Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,163,411 members, 7,853,810 topics. Date: Saturday, 08 June 2024 at 03:20 AM

Ifankaleluya's Posts

Nairaland Forum / Ifankaleluya's Profile / Ifankaleluya's Posts

(1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) (of 10 pages)

Business / Re: Binary Options Alertz/strategies Season 5 !!hot!!! by Ifankaleluya: 10:01am On Apr 04, 2016
[quote author=haywhy59 post=44379206][/quote]

Builth with my MT4 bro....i've tried to share it, but unbable to get it done.
Business / Re: Binary Options Alertz/strategies Season 5 !!hot!!! by Ifankaleluya: 9:59am On Apr 04, 2016
STRENGTH CORRELATION

Business / Re: Binary Options Alertz/strategies Season 5 !!hot!!! by Ifankaleluya: 9:51am On Apr 04, 2016
GOOD MORNING. LONDON SESSION BEGINS ABOUT AN HR AGO

Business / Re: Binary Options Alertz/strategies Season 5 !!hot!!! by Ifankaleluya: 7:33pm On Apr 03, 2016
henryadex:
People in the the house please welcome the youngest binary trader to the forum, trading the binary option without a meta 4 platform is a great task, is there any binary company with its own MT4 platform ?

I don't think there is a means to trade Binary without MT4. Because every Binary option companies use to get or linked their websites to forex. Nd if you want to trade Binary without MT4...how can you forcast or get the present condition of the market?
Business / Re: Binary Options Alertz/strategies Season 5 !!hot!!! by Ifankaleluya: 1:00pm On Apr 03, 2016
I'm there to help and rub-minds together with the great traders on this thread. Below was the typical example of what happened on FRIDAY.

Business / Re: Binary Options Alertz/strategies Season 5 !!hot!!! by Ifankaleluya: 12:53pm On Apr 03, 2016
pocoapoco88:
somtimes wot u tink is a breakout on lower timeframe mite ba false brk on higher timeframe,and wot u tink is a false brk on lower timeframe mite b a potential brk out on higher timeframe.dats y its an unstable marketshow interest nd i mite explain further or beta stil jst use ur IQ

The most important thing in trading either spread-betting known as Forex or Binary option is to understand the market.

How do you understand the market? The first thing to do is to identify the trend of a particular pair.

I've managed to test many of the indicators and found that they were lagging, I think the best way out is to trade price action.

You look for the strength of each currency to fix the strongest and the weakest currencies, after you have done that, you open a chart for the

pair of currencies that you have identified to check for the trend of the pair. then, you check the trend on the higher time-frame like 15MINS,

30MINS, 1HR, AND 4HR. if the trends are the same,then you go to 5mins to get the retracement, once the 5mins is against the trend, you

should know that, it is a retracement. Then, you have to wait for the price action to move th trend on the lower time-frame in the direction of

higher time-frame to confirmed that the retracement has end and follows the trend provided NO News on those currencies you identified. As you have known that NEWS always change the direction or trend of a market.

NOTE; If there is a great movement or volatility in the market, both RESISTANCE OR SUPPORT have no means to stop the movement.

Bids you all green pips ahead of the market resumption in the evening.

1 Like

Culture / Re: .. by Ifankaleluya: 8:17pm On Mar 30, 2016
IFA ERO TI A MA N SE SINU ILE TABI SHOP
Ewe-ekuku,
Ewe-ekuya,
Ewe-imi esu
Ejo-aro kan to tobi
ao gbele larin ile tabi shop yen,
ao fi eja-aro yen tele koto yen,
ao ko ewe-imi esu le lori
ao wa ko awon ewe yen toku si
ao wa fi yepe ki mole(mi do),
Awon agbalagba ki yio le wo ile tabi shop wa lati di wa lowo..!

3 Likes

Culture / Re: .. by Ifankaleluya: 8:07pm On Mar 30, 2016
Ifa so ninu odu-mimo re Ogbe riku sa.

Ogbe sa

N o la

Ogbe ko sa

N o la

Oriire Agbo nii s'Agbo nire kaa oko

difa fun Alakoko(re mi mi mi)

A bu f'osorun akoko(do mi mi)

Alakoko oo, Oba lo je!

Osorun re Oba lo je!

Ifa bo ba semi(re mi) titi

ki o gbemi dele Aje(re mi)

kinrinjin(re re re),kinrinjin(do do mi)

Ibi rere n l'ope n gbemi i re,

Ori o ba semi titi ki o gbemi dele

ire gbogbo kinrinjin, kinrinjin

Ibi rere n l'ope n gbemi re.

