Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / NewStats: 3,160,689 members, 7,844,276 topics. Date: Wednesday, 29 May 2024 at 05:35 PM |
Nairaland Forum / Ifankaleluya's Profile / Ifankaleluya's Posts
(1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) (of 10 pages)
Culture / Re: .. by Ifankaleluya: 10:27am On Mar 19, 2016 |
dominicson: OKARE OMO-ONIBABALAWO. BEE NI...BI IFA NA TI RI NU. AO GE IGBIN YEN NI MARUN-MERIN NI, TI GBOGBO E A JE MESAN SUGBON KIISE OBE(KNIFE) NI A FI MA N GE OO. FANRAN OPARUN(re re re) NI AO FI GE. OTUTU(re mi do)-OPON(re do) yen ni ileke ti awon babalawo ma n fi so ide(re do) ti won ma n so mo owo(hand). Kiise ileke-fun-fun oo, GREEN & REDISH brown ni. Ileke yen na ma je mesan! Sefunsefun yen ni a pe ni Sese-efun(mi mi re re). Ela-boru,Ela-boye,Ela-bosise. 4 Likes |
Culture / Re: .. by Ifankaleluya: 6:22pm On Mar 18, 2016 |
@Healthfirst I was busy in d morning, So, I could not responded to you post on after the other. Truely, we have not met in camera,but,if w do. You're still very small to challenge or stop me on any ground cos I no b your caliber, to set proudness apart. You're very free to invite me to any ground, you w know GOD still exist! |
Culture / Re: .. by Ifankaleluya: 6:07pm On Mar 18, 2016 |
[quote author=fxopen post=43881731][/quote] @fxopen..! R u a forex-trader? If you're one, what are d indicators you're using? Concerning wht you asked. Asiri bibo keekeke ni awon yen now,so ko ni eewo or whteva kankan. Awon alujon-nu ti n wa owo(money) fun awon eeyan po lode(mi re). So.....Oloju awon-asiri bibo to le sise(re mi). Emi kan n woran ni....Nigbati mo ri awon kan ti won post oso-owo olojo-meje to gbona pe ke lo fi isu dandan je. Kosi wahala kankan ore mi(my 5rnd)! |
Culture / Re: .. by Ifankaleluya: 8:54am On Mar 18, 2016 |
healthFirst: Is this not gibberish you posted & reffered as caution..... Ogbeni Ifankaleluya ati OnileIfa, ki keke pa mo yin lenu, eyin obileje awo eke. ki le ri ninu obe te fi waro owo bayi? A gbe eto yi sita lati ran awon ti aye n fiya je lowo ati lati gba won sile lowo eyin Awo eke gbogbo. lehin gbogbo ikilo ta kin yin, e tun wa n paro orisirisi. Mo fe fi dayin loju, teo ba dawo ibi duro, eo gba Esu lalejo laipe. Egbinrin ote loro yin, ba se n pa kan nikan n ru jade. E ki owo omo yin sinu aso ni kiakia te ba fe ka fi Epe ranse si yin? You started the blackmailing but you was unable to scale-2ru because am real babalawo not awo-eke as u stated. I think the tag of this thread is to help,but,you posted a wrong medicine to waste these peoples money. So,4 me to tell them the truth that what you posted was wrong is ''slandering & blackmailing'' to get cheap popularity as u stated abi? Can you pls tell me what ''impersonation'' mean if not to ''de-fraud'' pple? You presented yourself as an ifa-priest but confessed for me that you're not when I engaged you on whatsapp & asked for an ifa verse. You come-out now said by the time you do what you wish to do everything w come to an end. R u the one that own the website? I'l always says the truth!!! 1 Like |
