Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,151,104 members, 7,811,105 topics. Date: Saturday, 27 April 2024 at 11:40 PM

Ogun Awon Bàba Wa - Culture (9) - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / Ogun Awon Bàba Wa (326075 Views)

Asiri Aiye Siwa Lowo Awon Agba Woli / Asiri Ijinle Awon Woli Lailai / Asiri Ogun Awon Baba Wa (2) (3) (4)

(1) (2) (3) ... (6) (7) (8) (9) (Reply) (Go Down)

Re: Ogun Awon Bàba Wa by 08101646045atwp(m): 2:36am On Jul 29, 2020
*ALUBOSA*
Ao ge alubosa si wewe, ao bu si igun yara wa, omanle Asian kiaisan ni inu ile yala otiwa ninu ile tele, tabi osesefe wole alekuro ni igun ile na ati gbogbo ile ti age si.

ELENKEJI TOTUN DABIRE: ao mu alubosa ti age si wewe, ao fi si atelese wa, ao wo ibose si omanda arunkarun duro ninu ago ara ni, ositun man tun gbogbo ago arase.

*ISU OGIRISAKO*
Ogirisako naa situn dara ninu awon egbogi fun iwosan: aomu ogirisako yi aogesi wewe, ao reé pelu omidun ati osan wewe tabi omi ati omi osan wewe, tabi emu ewa jinpo odimimu, gasi kan lojumo.

*EWE EWURO*
Ewuro, imiojo, Aidan, eeru awonka, alubosa. Bakanna ao gun papo ao sa si inu ile, tibagbe odi finfin ni turari, gbogbo ohun to nje Asian afojuri ati aifojuri ni yiolelo.

Asitunlemu turari yi bakanna, kiabu sinu omi gbigbona, kia fin pelu dida bulanketi bori pelue ki orure le WO ago arawa.

*EWE EWURO*
Ao gun kunna dada, bi agunmu, kiema busi omigbigbona fun mimu ni ekan lojumo.

*EWE AKOKO*
Ao gun Ewe akoko ati ewe dongoyaro pelu eso dongoyaro papo mo ose iwe eyikeyi, odi wiwe lararo.

Anfani situn wa fun eyin aworo sasa toje AWO, bii WOLI, ALFA, ati ISESE todarare loju, lati darapo Mon egbe awon ojogbon ti ati ngbe awon ise alagbara jade, ti ape orukore ni (AAA) ALUMONI AWON AKONI lori WhatsApp

ele fi orukoyin sile si ori :-
https:///8ahrCpBnxgS3qHb0L63Hp8

:- bere lati Omo ogbon odun losoke. 30 years above!
Jowo mase fi number re si abe comment'o
Whala koni payin'o
Add links yen si odo'e
Kede mura sile fun idahun si awon ibere wa Ni ekun rere.
Ajuwase o

1 Like

Re: Ogun Awon Bàba Wa by Olu317(m): 7:00am On Jan 21, 2022
Ẹ ku ìṣẹ tákun tákun

1 Like

Re: Ogun Awon Bàba Wa by 08101646045atwp(m): 10:40pm On Jul 29, 2022
Epa
Eleyi ni ama nfi nyo inira kuro laro,bi magun, majele, ata siso, ati bebelo, Alo sibi ti ewe olatidijo bawa, ao fi owogba pelu pipe oruko re :- olatidijo 3*, asalaye bi ase nfe koma sise si, ao wu tiditidi, ajopelu odidi padi atare kan, aolo ti yo kunna, ao mafi omi lo pelu pipe oruko re:- olatidijo, ao wa daniyan si wipe nkan baibai ti nsemin tabi ti mio mon ti ndami lamu, ni kiakia ni mo nfe kotidijo bai, ki nya mo igbe, ki ntomo ito,✅kosi ibiti akole gbesi,eleyi kiba ogunje. Odaju

Anfani situn wa fun eyin aworo sasa todarare loju, ninu ise isegun ibile tabi ti oyinbo lati darapo Mon egbe awon ojogbon ti ati ko arawa ni ona ti afi ntoju alaisan ni ona isegun ibile ati ti igbalode, ti ape orukore ni (ALO) ALAFIA LOGUN ORO) lori WhatsApp

ele fi orukoyin sile si ori :-
https:///8ahrCpBnxgS3qHb0L63Hp8

:- bere lati Omo ogbon odun losoke. 30 years above!
Jowo mase fi number re si abe comment'o
Whala koni payin'o
Add links yen si odo'e
Kede mura sile fun idahun si awon ibere wa Ni ekun rere.
Ajuwase o