Lagbara lowo Eledumare, Ori wa yio se wa titi, yio si gbe wa dele(mi mi) Ire gbogbo. Ase!

Aboru, Aboye, Abo-sise.

2 Likes

Culture / Re: .. by Ifankaleluya: 2:45pm On Mar 26, 2016
omoemi007:
Kini iwulo ewe akoko

Iwulo ewe-akoko(re do re) po daadaa, koda a ma n fi se awure.

Bayi ni a ti ma n lo fun awure

Ao lo wa ewe-akoko yen ti yio po daadaa...ao wa fi schnapps gidi gbo ewe yen, ao wa ro pada sinu igo yen, ao wa da apo aso fun-fun fun,ao wa gbe si igun(re re) yara.

Ao ma mu die-die ni ara-aro pelu adura,ti a ba ti fe bu,ao fi owo(hand) gba igo yen,ao wa wi bayi pe...''fun mi lowo kin daso fun oo, ai ti fun mi lowo ni ko ti je kin n daso fun oo''. Adura wa yio si gba pelu ogo-Olohun!

Aboru, Aboye, Abo-sise.

2 Likes 1 Share

Culture / Re: .. by Ifankaleluya: 10:15pm On Mar 25, 2016
dytex:
eku ise o odua agbewa o ejowo nje tiwon ba ji irawo eniyan nje eniyan le ri gba pada eseun

Baba...ti eniyan kan ba so fun yin wipe ogun kan wa ti e le se. O kan fe gba owo lowo yin lasan ni.

E ke si awon babalawo to gbofa yanran-yanran ki won o ba yin so ifa kale ni, ki ifa o ba yin ba olodumare soro ki eleda yin o so bi e o ba ti rin irin-ajo aye yin . Etutu dara ju egberun-ogun lo..!

2 Likes

Culture / Re: .. by Ifankaleluya: 10:09pm On Mar 25, 2016
bwayomide:
eejo baba,se ao ka omo ileke itun ati ifa ye ni woro kankan ti yio fi pe merindinlogun ni tabi a o ka ni eyokan bi won se di si ara igi re titi ti yio fi pe merindinlogun,ese baba,oodua a gbe wa ooo.

Ao ka Ileke-Itun yen ni eyo ko kan ni.

2 Likes

Culture / Re: .. by Ifankaleluya: 7:19pm On Mar 24, 2016
IFA NLA TI ENIYAN FI MA N SE ORIRE ATI INTERVIEW ONIBEJI

1.

IYE-AGBE EYOKAN

IYE-ALUKO EYOKAN

IYE-OKIN EYOKAN

IYE-EYELE MERINDINLOGUN

ILEKE-ITUN MERINDINLOGUN

ILEKE-IFA(do do) MERINDINLOGUN

ABERE MERINDINLOGUN

EWE-IRE

FITILA OLOJU-MERINDINLOGUN

ORI(do mi)

EPO-PUPA

ADI

HNMMMMMM!....IFA ELERI IPIN ATUN ORI E NI TI O SUN-WON SE, MO MORI-BALE. ABORU, ABOYE, ABO-SISE GBOGBO BABALAWO.

EWE-IRE YI NI AO KOKO GUN DAADAA, AO GUN AWON IYE YEN MO, AO KOKO LO AWON ILEKE YEN LORI OLO(re re) KI O MA BA TA DANU, AO WA

DA SI INU ODO YEN, AO GUN GBOGBO RE PAPO, AO WA GUN OSE PAPO MO. AO GBE EPO-PUPA, ORI, ATI ADI YEN SINU OORUN LOKOOKAN.

TI WON BA TI YO DAADAA, AO DA WON SINU FITILA YEN TI YIO PO DIE, AO WA GBE OSE TI A TI PARI YEN SINU FITILA YEN, AO TI SE

OWU-FITILA SI GBOGBO OJU TO WA NIBI FITILA YEN. NITORI TO O BA TI KU ISEJU-MARUN TI A FE WE OSE YEN NI AO TI TAN INA SI GBOGBO

OJU FITILA YEN KI A TO BU OSE YEN, INA YEN YIO SI WA NI TITAN TI AO FI WE TAN KI A TO PA.