Culture / Re: .. by Ifankaleluya: 10:46pm On Mar 17, 2016 |
Irete-Osa ni. Arote tan a n sa, won se bi eru ote(do do) la n ba,eru(do do) ko la n ba, sebi enu ni a n sa fun. Emi ko beru enikeni....Eledumare nikan ni mo beru. Ti o ba ko ifa, O ko si apo(do do) ara re ni. Ti o ba ni oogun, O ni si apo ara re ni. Tori ara(re re) eni(re re) ni a se ma n ko ifa. Ati aasan, ati epe, ati egede, ati apepa, or whatever gbogbo e ni n be nikun awo Babalawo o ni kere titi(mi mi) ko ma ni Esu nikun. O dorun kato gb'oku Ile(re do). 1 Like |
Culture / Re: .. by Ifankaleluya: 10:35pm On Mar 17, 2016 |
Ifa ni; Ogbori ngbiri a tehin dopo Ona(do do) taa ba to ri Nii se ni siba(do mi) sibo Ohun rere ni yowo(re mi) obi ninu aso(re re) ohun buburu(mi re mi) ni yowo ofa(re do) ninu apo(re mi) Lodifa fun ako(re re) aaya Lodifa fun abo(re re) aaya Lojo ti won lo oko iwaje Ako aaya ni koloko ma ku Ki igi-Ogunbere ma faya Ti o ba di iwoyi amodun Ki a ri bi jo,Gbantete,gbantete Abo aaya ni boloko ba le ku,ko ku Bi igi-Ogunbere le ya k'oya Bi o ba di ni amodun Ao ri Ibomiran jo,Gbantete,gbantete. E dakun, e wo lo se ire ninu won? Ela-boru,Ela-boye,Ela-bosise. 3 Likes |
Culture / Re: .. by Ifankaleluya: 10:20pm On Mar 17, 2016 |
@healthfirst......I noticed you online,that's why I login. I don't av any ill-will against you. Some people av talked to me abt d issue,so,to clarify my stands,i don't av personal issue with you. Agba kii wa loja,ki ori omo-titun ko wo. 3 Likes |
Culture / Re: .. by Ifankaleluya: 5:39pm On Mar 17, 2016 |
dominicson: Ori a gbo, Ori a to ooo. Okare omo-onibabalawo ''Ogbe'yonu'' lo ki yen. Ninu Ogbe'yonu yen na ni ifa ti tun wipe; Ibinu(do mi mi) o da nkan Suuru ni baba iwa Agba to ni suuru Oun gbogbo lo ni Difa fun ina(re mi) To l'oun o j'oye olonroro Abu fun oorun(sun) To l'oun o j'oye olonroro Dia fun osupa kirimu To l'oun o j'oye olonroro Ebo won ni ki won o se Osupa nikan ni nbe leyin ti n se ebo A m'osupa j'oye olonroro Ire de A m'osupa j'oye olonroro aye gun(mi) Lasan(mi mi) ni ina gb'oju ina o ni iwa ninu Lasan L'oorun gb'oju oorun o ni iwa ninu Osupa j'oye olonroro Ire(re mi) de. Ibinu ko da nkan Agba to ni suuru ohun gbogbo lo ni. Aboru,Aboy,Abo-sise. I'm not angry with anyone here! 2 Likes |
Culture / Re: .. by Ifankaleluya: 5:20pm On Mar 17, 2016 |
