. 1 Like |
Culture / Re: .. by Ifankaleluya: 10:29am On Mar 09, 2016 |
skypeme: BEE NI, O KARE OKUNRIN YI. OGBE'YONU NIYEN. E LE FIAGBON YEN SE SARA FUN ENIKENI. 1 Like |
Culture / Re: .. by Ifankaleluya: 12:01pm On Mar 08, 2016 |
Zenlife: You can not comprehend! Anyway...u can reach m 2ru ds e-mail.......ifankaleluya@gmail.com 1 Like |
Culture / Re: .. by Ifankaleluya: 9:35am On Mar 08, 2016 |
Ifa ni; Ti a ba ji ogbon ni e je a ma ko ra wa ka ma ji ni kutukutu pile were Oro ta ba ro ti o ba gun Ikin(ifa) eni la keesi Difa fun pakara,alawo wininwini Nijo ti n lore jija alaranbara labe odan ebo won ni o se. Lagbara lowo Eledumare ara rere ni ao ma da,ao ni daran. Ela-boru,Ela-boye,Ela-bosise. 2 Likes 1 Share |
Culture / Re: .. by Ifankaleluya: 9:34am On Mar 08, 2016 |
Hnnnmmmmm! |
Culture / Re: .. by Ifankaleluya: 9:17am On Mar 08, 2016 |
skypeme: Ewe-ooyo ni e o lo re wa ti yio po dada. Odidi-agbon eyo kan. Ao sa oyo yen ti yio gbe. Ao gun po mo ose Ao pa agbon yen,omi-agbon yen ni ao fi po ose yen Ao fi ti inu-agbon yen se sara fin awon omo-kekeke,sugbon a ko ni je ninu agbon yen oo. Ao wa ko ose yen sinu koronfo agbon yen Ao wa te ni Ogbe-yonu OGBE-OGUNDA NI A MA N PE NI OGBE-YONU 3 Likes |
Culture / Re: .. by Ifankaleluya: 9:06am On Mar 08, 2016 |
Zenlife: Yes,but i'd removed my mobile number 4rm ds thread cos Babalawo gidi kan o kin polowo ifa re fun ra re. Ifa ni yio dide ti yio si lo polowo ara-re. |
Culture / Re: .. by Ifankaleluya: 9:00am On Mar 08, 2016 |
skamo74: It is not the issue of knowing all. You can not understand cos u're not an ifa-priest. But, those that av d knowledge of what I mean av testified nd got 2 know d fact. As an ifa-priest, i've not go against anyone here excepts d one dt claimed 2 b an ifa-priest but did not know how to respond when an ifa-priest is greeting, nd one onile-iro called himself onile-ifa that is abusing ifa verses here. Do u ever noticed m go against kadunasouth? NO!! I'm not here 2 go against anyone, but only 2 shed-light. 1 Like |
Culture / Re: .. by Ifankaleluya: 8:46am On Mar 08, 2016 |
skypeme: Owo(hand) ni ao fi mu oguna yen ninu ina. Ao wa ju sinu omi, lati inu omi yen ni ao ti mu ju si ori olo ti o ba ti ku tan. 1 Like |
Culture / Re: .. by Ifankaleluya: 5:50pm On Mar 06, 2016 |
OBARA-OGUNDA NI A N PE NI OBARA-EGUN TAN. IFA NI; Obara-egun tan oni(today) la o pa egun run adifa fun orunmila nijo ti omo-araye ni awon o fi eegun,epe ba aye baba je ifa ni iro ni won n pa egun kii mu ila egun kii mu ikan ati egun ati epe kii mu ata obara-egun tan ifa ba mi pa gbogbo egun aye mi. IFA YI NI A MA N FI, ata,ikan,ila ati etu-ibon se. Ti a ba pari re, enu ona ni ao ti te ifa re,ti a ba pe ifa tan. Ao wa fi etu ibon yen si ni aarin,ao wa sa ina si. Ti ina yen ba gbi, ise yen ti dahun niyen. Ela-boru, ela-boye, elo-bosise. 4 Likes |
Culture / Re: .. by Ifankaleluya: 5:37pm On Mar 06, 2016 |
MJAhmed: Beeni, OWONRIN-OSE NI A N PE NI OWONRIN-WESE. IFA NI; Ori buruku ko gbo ose Aweida ko gbo Ogun Alawoobi seran Omo araye te mon Lara A difa fun awo ELesinje mmogbe iraye Ti n se wolewode Oduduwa Ti n gbebi awon aya Oduduwa To tun se ale olokun aya Oduduwa Oduduwa na lo pa, ati be be be looooo. NIBE NI A TI MA N LO EFUN, OSUN, PEREGUN ATI BE BE BE LO. 2 Likes |