GBOLOHUN RE NIYI TI AO MA PE TI A BA TI FE BU OSE YEN

EWE IRE O NI ORUKO MEJI, IRE NI IRE N JE, ITUN LO NI KI TOMODE-TAGBA MA FI IRE OWO WON TUN MI SE, IFA LO NI KI

TEWE-TAGBA MA IRE OWO WON FA MI MORA, ABERE LO NI KI TERU-TOMO MA FI IRE GBOGBO BERE MI, BI EIYE BA PE IGBA NINU IGBO WON A SI

FI IRE GBOGBO JIN OKIN, KI TERU-TOMO, TEWE-TAGBA MA FI IRE GBOGBO JIN EMI LAGBAJA OMO LAGBAJA,BI AGBE TI N GBERE PADE OLOKUN TI

AYE FI N YE, KI TOMODE-TAGBA MA GBE IRE PADE MI KI AYE O YE MI, BI ALUKO TI N GBERE PADE OLOSA, KI TEWE-TAGBA O MA GBERE PADE MI, TOTUN-TOSI NI EYELE FI KORE WOLU,ATI OTUN ATI OSI MI NI KIN N FI MA GBARE LOWO TAKO-TABO, OWO(hand) MI WA BA FITILA LONI, LATI ONI LO KI IMOLE O TAN SI ONA MI KI IRE GBOGBO MA JE TEMI LAGBAJA OMO LAGBAJA.


2.

TI O BA TI KU OJO-META TI A FE LO SIBI INTERVIEW NI AO TI MA WE OSE YEN. AO WA LO WA AFOMO-RERE(mi mi), AO LO MO ATAARE EYO

KAN PERE, AO FI SIN GBERE KAN SI IWAJU ORI WA.

PELU OGO-OLORUN ADURA WA YIO SI GBA.


ABORU,ABOYE, ABO-SISE.

1 Like

Culture / Re: .. by Ifankaleluya: 7:56pm On Mar 23, 2016
@wildLife pls i need ur e-mail or line.
Culture / Re: .. by Ifankaleluya: 7:53pm On Mar 23, 2016
IFA ISEGUN OTA KAN NI

Eso-agunmona eyo kan ni ao lo re wa, ao lo po mo omo-atare-meta. Ao fi sin gbere kan si aarin ori wa,ao wa fi omi-omu pa oju re.

3 Likes

Culture / Re: .. by Ifankaleluya: 7:50pm On Mar 23, 2016
Aje(re mi) bori ogbon(re mi)
Otosi(do do do) so ofo oro
A bu ni lole(mi re) o mo oun ti n se ni
A kunle(mi do) a yan ipin
A dele aye tan oju n kan gbogbo wa
Ipin o se pada lo yanmiran
Aya fi bi a ba tun aye wa.
Ewe le(re) ole(mi re) le alele wure
Dia fun orunmila baba o ma se owo(do do) imele
Imele(do mi mi) ni mo se ti mo fi lowo(mi mi),laya,bimo,nire gbogbo
Ero(do do) ya, e wa wo ise imele n se.
Eledumare yio je aye onikaluku ko rorun(re do) ooo. Ase!
Aboru,Aboye,Abo-sise!

2 Likes

Culture / Re: .. by Ifankaleluya: 7:32pm On Mar 23, 2016
skamo74:
Thanks Baba. this is what we want sir. May you live long sir. thanks for the Understanding sir
stay blessed sir


thank you too 4 d gesture.
GOD bless u real gud!
Culture / Re: .. by Ifankaleluya: 7:31pm On Mar 23, 2016
wale259:
Se a ma ko ewe ati egbo ajeobale yen le Ega yen lori ninu Ologinni abi a pa ologinni de a si ko ewe ati egbo yen le ni?aso waji yi,se a ma ri lodo anwon elewe omo ati wipe ki ni minrinti

minrintin yen tumo si wipe ti ko ni abawon kankan(ko dudu dale),

aso-waji yen, aso-dudu ni ooo,awon elewe-omo ma n ta daadaa.

1 Like

Culture / Re: .. by Ifankaleluya: 7:28pm On Mar 23, 2016
Lero70:

edakun baba se eeso laara pupa ni tabi funfun. Eseepupo.

E seun fun ibere yen, eso-laara pupa lo dara ju, sugbon mejeji ni baba-awo mi ma nlo.
Culture / Re: .. by Ifankaleluya: 7:27pm On Mar 23, 2016
Lero70:

ejoo baba ifankaleluya, se omo ologinni dudu ni aoloni? nitori molerope yio soro pupo ki agba ologbo too le wonu abo-adiye, abi onibiaotisee ni?

