Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,160,826 members, 7,844,671 topics. Date: Thursday, 30 May 2024 at 05:28 AM

Ifankaleluya's Posts

Nairaland Forum / Ifankaleluya's Profile / Ifankaleluya's Posts

(1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) (of 10 pages)

Culture / Re: .. by Ifankaleluya: 10:54pm On Feb 24, 2016
ALIUDAVID:
Ekale o, ejo oruko wo ni won tun pe ewe 'rekunrekun' iba eyin ti olorun gbe ase ile aye fun.

Ewe-Rekureju
Apeje re tabi oruko miran ti won n pe ni Ewe-Balekale
Culture / Re: .. by Ifankaleluya: 8:15pm On Feb 24, 2016
Ifankaleluya:
Ifa ni kale wi awon won nile ado, Oriri mojo awo oke ijero,ogaga-laja awo ile owonrin-sindin,adifa fin orunmila nijo ti ifa lohun o so akapo ohun di eleni. Nje Ifa to ba se mi ti mo fi di olowo,iwo ni n o ma yin,to ba se mi ti mo fi di olomo,iwo ni n o ma yin,ti o ba se mi ti mo fi di onire gbogbo,iwo ni n o ma yin,ogaga-laja awo ile owonrin-sindin ko wa so mi onire gbogbo. Eledumare yio so gbogbo wa di onire gbogbo ooo. Ase orisa lenu mi,eyi ti mo ba wi ni irunmole yio gba,ase-orisa lenu mi. Ase ooo!

1 Like

Culture / Re: .. by Ifankaleluya: 7:53pm On Feb 24, 2016
Ifa ni kale wi awon won nile ado, Oriri mojo awo oke ijero,ogaga-laja awo ile owonrin-sindin,adifa fin orunmila nijo ti ifa lohun o so akapo ohun di eleni. Nje Ifa to ba se mi ti mo fi di olowo,iwo ni n o ma yin,to ba se mi ti mo fi di olomo,iwo ni n o ma yin,ti o ba se mi ti mo fi di onite gbogbo,iwo ni n o ma yin,ogaga-laja awo ile owonrin-sindin ko wa so mi onire gbogbo. Eledumare yio so gbogbo di onire gbogbo ooo. Ase orisa lenu mi,eyi ti mo ba wi ni irunmole yio gba,ase-orisa lenu mi. Ase ooo!

(1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) (of 10 pages)

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 9
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.