Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,160,807 members, 7,844,614 topics. Date: Thursday, 30 May 2024 at 01:37 AM

Ifankaleluya's Posts

Nairaland Forum / Ifankaleluya's Profile / Ifankaleluya's Posts

(1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) (of 10 pages)

Culture / Re: .. by Ifankaleluya: 7:39pm On Apr 12, 2016
[quote author=Tevez83839 post=44546648]Edakun shop yen fee die .e koo fun mi boya mo le see. Tabi ejowo e add me 08162736520.EDAKUN OJA KO WA[/quote

Kiise oun gbogbo lo je mo Ogun sise..! E se koko lo se iwadi oun to fa idiwo ki e to ma wa ogun kiri?
Ati wipe iru ise ti e n se yen o pon dan-dan pe ki e ri nkan mo shop yin. Nko mo igbagbo yin ninu ogun ririmo shop. Ko pon dan-dan ki e waste owo yin lati fi se Ogun ti ko ni sise...! Sugbon ti o ba sa wu yin lati ri nkan mo shop yin, e kan si mi lori e-mail.

1 Like

Culture / Re: .. by Ifankaleluya: 7:30pm On Apr 12, 2016
wale259:
E jo sir,se a ni mu owo(money) yen kuro ninu igba yen ti a fi ma ko ose le Oga lori.

@wale259, thank you so much 4 wht you sent to appreciate all wht you av got 4rm m. May GOD continued to bless you!

A ko ni mu owo yen kuro nibe rara, a ma fi Oga yen lo owo yen lori ni a fi ma gbe ose yen le mole.

2 Likes

Culture / Re: .. by Ifankaleluya: 7:22pm On Apr 12, 2016
WiLdFLame:

baami, mi ti kan si yin lori e-mail yin nipa esi lilo ogun yen fun ojo die oo

Mo ti ri e-mail yen....sugbon boya ka soro labe aso ti mo ba ti raye.
Culture / Re: .. by Ifankaleluya: 7:20pm On Apr 12, 2016
Oyeku-ka

Ifa ni;

Eke(do mi) ni Olorisa to ni iru oun ko si

Ti nyowo aso-funfun lala

Dia fun Asise(do do re)

Eyi ti segbon Orisa

Nijo ti n tikole orun bowa ile aye ebo won ni kose

O gb'ebo nibe o si sebo

O gb'atuka esu o si tu

Egun(mi mi) kan kii seni

Orisa(do do do) kan kii le loro(mi do)

Asise nikan lo le loro

Lo ju gbogbo ebo lo

Mo gbadura wipe ki Eledumare o fi oju fo Asise ti Onikaluku wa ti se to da aye wa ru. Ase!

Aboru, Aboye, Abosise!

1 Like

Business / Re: Binary Options Alertz/strategies Season 5 !!hot!!! by Ifankaleluya: 2:20pm On Apr 12, 2016
PRICE ACTION CONDITION @ D MOMENT.

Business / Re: Binary Options Alertz/strategies Season 5 !!hot!!! by Ifankaleluya: 2:15pm On Apr 12, 2016
NZDJPY

1 Like

Culture / Re: .. by Ifankaleluya: 4:03pm On Apr 10, 2016
Ifatoki16:
Baba Ifankaleluya,eku atunse ati agbaale wa lori ikanni yi.Ejoo emi Ifatoki16 bere fun imule awon aje ti won fi nfi ami igba si aya wa tie fi sita ti ko pe.mo bere ni ori email yin,sugbon e ko dami lohun lati igba na.tabi e nbinu simi ni.email mi ni eyi llcatz@yahoo.com

e-mail po ti mo n fo esi si ni. E ma ti binu, n o da esi pada laipe.
Culture / Re: .. by Ifankaleluya: 4:02pm On Apr 10, 2016
wale259:
Sir,bawo la se ma wa se obi yen to ba ti yan?obi yen ma je mejo(eight pieces)

Jije ni obi yen.
Culture / Re: .. by Ifankaleluya: 3:59pm On Apr 10, 2016
Ifa ni;
Idin Ran nnn
Babalawo Oyin lo ki ifa ojo kan fun oyin
Nijo ti n ti ikole orun-bowa aye
Ebo won ni kose
Ogb'ebo nbe o si sebo
Ogb'atuka esu o si tu
Nje morann-morann lawiran oyin
Awidun lawiran iyo
Morann-morann lawiran oyin.
Pelu ogo Eledumare, tomode-tagba yio ma soro wa si rere. Ase!
Aboru, Aboye.