Olonginni yen o nilo lati tobi pupo. Sugbon abo adire yen gbodo je eyi to ti pa omo ri oo. O gbodo dudu tan daada....ni yio fi je ise ti a fe ko je.
Culture / Re: .. by Ifankaleluya: 7:24pm On Mar 23, 2016
wale259:
Sir,igba kigba lale we Ose yi abi bawo?

Bee ni. Ose yi ko ni alebu kan-kan...kiise wipe ao ma ko owo ninu igba(re mi) kan or whateva. O kan jewipe olohun a ma bo asiri wa ni akoko ti a ba n lo ni.

1 Like

Culture / Re: .. by Ifankaleluya: 10:15pm On Mar 22, 2016
IMULE AWON AJE

Odidi Ologinni dudu minrintin kan ti ko ni ami.

Eiye ega kan

Abo adie dudu kan

Ewe-ajeobale pupo

Egbo-Aje-obale

Aso-waji

ko ni ataare kan-kan

ao la adie yen ninu,ao ki ologinni yen bo inu re,olonginni yen na ma wa ni lila(mi do) ninu,ao wa ki eiye-ega yen sinu re, ao wa ko ewe ati egbo aje-obale yen le lori,ao wa fi aso-iwaji yen di papo.

Ao gba sinu agbada, ti a ba ti jo tan ti a si lo,ao wa te ni ifa Osa-meji.

Ifa re:

Mo siju wo apa mi otun mo ri igba eleye,won fori gun rawon igege igege. Mo siju wo apa mi osi mo ri igba eleye,won fori gun rawon igege igege(re do do),dia fun orunmila nijo ti nbe larin eleye,ti won ni awon da ise baba ru,awon o ba ise orunmila je,orunmila ni iro ni won n pa,ati ile atona ni a fi jin olonginni,e ma fi gbogbo oun ti mo ba se jin mi,eiye keye kii fo ko ba sori ajeobale,bi alaso waji ba koja loru oro re a si ru eleye ki eleye loju. Ki oro emi lagbaja omo lagbaja ko ma ru eleyekelye loju.

Ao ma fi fo eko-tutu mu lalaale.

Aboru,Aboye,Abo-sise!

3 Likes

Culture / Re: .. by Ifankaleluya: 9:51pm On Mar 22, 2016
Ifa ni;
Eke(do mi) a pa eleke
Odale(do do do) a pa odale
Oun ti a ba se nisale(mi do do) ile
Oju olodumare nii to
Dia fun Amokun-se-ika(do do)
To ni oba aye ko ri oun
Bi oba aye ko ri o n ko
Oju Olodumare nwo oo.
Aboru,Aboye.

1 Like

Culture / Re: .. by Ifankaleluya: 9:46pm On Mar 22, 2016
wale259:
Sugar melo la ma lomo?
kosi iye sugar ti a ko le lo mo.

2 Likes

Culture / Re: .. by Ifankaleluya: 8:38pm On Mar 22, 2016
EYONU AWON AJE
Elo re wa eso-laara to po daadaa
Odidi-atare kan
Ao jo won papo ni
Ao wa lo(re) sugar mo
Ao ma da senu pelu adura ni alaale ati aro.

Aboru,Aboye.

3 Likes

Culture / Re: .. by Ifankaleluya: 8:28pm On Mar 22, 2016
FUN ENITI N LA ALA-KALA

Ewe-ajeobale mokanlelogun

Omi-agbon to po daa daa.

Omi-agbon yi ni ao fi gbo ewe-ajeobale yen,ao mu die ti a ba fe sun,ao si ji mu iyoku ni aro kutu-kutu.

Bayi ni ao se ma se ti adura wa yio fi gba.

3 Likes

Culture / Re: .. by Ifankaleluya: 8:23pm On Mar 22, 2016
Olori(re mi mi) niyanri

Ogberi(do do do) o gbodo gba obi pa lowo babalawo

Adifa fun ose(do mi) nijo ti n lo re rugba ise(do mi) sigbo, ebo won ni ko se

Ogbebo nibe o si sebo

Oru tesu o si tu

kiipe kii jina,ka wa ba ni ni ijebutu ire(re re)

Ijebutu ire la b ni lese(mi do) obarisa.



Ela-boru,Ela-boye, Ela-bosise.
Culture / Re: .. by Ifankaleluya: 5:16pm On Mar 21, 2016
Stop exchanging words on a dead issue. No rifts,or whatever between anyone here.


In fact, I & Healthfirst had a chat late yest9t.

You av not c my post here again because am a busy type.

I only like adding value whenever I see people talking about Yoruba culture,our gods & tradition.