[quote author=whykay77 post=43843481]@ifankaleluya why the grudges with @healthfirst mose bi awo lon gbawo ni gbonwo bi awo oba gbe awo nigbonwo awo ate awo aya. If truly you don't have any grudges with him then why not agree instead of disagree. If there is anything bugging you say it then we all Yoruba here can both contribute and solve it. Also @healthfirst why selling books when you said you are helping this trend as a yoruba Man. Even if you want to sell the book you should put the interest of the lovers of yours at heart, we all know how nigeria is now money is not flowing like before becos of budget. You can reduce the price from the said amount to something convinient remember we are all Kaaro oojire. @ifankaleluya wade off this attitude of giving people uncompleted herbs. This thread should be as uniformly as ever why do we Yoruba always hate and tends to do iwo ju mi emi o ju ooo kind of attitude God gives us all we need but greediness and Pride makes us lacky in everything. Yoruba Eronu yin ooo. E fote sile ka di jo gbe ogo Yoruba ga.... Ote ole gbe wa de ibi kankan. Moki gbogbo ile ooo ati awo ati ogberi. Ati alfa,adahunse,elerindilogun,olopele ati eni mewe megbo. Agba to Banbe ni Be Pls Yoruba ogbodo rehin. Let's solve this Pls together.[/ 1 Like |
Culture / Re: .. by Ifankaleluya: 3:26pm On Mar 16, 2016 |
[quote author=zenith329 post=43813919][/quote] isu etipon-ola ni, kiise ewe-etiponla ooo. 1 Like |
Culture / Re: .. by Ifankaleluya: 3:23pm On Mar 16, 2016 |
Zenlife: @Zenlife Pls drop your e-mail. i'l forward it to you. |
Culture / Re: .. by Ifankaleluya: 3:21pm On Mar 16, 2016 |
[quote author=zenith329 post=43815028][/quote] Ere(do do) ina. |
Culture / Re: .. by Ifankaleluya: 3:18pm On Mar 16, 2016 |
dominicson: @domincson O kare omo-onibabalawo. Ti o ba je wipe o ti te-ifa, ifa o la o si rere. Ti o ko ba si ti te, igbakigba ti o ba te, ifa o ro(do) oo, yio si la o si rere Tori ifa ni; Poro bayii, ala bayii a difa fun Irẹ ti o tẹ meji ti o si la gudugudu. Ero-ipo, Ero-offa igbat ire(do do) te meji lo to la(do) gudugudu. thank you so much. IFA NI; Okiti(do do do) bamba ni pekun opopo a difa fun Alagan a bu fun Esu. Labalaba(re re mi mi) nikan(do do) ni nbe leyin ti n sebo. Labalaba ni, e wo inu(re mi) mi e wehin mi, Labalaba o mo lote(mi do) ninu. E wonu mi e wehin mi,Labalaba o ma lote ninu. I don't keep any grudges with him(healthfirst). Once again, Ifa a gbe oooo. Aboru, Aboye, Abo-sise. 2 Likes |
Culture / Re: .. by Ifankaleluya: 9:10pm On Mar 15, 2016 |
Ayomidegbenga1: Se e le ri aloku eni fafa? Ti e ba ti ri ki e kan si mi. |
Culture / Re: .. by Ifankaleluya: 3:08pm On Mar 15, 2016 |
Fun awon ti won bere asiri-bibo lori e-mail. E lo re wa isu~etiponola, ewe papasan,awom miran n pe ni dedenkude, eyin adire ororo meta,ati ori. E o lo awon ewe yen papo ni,eo jo eyin yen sibi kan,eo da ewe yen si ti e ba ti lo tan,eo po papo daada. Eo ju ori yen sinu agbada,ti o ba ti yo,ori yen ni eo fi din eyin yen. Idi-ikoko yen o gbodo kanle mo oo. Ti o ba ti di ni oru,eo bo ara sile ni ihoho,eo se adura si,eo si ko je. E o ti wa iyere-osun sile, iyere-osun yen ni e o fi te eji-ogbe eo wa pe ifa re si. Mo ti fi ifa yen sile lori fanran yi,e lo re wa nibi ti mo ti ki ifa pe''Oro kan n se mi bi kin ma jo,bi kin ma jo''. Ti e ba ti pe ifa yen tan,eo fi owo(money) gba iyere osun yen jo,eo da senu. E le mu schnapps tabi seaman kekere si tori ko dara ki eniyan ma mu omi le aseje lori. Adura yin yio gba ooo. Ela-boru, Ela-boye, Ela-bosise. 2 Likes |