Culture / Re: .. by Ifankaleluya: 2:07pm On Mar 06, 2016 |
Boya ki e tun lo bere lowo awon agbalagba, OMI-AGBON NI WON N PE NI OMI - APEGUNRUN. EWE-PEREGUN SI DA WA LOTO. Bayi ni won se ma n lo omi agbon lati fi pa egun, epe, ati ise run. A o lo wa omi-agbon to po daadaa, ao wa mu oguna to ti pon daadaa ninu ina,ao sare ju si inu omi(owo(hand) ni ao fi mu ogunna yen ninu aro),ao ju si ori-olo,ao lo,ao po mo ose dudu,omi-agbon yen ni ao fi po ose yen. Kanrinkan titun ni ao fi we ose yen ni odo to n san. Gbolohun yi ni ao ma pe ti a ba ti n we ose yen: ojo ti ina ba wo inu omi ni egun aye re tan, ki egun aye mi ko tan loni. Owo(hand) mi ti ba omi-apegunrun lo ni, ki gbogbo egun aye mi ko tan loni, ati egun, ati epe, ati ise(poverty) aye mi ko ma ba omi lo loni, ko je ki n gbaye se rere. Ao ju kanrinkan yen si odo,yio ma ba omi lo. 3 Likes |
Culture / Re: .. by Ifankaleluya: 1:54pm On Mar 06, 2016 |
Zenlife: Maybe you should try to go 2ru my previous posts. You will understand why! You may send an e-mail 2 m nd i'l respond 2 ur request privately. Nd if u av done so,bt,yet 2 received my responds, you shld understand dt there are numerous messages on my e-mail nd urs may went over-sight. More-over,all my posts here is a prayer 4 u. U may like to say amen 2 it, nd u shall received d blessings in it. |
Culture / Re: .. by Ifankaleluya: 1:40pm On Mar 06, 2016 |
[quote author=MJAhmed post=43527270] this is nothing but true is also call ewe ogunbo to elomiran oba due oko baba elomiran ani oko baba oun lotobi julo ibi ima awan nkan parisi ibeniti elomiran ti bere, eje kama nisuru funrawa, oduwa ateworo ni ife yio gbe gbogbo wa obami oke olodumare koni jeki asise o! amin Titi to fi de odo-eledumare,kosi ese ifa kankan ti n je obara-dagise, Okaran-adasenu lo wa. 2 Likes |
Culture / Re: .. by Ifankaleluya: 11:45am On Mar 06, 2016 |
Ifa ni; Eri pese, Ere pese, A difa fun Olokanran, Eyi ti n lo ree rugba ise(poverty) sigbo, Ebo n won ni o se, Olokanran gbebo nbe, O rubo, Olokanran gbaka fun esu, O si tu, Nje Awedewerisa werii mi fun mi Awedewerisa. Ise(poverty) awa tan(end), Ola(wealth) lo ku o, Awa roju sebo. Lagbara lowo eledumare, Awedewerisa yio we ori wa fun wa. Ise(poverty) aye wa yio si tan(end) Aboru, Aboye, Abosise. 1 Like |
Culture / Re: .. by Ifankaleluya: 7:47pm On Mar 05, 2016 |
skypeme: skypeme:[/color] skypeme: Ogun-aanu ni ogun yen, sugbon kope. Ewe-ominsinmisn gogoro ati ewe-aanu, pelu eran ike-maalu, ti e ba ti gun tan,oti-shnap ni a o fi po, ao ko sinu igba-funfun tabi ike-funfun, ao wa tu bintu si, ao wa fi eran ike-malu yen gun lori. Lo ba tan! Ela-boru, ela-boye, ela-bosise. 2 Likes |
Culture / Re: .. by Ifankaleluya: 5:17pm On Mar 05, 2016 |
Ifa ni; Elefiri-mogun, aja ni aja olofin, agbo lagbo olori, oja-agbala ni ki e fi gbami, oja ti e ba fi gbami ki e ma je ko ja,kike ni ki omo-araye o ma ke mi, gige ni ki omo-araye o ma ge mi, oja ti e ba fi gba mi e ma je ko ja, ewe aje-obale le fi pin ohun lotu-ife nijo n,ogbe-tun-omopon lo ni ke gbe mi pon seyin giri-giri. Lagbara lowo eledumare awon eleye yio da owo(respect) fun wa. Ase-orisa lenu mi,eyi mo ba ma ma wi ni irunmole yio gba, ase orisa lenu mi! Ela-boru, ela-boye, ela-bosise. 3 Likes |