1 Like

Culture / Re: .. by Ifankaleluya: 3:58pm On Apr 10, 2016
Apete ti a ma n fi sara to sise ibon, Ada, Okuta, Apola or whatever,

Ti a ba se Apete yi tan, ti o ba wa lara wa, ti won ba yin ibon(gun) mo wa, eni ti o yin ibon yen yio si di Aka(re mi)(Adete) lesekese.

Ao lo re wa ewe-ina pupa, ewe-esisi, Ahun, ewe-airagba, Aso-aka. Oruka ti ko wo omi iyekiye. E je kin da enu duro nibi tori awon oni-ise ibi.
Culture / Re: .. by Ifankaleluya: 11:02am On Apr 09, 2016
Ifa isegun ota o ni Obara-ika to daju.

Ao lo wa epo igi-iroko, ao lo kunna daadaa, ao sa gbe, ao fi te Obara-ika sinu awo-amo dudu. Ao pa obi-meji fun, ao je die ninu obi na ni ao fi pe ifa re

Ogun ni be mo lori omo-okege

Iroko alu ji ni deru ba agba

Opelope obara-ika

Ngba tomo araiye yo ida

Ti won ni awon o pa mi

se bi akaniku,Orunmila lekun

Aja ki ja mo lehin ekun paje

Oso ile to ba nperi mi nibi

Obara-ika o,ka oluwa re sorun

Aje-ile, okunrin, obinrin ti ba n

peri mi nibi, Obara-ika, ko ka

Oluwa re sorun.

Ao da obi yen fun, ti obi yen ba ti yan, ao bu epo pupa si, ao la ti a ba fe sun lale.

Aboru, Aboye.

2 Likes

Culture / Re: .. by Ifankaleluya: 10:32am On Apr 09, 2016
Tevez83839:
Baba edakun.ise ayaworan ni mo yan-an laayo. Sugbon ni shop mi oja ko yaa daada oorun ni mo n sun edakun kini ogun ti mo le ri mo inu shop bi aworo todaju ti customer fi maa wa pupo...boya eyi ti eyan ma gbe ile fun Atipe se ise yi daju ( ao gbe ile sinu shop ,ao da iyo sibe ,aote ni eji ogbe ao wa fi pandoro si inu ile yii .ao da iyo lee lori to maa bo pandoro yii ,ao wa da aso funfun boo lori ao wa ro iyepe lee lori ) se odaju tabi afikun .tabi ki e fun mi ni ominra aje biidan .edakun

Ore wa, n ko ise ti e bere nipa re yen. Eleyi ti emi mo to jo mo nipe ao ko tewe-tegbo kun-kun(mi mi) le odu ti a fi iyo te yen lori ni. Ao si tun fi awon ewe-ifa kan kun.

Nko mo bi shop yin yen se tobi to ni...Oso-afaro wa toje wipe laarin 21days shop yin yen a ti di Oja(market). Sugbon kiise oun ti e le da se, ati wipe ti shop yin yen ba kere, ko dara to.

2 Likes 1 Share

Culture / Re: .. by Ifankaleluya: 10:24am On Apr 09, 2016
Ifatoki16:
Baba mi agbalagba Ifankaleluya,e jowo mo fi Orunmila beyin kie fun mi ni ise imule awon agba ti won fi nyo si wa loju orun fi ogun aye wa han wa yen kio pe.O fi tie sile gbo teni eleni, Olorun yio gbo tiyin na ooo.Ase. number mi 09053297971 @Ifatoki16

Omo baba-awo ifatoki, Imule awon agbalagba to tun lagbara ju iyen lo si wa. A ko mo ifa ni...Orunmila ni oko-oso ati Aje, so boya ka soro labe aso.