1 Like

Re: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(m): 10:12am On Feb 22, 2023
E karo o gbogbo Omo Yoruba atata, gbogbo Awa ti awa ni Yara ikanni Ogun awon baba wa, ojumo ayo ni oni fun wa, eto idibo to bowa Yi emi enikeni wa o ni losi o, emi baba ayokomi Yi moda nkanni Yi sile tide pada bayi, lati ma ta yin lore okan o jokan asiri tewetegbo Yoruba. Number Whatsapp mi niyi, 08135072961.
Re: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(m): 10:17am On Feb 22, 2023
Akiyesi gbogbo eyiti e wa si Ori ikanni mi mawa polowo Yara yin, e dawo be duro lati akoko Yi lo, eyin enia mi baba ayokomi kobere owo lowo enikeni o, ema jeki won gba yin o, eniti o ba Fe ni Oro adaso pelumi number mi na niyi ko yipada 08135072961,lehin re e ma ni Oro pelu enikeni nibi o mi ni idaun si eniti won ba lu ni jibiti o, mose ikilo oemi ni tiyin Baba Ayokomi1010,oludasile Ogun Awon baba wa.
Re: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(m): 10:27am On Feb 22, 2023
Lati December 4 2015,ti Moti da Yara asiri Ogun Awon baba wa, sile mi bere owo lowo Omo egbe Yi kankan ri o, mo Pataki oruko pupo, afi eniti o ba salaye Oro aiyere funmi ni Iwon igbati o pemi ni ma so igbese toye ko gbe fun, toripe otito Inu ni awon baba mi Fi sise lose yewon, emi o wa Fe sawo odale alaso pipon, torina ekiyesi ara o, kiwon ma lo afani oruko ati ife ti awon enia ni si Yara Yi luyin ni jibiti o, number mi niyi 08135072961.By Baba ayokomi1010,oludasile Inu Yara Yi, Ogun Awon baba wa, Koni baje o, Ile ati ona eni kokan Koni baje o, enikeni tobawa Fi oruko tabi afani Inu yarami Yi lu jibiti gbogbo ise Toba se laye, elomi ni o je, kise oun Tori oka ki jere Omo re, eiye kijere Omo re, ase wa. Sugbon gbogbo eniti o ba wa si Inu Yara Yi tofi Ogun otito sile tose awon enia ni afani, ti ko ba Yara Yi he, ti ko lu jibiti, adara lati owuro aiye enibe titi di ojo ale re ni, Koda onitoun ajere ara re atun jere Omo, Tori ogo Omo elewuji enikan soso ni iru enibe pe, igbaa enia ni o ma je ipe re fun owo ola aiku bale Oro asewa .

1 Like

Re: Ogun Awon Bàba Wa by Olu317(m): 1:33pm On Feb 22, 2023
A gbọ́ ye ni o yẹ kí ọ̀rọ̀ jẹ́ fún wa
Nítòri àbọ ọ̀rọ̀ niwọn máa ùn sọ̀ fún ọmọlùábí ;
tí o bá de inu rẹ̀ tan a dí odídì