Culture / Re: .. by Ifankaleluya: 9:32am On Mar 05, 2016 |
healthFirst: hnnmm. 1 Like |
Culture / Re: .. by Ifankaleluya: 6:22pm On Mar 04, 2016 |
Oluokunoluwole: E seun, Babalawo lo ni isoye,so ifa-isoye po lorisi-risi daadaa,sugbon n ko fe fi ifa sile lori faran yi mo. A o ma soro lona miran! |
Culture / Re: .. by Ifankaleluya: 6:14pm On Mar 04, 2016 |
Humm..! |
Culture / Re: .. by Ifankaleluya: 5:51pm On Mar 04, 2016 |
Ifankaleluya: mo ti fi esi ranse si e-mail yin. Bi e ba ti se, be ni o ri tori tokan-tokan ni mo fi yonda ifa yen fun yin. |
Culture / Re: .. by Ifankaleluya: 5:22pm On Mar 04, 2016 |
Lero70: Agbo ato baba! Ma fo esi si awon ibere yin yen via d e-mail. O wu mi lati fo esi nibi, sugbon ifa ni ise yen, mo si jiya fun kin to ni lowo ni, ko se fi sere nitori awon ti n ta iwe-ogun. |
Culture / Re: .. by Ifankaleluya: 2:54pm On Mar 04, 2016 |
ONILEIFA: I'l nt join any issue with you cos u'a nothing but jst a cockroach! I do not come here 2 obtained money from pple under the false pretence that am this nd that. I come here 2 shed-light. IWO-KE....IWO TI O TI E MO OJU-ODU NI MA MA BA SORO. Hiss!! |
Culture / Re: .. by Ifankaleluya: 1:54pm On Mar 04, 2016 |
[quote author=Lero70 post=43462848][/quote] e dakun kin ni e-mail yin yen? Tori orisirisi e-mail lo wa lori e-mail mi. |
Culture / Re: .. by Ifankaleluya: 1:48pm On Mar 04, 2016 |
Lero70: ''ki keke pa yin lenu'' eniti o kin n se babalawo,ko fo iru esi yen fun emi ti mo je babalawo,eyin o mo wipe ede abuku niyen. Idi ti mo fi fo esi niyen. I dnt av any personal issue with him. E seun modupe. |
Culture / Re: .. by Ifankaleluya: 1:36pm On Mar 04, 2016 |
Some pple av tried 2 confirm if truly am an ifa-priest....but,so far I am one,I easily convinced them, if not they would av come 2 post on this thread to accused me. Even lately yst9t....som1 asked m what Okanran-odi says nd when I respond,I asked him if am lying or not,nd he said I was not lying that was wht araba-oluawo of osogbo told him. Abt 2 days ago,someone asked m abt Obara-bogbe,nd so many things like that. If u ask m wht I kno,,,I'l tell u,nd If I dnt kno it,i'l tell d truth. Ifa kii-puro,Opele kii-seke babalawo ni o ya ni gbo ohun ti ifa n so. Iranse lo si gbo-ifa ju,ohun to ba ru ni loju,a ma n fi iranse bere ni. Ela-boru, ela-boye, ela-bosise. 1 Like 1 Share |
Culture / Re: .. by Ifankaleluya: 1:20pm On Mar 04, 2016 |
Zenlife: I've vowed not 2 write on this issue again cos some pple av spoke 2 m 2 let it go. But, anytime i observed unbalanced on this issue my emotion always moved. I do not av any personal issue with him(healthfirst) so far i w nt ask 4 a share 4rm d money he is collecting 4rm pple. All my accusation 2 him was 4 d benefit of users of this thread. Though,he owns d thread,but,nt dt he can collect money from users of this thread under d false pretence dt he is an ifa-priest nd he w help dem consult ifa. I'm very sure he did not