1 Like

Culture / Re: .. by Ifankaleluya: 10:20am On Apr 09, 2016
Ifa ni;
Owonrin-wese(do mi) wese
A dia fun Abi-ose
Ti s'omo Ose-lawe(re do re do)
Nijo ti n be larin iponju
Ebo won ni kose
Ogb'ebo nibe o si sebo
Ogb'atuka esu o si tu
Nje ero-ipo, ero-offa
E wa wo ifa awo ki bi ti n se.
Mo gbadura ki Eledumare o ba onikaluku wa we ise(do mi) aye wa nu. Ase!
Aboru, Aboye!

1 Like

Business / Re: Binary Options Alertz/strategies Season 5 !!hot!!! by Ifankaleluya: 5:47pm On Apr 07, 2016
amolak:
I think you don't need indicators at all, Ifa can tell you where market will be heading to cheesy

Lols...!!!
Culture / Re: .. by Ifankaleluya: 5:40pm On Apr 07, 2016
Ifa ni;

Ewure(re mi mi) lo fi ori sile

Lo pa(mi) lorunkun(mi mi mi)

Adifa fun Orunmila

Nijo ti wa n tori baba kewu

Ti won tori baba pe egede(do do do)

Ti won n tori baba pe aasan

Ti won tori baba sa ogungun(do do do)

Orunmila ni, e ba tori mi kewu oo

E ba tori mi pe egede

E ba tori mi pa aasan

E ba tori mi sa ogungun

E ba tori mi tan abela(do mi do)

Ti owo mi ba ba(re) ikin(re re)

Ma si sete(mi do)

igba(do do) ti owo mi ba Ikin

Mo si sete.

Aboru, Aboye, Abo-sise!

1 Like

Culture / Re: .. by Ifankaleluya: 5:33pm On Apr 07, 2016
fxopen:


e seun sir, e jowo ti won ba so pe eeyan maa sefa (m m) ki lo tunmosi sir,

Ifa sise tumo si wipe eniyan ma da ifa re ni, yio si ma ba soro nigbakigba ti o ba wu eniyan.
Eniyan le gba ifa ko gbe si odo(do do) Baba-awo re, a sile gbe si odo(do do) fun ra wa.

2 Likes 1 Share

Business / Re: Binary Options Alertz/strategies Season 5 !!hot!!! by Ifankaleluya: 9:02am On Apr 07, 2016
hardeniji02:
@ Mr Ifankaleluyah are you the same ifankaleluyah we know that present on Faaji Fm and Radio lagos

Not @all bro. I'm not a presenter but an Engineer & a Currencies analyst. Thanks..!

1 Like

Culture / Re: .. by Ifankaleluya: 8:20pm On Apr 05, 2016
Aworo Itaja

Era aladi

Awo-eta

Ao fi owo(re mi) fon ina si

Ose

Ao gun papo ati ose yen,ao wa pe gbolohun re si, ao ma fi we.

Gbolohun re; Afi atewo fon ina kii duro, ina loni ki e fi owo(re mi) owo(hand) yin ba mi na, era loni ki e fi owo owo(re mi) yin ba mi ra, eta ni koko ta ki omo-eranko miran to ta. Ao so oun ti a fe, ao fi we.

2 Likes

Culture / Re: .. by Ifankaleluya: 8:15pm On Apr 05, 2016
[quote author=fxopen post=44432917][/quote]

fifo bawo....Ika-owo ni a ma fi lu ose yen ooo.

1 Like

Culture / Re: .. by Ifankaleluya: 8:14pm On Apr 05, 2016
Ose iyonu awon agba
imi-ewure, imi-agutan, ewe-eko ti won sonu, ewe-orijin pupo. Ao gun po mo ose..ao ma fi we.

1 Like

Business / Re: Binary Options Alertz/strategies Season 5 !!hot!!! by Ifankaleluya: 5:24pm On Apr 05, 2016
TRADING IS SIMPLE! YOU DON'T NEED TO CRACK YOUR BRAIN!!

Volatility is over for today as LONDON banks closed for the day.

