Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,155,529 members, 7,826,983 topics. Date: Tuesday, 14 May 2024 at 02:26 AM

Mama H.I.D Awolowo Ti Lo Sun Ninu Oluwa - Politics - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Politics / Mama H.I.D Awolowo Ti Lo Sun Ninu Oluwa (713 Views)

Atiku Abubakar Receives His National I.D Card In His Yola Residence. Photos / Atiku And Wife Register For National I.D Card At Thier Abuja Residence / BREAKING: H.I.D Awolowo Dies At 99 -- TVC Breaking News (2) (3) (4)

(1) (Reply)

Mama H.I.D Awolowo Ti Lo Sun Ninu Oluwa by SisiGbeborun(f): 9:04pm On Sep 19, 2015
Won ni oja l'aye, gbogbo wa naa bayi la de wa na oja naa, bope boya, onikaluku a pada re'le naa ni. Mama, Oloye Hannah Idowu Dideolu Awolowo (HID) ti r'orun alakeji. Omo odun mokandinlogorun (99 years) ni mama n se ki olojo to de, ko da, osu meji pere lo ku ki mama HID pe omo ogorun odun. Iroyin ti a ri gbo ni wipe nkan bii wakati die seyin ni mama dake. Ireti wa ni wipe laipe, awon molebi a fi oro sita, lati se ikede iku mama.
http://www.sisigbeborun.com/2015/09/mama-hid-awolowo-ti-lo-sun-ninu-oluwa.html
Re: Mama H.I.D Awolowo Ti Lo Sun Ninu Oluwa by abat4real37(f): 9:22pm On Sep 19, 2015
Mama sun re o,Ki oluwa te mama si afeferere

(1) (Reply)

Polish Football Fans Protest Arab Invasion Of Europe / N200 Million Expended On Botched Buhari Visit To Cross River State / Even With General On Throne Bomb Still Went Off In Abuja

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 5
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.