Beeing an ifa-priest does not means my earnings for living was from that source.(i.e. Some governors are ifa-priest,&also some musicians)

I only like to shed-light about Ifa anywhere the needed be.

I hope Healthfirst w b back,& I also w alys contributes anytime I wish & @leisure to do so.

2 Likes

Culture / Re: .. by Ifankaleluya: 2:46pm On Mar 19, 2016
whykay77:
@ifankaleluyah I want to urge you not to post anything that will affect the future of people on here for the sake of those who do not know the consequencies. Not everyone knows what he or she will do to avert the horror when it beckons. Thank you in anticipations. Just a saying. Omo ti ologun arinya kogbudo je aayan. Toto se bi owe awon agba.


Thank you, don't be scared! just bear it in mind that whatever i post here is useful for you peoples & has no side-effect.
Culture / Re: .. by Ifankaleluya: 2:40pm On Mar 19, 2016
FUN AWON TI WON N TUN BERE ISOYE

IFA-ISOYE ONI OBARA-MEJI NIYI

Ewe oniyemiye

Ojuso-eko mesan

Eiye awoko kan

Kuluso mesan

Ori-ikun(re mi)

Sonso ori ogan

Odidi ataare kan ti omo re kan kan ko so'nu

Ao jo gbogbo re papo ni, ti a ba lo tan, ao te ni obara-meji.

Ao wa pe ifa re bayi;

Ikun(re mi) ni fi agbari se ile

kelebe(do do do) ni fi ono-ofun sodo

Okiti banba won so seu-seu(do do) ope(do re) jo rigidi(do do do)

Wa fi inu mi se ibugbe oo

Obara-nikosi ifa ma ko mi niye temi lo, Obara-nikosi

ao fi sin gbere si aya(do do) 9 fun okunri, 7 fun obinrin. ao da iyoku sinu oyin, ao ma la laro-laro

Odu yen niyi nisale yen


Aboru, Aboye.

2 Likes

Culture / Re: .. by Ifankaleluya: 2:19pm On Mar 19, 2016
OSO KEKE KAN TO GBONA NIYI

Ewe-laali

Eyin adire ororo(do do do) merin

Oga aaye kan

Owo-titun (#500 or 1000)

Igba-olomori

Ose

Oyin

Lofinda bintu meji.

Ao gun ewe-lali yen daadaa, ao gun awon eyin yen mo, ao gun ose yen papo mo, ao fi oyin po ose yen, leyin na ao tun po pelu lofinda bintu kan, ao fi owo(money) yen tele(mi do) igba, ao fi Oga yen le owo yen lori ki o gba awo(do do) owo yen, ao gbe ose yen le lori, ao wa lu ose yen laarin ti yio fi kan Oga yen lara, ao wa tun bintu kan to ku yen si. ao de igba yen pa fun ojo-merindinlogun(16days) ki a to ma we ose na.

Pelu Ogo-Olohun yio si ri be.

NOTE; Akii fi omi si oso yen ti a ba n se lowo oo.

Aboru, Aboye!

3 Likes

Culture / Re: .. by Ifankaleluya: 2:02pm On Mar 19, 2016
MO FE RO(urge) WA. E JE KA MU ORO(do do) KURO LORI ORO YEN.

SE EMO WIPE ORO-SISO OBEY HOOKE'S LAW, BI A BA TI N SO,BEE NI YIO MA GUN(do) SI, UNTIL IT EXCEEDS THE ELASTIC LIMIT.

SUGBON TA LO MO IGBA TI YIO EXCEED ELASTIC LIMIT? NO-ONE.

SO,LETS STOP POSTING ABOUT IT. KOSI ENIKENI TO N BA ARA WON JA LORI FANRAN YI.

LETS CONCENTRATE ON THE SALIENT OF THE THREAD.

THANK YOU ALL FOR THE SPOKEN & UNSPOKEN WORDS. I WISH YOU ALL, ALL THE BEST.
Culture / Re: .. by Ifankaleluya: 11:27am On Mar 19, 2016
Ifa ni;

A kii s'omo babalawo ka binu

A kii s'omo onisegun ka saigboran

A kii s'omo baale ka ba ilu je

Dia fun Adekambi ti s'omo okaransode
Mo gbo wipe won so ide mo ba won so.

Emi o ma ma mo oun won n fi se

Mo gbo pe won n s'ode mo ba won so.

Aboru, Aboye!

4 Likes

(1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) (of 10 pages)

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 56
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.