CONGRATULATIONS if you have followed my trade insight in the morning. AUDJPY, NZDJPY, GBPJPY falls as JPY dominates the market.

I'l be off 4 some times to add more values to my xperience in trading as I hope to compete with some international currencies analysts in the next quarter of the year.

For insight & my trading systems(i.e. MT4, INDICATOR ETC)...you can reach M 2ru ds mail.....ifankaleluya@gmail.com.

Bids u all a green pips.
Business / Re: Binary Options Alertz/strategies Season 5 !!hot!!! by Ifankaleluya: 10:36am On Apr 05, 2016
CURRENCIES TO WATCH AT THE MOMENT JPY CHF AUD NZD USD & EUR.

OPEN YOUR CHART & WATCH THEIR PAIRS TO LOOK FOR OPPORTUNITY TO ENTER MARKET. CHECK FOR THE NEWS ON THOSE CURRENCIES & USE YOUR MFI ON VOLUME INDICATOR OR RSI TO CHECK FOR OVER-SOLD OR OVER-BOUGHT......THEN SMILES TO THE BANK.
Business / Re: Binary Options Alertz/strategies Season 5 !!hot!!! by Ifankaleluya: 10:30am On Apr 05, 2016
IF YOU'RE GOOD IN TRADING VOLATILITY......YOU WILL HAVE TO WAIT TILL NORTH-AMERICA(NY SESSION) WILL ENTER MARKET BY 1PM NIGERIA TIME. BY THEN, LONDON BANKS WILL GO FOR LUNCH FOR JUST AN HR( 1-2PM),SO VOLATILITY W START AS FROM 1:45PM OR 2PM TILL 5PM. BIDS YOU ALL A GREEN PIPS.
Business / Re: Binary Options Alertz/strategies Season 5 !!hot!!! by Ifankaleluya: 10:20am On Apr 05, 2016
STRONGEST CURRENCIES AS ASIA SESSION ENDS & LONDON SESSION PUSHING THE TREND IN THE DIRCTION ASIA SESSION LEFT IT

Business / Re: Binary Options Alertz/strategies Season 5 !!hot!!! by Ifankaleluya: 10:14am On Apr 05, 2016
CURRENCIES STRENGTH AS IT STANDS NOW

Business / Re: Binary Options Alertz/strategies Season 5 !!hot!!! by Ifankaleluya: 10:26pm On Apr 04, 2016
I'm using hours to trade Binary to avoid false breakout nd pave way 4 d pair to breathe......once i got the trend rit nd no news on any of the currency of d pair I chosed to trade, No panic! Do av a lovely dream..!
Business / Re: Binary Options Alertz/strategies Season 5 !!hot!!! by Ifankaleluya: 10:21pm On Apr 04, 2016
GabrielYulaw:
Dear Ifanka pls where did you get your chat? Its seems about right. Where can i download am na?

I'l do my best to code it & make it available for you guys very soon.
It's all abt price action nd currencies correlation, you don't need much stress or cracking ur IQ to trade forex or binary. Everything is simple...!!!
Business / Re: Binary Options Alertz/strategies Season 5 !!hot!!! by Ifankaleluya: 10:17pm On Apr 04, 2016
haywhy59:


Pls wat d name of d indicator and pls where did u download ur Mt4 platform... Thanks

I got it 4rm a currency analyst named Greg Michalowski 4rm US bro.
Business / Re: Binary Options Alertz/strategies Season 5 !!hot!!! by Ifankaleluya: 10:10pm On Apr 04, 2016
THE STRONGEST CURRENCIES TODAY WERE JPY EUR CHF & THE WEAKEST WERE AUD &NZD. you can cross-checked.
Business / Re: Binary Options Alertz/strategies Season 5 !!hot!!! by Ifankaleluya: 10:07pm On Apr 04, 2016
BINARY OR SPREAD BETTING IS SIMPLE WITH PRICE ACTION

Business / Re: Binary Options Alertz/strategies Season 5 !!hot!!! by Ifankaleluya: 9:57pm On Apr 04, 2016
GOOD EVENING.

(1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) (of 10 pages)

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 55
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.