known dt am d one dt challenged him on d social network called whatspp until I respond 2 his comment concerning I nd one Onile-iro called himself Onile-ifa. It was after I challenged him nd found dt he was not an ifa-priest i registered nd began 2 post on this thread. This is our last conversation''I WAS BORN INTO IT BUT SINCE AV NT ENTERED GBODU THAT IS WHY I CAN NOT CALLED MYSELF BABALAWO'' then I respond ''YOU WAS NOT BORN INTO IT COS D EXCUSED THAT YOU AV NOT ENTERED IGBODU DOES NOT RESTRAIN YOU 2 CITE A VERSE ND CONVINCED M THAT U'A REAL BABALAWO. i said gentleman go away..! He does'nt even know how 2 respond when an ifa-priest is greeting! I'm not here 2 spoil his business,but,he shld b more truthful. |
Culture / Re: .. by Ifankaleluya: 11:03am On Mar 04, 2016 |
Lero70: Rara oooo, ewe oniyemiye yato si ewe-iyeye ooo. Awon miran tun ma n pe ni ewe-oniyesoye. Inu-omi ni ewe yi saba ma n wa tabi ibi ti o ba tutu. Ti e ba kan ewe yi si meji e ma ri iho keke merindinlogun ninu ewe yen. E bere lowo awon elew-omo,ewe yen wa daadaa. Odu ologbon-meji ni a n pe ni oturupon meji. Bayi ni won se ma n te; || || || || | | || || ela-boru, ela-boye, ela-bosise. 2 Likes |
Culture / Re: .. by Ifankaleluya: 11:00am On Mar 04, 2016 |
Lero70: Rara oooo, ewe oniyemiye yato si ewe-iyeye ooo. Awon miran tun ma n pe ni ewe-oniyesoye. Inu-omi ni ewe yi saba ma n wa tabi ibi ti o ba tutu. Ti e ba kan ewe yi si meji e ma ri iho keke merindinlogun ninu ewe yen. E bere lowo awon elew-omo,ewe yen wa daadaa. Odu ologbon-meji ni a n pe ni oturupon meji. Bayi ni won se ma n te; || || || || | | || || ela-boru, ela-boye, ela-bosise. 1 Like |
Culture / Re: .. by Ifankaleluya: 10:48am On Mar 04, 2016 |
Ifa ni; Adaseke jiyan won o lohun re lenu, adifafun Orunmila nijo ti asude suleke nbaye e je, ebo won ni ose,o gbebo nibe o si sebo,o gba akasu esu o si tu,asude suleke jowo ma ba aye yi je fun mi, asude suleke. Lagbara lowo Eledumare, aye gbogbo wa ko ni baje ooooo. Ase! 2 Likes |
Culture / Re: .. by Ifankaleluya: 6:50pm On Mar 02, 2016 |
Mo dupe pupo lowo gbogbo eyin ti e pe ati eyin ti e ba mi soro lori whatsapp to fi de odo eyin ti e lo e-mail. E seun mo dupe. Emi ko dede ma ba enikeni ja,sugbon o semi ni aanu nigbati mo ri awon obayeje kan ti won n fi dudu pe fun-fun fun awon eniyan loje ki oro fe se bi ija nitori emi ko fe ibi ti ko ba si otito. Nigbati a si bawon soro ni tutu,won ba bere si leri ogun,to je wipe won o ni ogun eyo-kan ti n sise lowo gan. Koda ti won ba tie ni gan,awa ti tayo eni ti enikeni le ma leri ogun si,notori wipe ifa ni kaka ki aye o ja ko pare,igbin ni a mu to,Ibi won ka sai sun siwon lorun,ibi won. IFA NI KOKO IGI NI O BERE OJO,ADIFA FUN EJO N BE LORUN TI SE OMO-AWISUNKUN,IFA NI IRE LO BA MO SE. MA SE LOO,IKA LO BA MO SE, MA SE LO,AT'ORE AT'KA OKAN KAN KIIGBE. Gbogbo eleyi to ba se ni wa je ere re...! ela-boru, ela-boye, ela-bosise. |
Culture / Re: .. by Ifankaleluya: 2:59pm On Mar 02, 2016 |
WiLdFLame:kin ni e fe ki a se fun yin baba? |
(1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) (of 10 pages)
(Go Up)
Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 92 |