Culture / Re: .. by Ifankaleluya: 2:52pm On Mar 15, 2016 |
ONILEIFA: THANK YOU MY FRND,DONALD TRUMP IS A GREAT MAN. BUT, I DO NOT NEED A THREAD. kiise gbogbo ewe-eko ni a ma n darijin. Tori a ma n fi ewe-eko se ifa-abilu o ni osa-lu~ogbe(osa-esu). Sugbon,o ko ti e se(offend) mi rara! |
Culture / Re: .. by Ifankaleluya: 10:41am On Mar 15, 2016 |
sammyjay76: The truth is that,maybe he(healthfirst) had falls a victim, bought some books sometimes ago & want to re-sale it for you people. You better forget the tag that he is an ifa-priest as he presented himself initially. |
Culture / Re: .. by Ifankaleluya: 10:33am On Mar 15, 2016 |
skamo74: |
Culture / Re: .. by Ifankaleluya: 11:19pm On Mar 14, 2016 |
Zenlife: @zenlife With a gaiety,I salute your courage. I think you challenged him(healthfirst) on this thread,but,why he opted to responded on general section? I'l like him to come out here & named those he reffered as ''semi-iliterate, do-no-good,& ill-will chartalans'' that he stated to quoted your post. Before,I see him as a chamelon that do change as its surrounding changes,but,now I can finally resolved that he is jst a gadfly. Let him go ahead to execute his intent. I'l not fold my hands & watch him abusing ifa-verses,& hide under the false pretence that he is ifa-priest to dupe users of this thread. |
Culture / Re: .. by Ifankaleluya: 1:57pm On Mar 13, 2016 |
dominicson: O kare jare....iwo nikan loro mi ye. Ori a gbo, Ori a to ooo. 3 Likes |
Culture / Re: .. by Ifankaleluya: 10:17am On Mar 13, 2016 |
Ifa ni, Eni a ba ba wa ode la ba rele Eni aja ba wa ni aja ma n ba lo A difa fun orunmila Ifa ni ohun o koju si akapo Ifa koju si mi wo mi ire Eji-koko iwori. Eledumare yio koju rere si wa. Ase-orisa lenu mi,eyi ti mo ba wi ni irunmonle yio gba,ase-orisa lenu mi. Ela-boru,Ela-boye,Ela-bosise. 2 Likes |
Culture / Re: .. by Ifankaleluya: 10:08am On Mar 13, 2016 |
@jbabas. IFA(OGUN) WA TI ENIYAN FI MA N SE ORIRE, ORU NI A MA N WE OSE YEN. KODA TI A BA N WE OSE YEN LOWO, ENIKENI TO BA FI OJU KAN WA NI AKOKO YEN NA TUN MA SE ORIRE. ENIYAN MERINDINLOGUN(16) LO TUN MA SE ORIRE LEYIN YIN. SUGBON BAWO NI A SE LE RI OKU-IMI~OSUMARE TI O JE ORIGINAL? ORI-ERANKO KAN TI WON N PE NI IRU. ANYWAY....KIISE OGUN TI MO LE FISILE LORI FANRAN YI RARA. SUGBON TI E BA RI OHUN TI MO SO YEN, E JE KA RIRA(lets see). |
Culture / Re: .. by Ifankaleluya: 8:46pm On Mar 12, 2016 |
skypeme: E ma fi se ibinu baba. Alfa yen fe ki e wa holy ni jawe. 1 Like |