Ẹ ku imọ̀
Aṣẹ́ Ẹdù kó ni kúrò nínu ayé yin o
Re: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(m): 9:57am On Mar 23, 2023
[color=#000099][/color]OGUN AWURE TI AMA FI RI OWO NA LOJOJUMO LABE BOTIWU KORI.
Ao toju, ewe ila iroko, ewe igi iPin, erupe akitan nla to gba eru dada, ao bu erupe akitan na, ao gun nkan meteta Yi Po mo ose, Ao Fi onronro malu Po, ao kosinu asunwo aso funfun, ao ma bu we ni aro , Oro Yi la o maso ti aba Po ose na lowo, Ohunre:-ipin loni ki e pin ore nla kanmi loni, ilairoko loni ki e ro ore nla ti o lami kanmi loni, pinran pinran ki pin eran ko ma pin ti oronro fun, ti aba gba Ile ti a gba itan, Odo akintan lama ko lo, eko ore nla wa funmi lati oni lo.
Re: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(m): 10:05am On Mar 23, 2023
Ogun ituwo Awebidanu
Ao toju Ori alangba tutu, oun na la Leni adaripon tabi orikoko, ao toju egbo tude, ati ata ijosi 7 fun obinrin, 9 fun okunrin, egbo ibepe Ako, epo obo die, ao gun mo ose ti ale we ni ekan, ao Fi epo pupa para, ao we ose na pelu kankan titun, si Odo tosan, tabi si Inu baluwe wa, ha ara Ade enia by baba ayokomi gangan, oludasile ikanni Yi:-ogun awon baba wa 08135072961
Re: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(m): 11:05am On Mar 23, 2023
Afanni wa fun Iwo tobafe pemi salaye aiyere, tabi arun tabi amodi kan se o, tabi Iwo ti onleri awon ise ti a Fi sile se funrare tofe Kaba e se, Ka Fi ranse si e, kibaje ni Nigeria tabi ni okeokun, number baba Ayokomi niyi timoje Alase ati oludasile Ogun Awon baba wa,
08135072961,oun na ni Whatsapp mi, ti o bati setan fun oun ti o Fe kamojuto ma pemi o, Kisi aiye lati Mafi akoko sofo funmi o
Re: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(m): 11:07am On Mar 23, 2023
Ogun iwosan Ile gbigbona.
Stare odidi kan, otanu iroko, orogbo gbigbe, ewe ahara gbigbe, ao lowo Po, ale dasi oyin kama la, tabi kama Fi omi tutu lo
Re: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(m): 11:14am On Mar 23, 2023
Ogun iferan Gbogbo enia ati ibiti ati sise.
Ori ologbo tobani irin kan, eweji, ewe ajeobale, atare odidi kan, ao jopo ao ma Fi epo la, tabi kama Fi fo Eko tutu mu, a sile Pomo ose kamawe.
Re: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(m): 11:20am On Mar 23, 2023
Ogun oko ti o tiku tiko sise mo, tabi ko le mo.
Egbo igi osunsun, egbo idi apata, egbo igi aika, odindi aipon eso eyin, eja ojiji, ijapa, atare odidi kan, eri agbado, ata jije, iyere, ao gun won Po , ao sagbe mimu Eko lalelale.
Re: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(m): 11:24am On Mar 23, 2023
Ogun ajegun fun eniti o lo Ogun ti o ki sise.
Atelewo inaki, ewe ela, oga kan, ase oka, oko atare, ao jopo gbere yipo orun owo mejeji
Re: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(m): 11:36am On Mar 23, 2023
Ogun atosi
Odidi bara egunsi, ao be epo arare danu, ao get si merin, kanun Ako die, isuepaikun, ao se Lori Ina pelu omi didun, ao ma mu gasi kan ni osan, osan, odaju
Re: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(m): 10:13am On Mar 24, 2023
E karo gbogbo Ile, aku ojumo ire loni, oni ni ojo eti, olodunmare amu ajogun buburu eti kuro loju ona aiye gbogbo wa ati eyin ololufemi ni Ori ikanni Yi, moki eyin elesin Islam pe eku ongbe emi yo rehin osun o, bakan na moki eyin Omo lehin Jesu na pe eku irin Ajo Lent ogoji ojo, e pari re layo, e se odun ajinde pelu ayo, moki elesin adayeba, awon alaseku a bawa se o, emi baba ayokomi na ni mokiyin alase ati oludasile Yara Yi :- Ogun Awon baba wa, 08135072961/08075198871.
Re: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(m): 7:22am On Apr 01, 2023
E karo aku ojumo o, aku osun titun loni atuwalara o
Re: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(m): 7:44am On Apr 12, 2023
Naturewonders:
Ejo baba se etu elese merin ni abi eye awo ti won pe ni eye etu.eseun pupo
eiye etu ti ape ni awo

1 Like

Re: Ogun Awon Bàba Wa by Rowj: 12:39pm On Sep 04, 2023
08101646045atwp:
OSOLE=Ti o ma n mun EYAN Mon AWON nlanla nileyi ati okere.(OMO-YAHOO LELO KOSI LABURU)
Eiye kannakanna tutu kan,ao fi biscuit okin si labiya otun, ao fi Odidi atare kan si labiya OSI,Ao wa ka iye re mejeji Mon Lara ki awon nkan wonyi maba bole.....ao wa ko eyin ororo meta tele ape tuntun, ao wa GBE eiye kannakanna yen le monle.....ao wa ko ewe ekuya tutu pelu sawerepepe tutu die bo monle....odi jijo.......ao lo kuna Dada,ao wa ma fi 1000naira tuntun kan ko ebu yen sinu oti ST-REMMY....Ao wa GBE si igun yara wa,ao fi 1000naira yen si legbe.
Ao wa sope:---------Owo timofi dao loko owo re ooo,kio lo ma bami WO olowo nlanla, olooro,okunrin, obinrin tiowa fun emi l omo l ni owo nlanla wasi odo mi.ADURA....
Ao ma mun diedie laro laro.
N/B******

Anfani situn wa fun eyin aworo sasa toje AWO, bii WOLI, ALFA, ati ISESE todarare loju, lati darapo Mon egbe awon ojogbon ti ati ngbe awon ise alagbara jade, ti ape orukore ni MAJEMU LAILAI ON WSP!
ele fi orukoyin sile si ori :- https:///6rRqiAC3Y2bHcFdinedWUS :- bere lati Omo ogbon odun losoke. 30 years above!
Jowo mafi number re si abe comment'o
Whala'oni payin'o
Add links yen si odo'e
Kede mura sile fun idahun si awon ibere wa Ni ekun rere.
Ajuwase o
mose tan lati dara po mo yin, eseun baba

(1) (2) (3) ... (6) (7) (8) (9) (Reply)

Meet The Most Beautiful People On Earth- The Fulanis / Post Pictures Of Traditional Weddings. / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here!

Viewing this topic: 1 guest(s)

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 79
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.