Culture / Re: .. by Ifankaleluya: 8:43pm On Mar 12, 2016 |
jbabas:Ibere yin yen o fi gbogbo ara ye wa. E tun ibere yen ko lona ti yio gba ye wa. |
Culture / Re: .. by Ifankaleluya: 10:12pm On Mar 11, 2016 |
sammyjay76: Beeni...e o lo re be won ni omo-owu yen lagbade ni. Ki esi so fun won wipe omo-owu yen o gbodo wo omi ooo. 2 Likes |
Culture / Re: .. by Ifankaleluya: 9:42pm On Mar 10, 2016 |
kuddus: ERO-ABILU PE ORISI-RISI.....ADURA MI NI WIPE KI OLORUN MA JE KI E BO SI OWO(HAND) BABALAWO TI O NI EKO(KNOWLEDGE) DAADA. TORI KIN-NI KAN WA TI A N PE NI AKOFA(NEUTRALISES OF CHARMS OR MEDICINE IN SOMEONE's BODY), KINNI YI NI BABALAWO TO BA LEKO DAADA MA N KOKO SE LATI FI BA OGUN TO WA LARA ENIYAN JE TO BA FE BA ENIYAN JA. AASAN(gbolohun) RE WA, WON SI MA N SA OMIRAN LORI ESU PELU AWON EWE-IFA KAN. SUGBON JU GBOGBO E LO, TI E BA TI RI OMO-OWU KI E KAN SI MI. KIISE OGUN TI MO LE FI SILE LORI FANRAN YI. 2 Likes |
Culture / Re: .. by Ifankaleluya: 6:39pm On Mar 10, 2016 |
Ifa ni, Ọtọtọtọ, ọrọrọrọ, ọtọtọ laa jẹpa. Ọtọtọ nla jẹ imumi. Ohun tori tori, ohun tore tore nlaa fọba makin nile Iranje, ko ba le fi ohun to ri to re ta ni lọrẹ a dia fun Ogotẹẹrẹ ẹyi ti n gbogun lọ Ẹhinwọran. Ogotẹẹrẹ lorukọ a n poko. Ẹhinwọran lorukọ a n pobo. Eewọ oriṣa oko ii jagun ilobo ko sanwọ-o. Lagbara lowo Eledumare ao ni sanwo(lack) ohun rere. eewo-orisa ni, oko kii jagun ilobo ko sanwọ. Ela-boru, Ela-boye, Ela-bosise. 2 Likes |
Culture / Re: .. by Ifankaleluya: 6:28pm On Mar 10, 2016 |
Oluokunoluwole: E MA BINU MESSAGE PO LORI E-MAIL WA NI. |
Culture / Re: .. by Ifankaleluya: 6:26pm On Mar 10, 2016 |
wale259: OMO YEN SI KERE OO. |
Culture / Re: .. by Ifankaleluya: 6:25pm On Mar 10, 2016 |
wale259: BEE NI. |
Culture / Re: .. by Ifankaleluya: 10:56am On Mar 09, 2016 |
wale259: BEE NI. |
Culture / Re: .. by Ifankaleluya: 10:54am On Mar 09, 2016 |
wale259: IFA-ISOYE TI O MA N JE GBOGBO OHUN TA BA KA KO DURO SIKUN WA LOKOKAN. E LO RE WA IGBA-AHUN, ATI IKARA-HUN IGBIN. AO JO MEJEEJI PAPO, AO LO KO NI ATAARE NINU OO AO WA TE NI IFA OFUN-SE (OFUN LOWO-OTUN ATI OSE LOWO-OSI) NI A N PE BAYEN AO WA PE IFA RE SI BAYI MO DE IBI WON TI N MUMI OGBON(WISDOM) MO BA WON MU MO DE IBI WON TI N GBAMON-RAN IMO MO BA WON GBA ADIFA FUN ORUNMILA NIJO TI N LORE KO MO-IFA, TI N LORE KO OGUN MO-OGUN WON NI BAWO NI O SE NI GBAGBE IFA NI EEWO-ORISA IGBIN KII-FA KO GBAGBE IKARA-HUN BEENI AHUN KIIFA KO GBAGBE IGBA-EYIN RE WON NI TI O BA GBAGBE BAWO NI O SE NI WO'NU ARA WON ORUNMILA NI EEWO ORISA IGBIN KII-FA KO WO'NU AHUN BEENI AHUN KIIFA KO WO'NU IGBIN OFUN-SE FUN MI NIYE TEMI KI N MU SAWO. AO MA FI MU EKO-TUTU. BI WON TI MA N SE NIYEN, E LE TUN BERE LOWO BABALAWO MIRAN TI O BA MO IFA YEN. ELA-BORU, ELA-BOYE, ELA-BOSISE. 3 Likes 1 Share |
(1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) (of 10 pages)
(Go Up)
Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 98 |