Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / NewStats: 3,194,323 members, 7,954,298 topics. Date: Friday, 20 September 2024 at 04:15 PM |
Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / Ogun Awon Bàba Wa (329952 Views)
Asiri Aiye Siwa Lowo Awon Agba Woli / Asiri Ijinle Awon Woli Lailai / Asiri Ogun Awon Baba Wa (2) (3) (4)
(1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (Reply) (Go Down)
Re: Ogun Awon Bàba Wa by ALIUDAVID: 10:43am On Dec 29, 2015 |
Ago onile
Baba wa ayomikun ati eyin agbagba lori itakun yi, ejo ti e ba ni atupa
aye(lantern) ejo efun wa, aye ko ni pa atupa
wa ase... Iba eyin to laye iba
agbagba.. 1 Like 1 Share |
Re: Ogun Awon Bàba Wa by Naturewonders: 10:58am On Dec 29, 2015 |
ayokomi1010:Ejo baba se etu elese merin ni abi eye awo ti won pe ni eye etu.eseun pupo 3 Likes |
Re: Ogun Awon Bàba Wa by Snowealth: 2:10pm On Dec 29, 2015 |
ayokomi1010:E ku ise takuntakun Baba, oluwa a ma ran yin lowo. E jowo, onmo yii, se ti onmo oju orun ni tabi ti iriran ti eniyan fi n mo ohun to ti sele ri, ati ohun to tun nbo wa sele lola? E seun , modupe, odun a ba wa layo. 2 Likes |
Re: Ogun Awon Bàba Wa by pappykay0428(m): 2:27pm On Dec 29, 2015 |
ayokomi1010:E jowo se ajegun mi ttunwa leyin eleyi ti o si sise daada, 1 Like |
Re: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(m): 4:58am On Dec 31, 2015 |
ori eye Awo ni ti a tun peni etu 1 Like |
Re: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(m): 4:59am On Dec 31, 2015 |
beni ajegun Miran wa |
Re: Ogun Awon Bàba Wa by ALIUDAVID: 7:56am On Dec 31, 2015 |
Baba wa ayomikun ati eyin
agbagba lori itakun yi, ejo ti e ba ni
atupa aye(lantern) ejo efun wa, aye
ko ni pa atupa wa ase... Iba eyin to
laye iba agbagba.. |
Re: Ogun Awon Bàba Wa by Ousmaf(m): 9:24am On Dec 31, 2015 |
Agoo nile, ejoo efun wa ni Ogun ti eni to sese pari eko re to nwa ise yio fi ri ise to lalubarika, eseun adua wa a man gba pelu ase Edumare. |
Re: Ogun Awon Bàba Wa by Nobody: 3:32pm On Jan 02, 2016 |
ayokomi1010:MO NILO IRANLOWO YIN O E jowo, se oogun yi le sise fun lotto jije? Ati wi pe onmo wo le tun mo ti eroja ko ju nnkan meji tabi meta lo? E o ni subu daanu o. 1 Like |
Re: Ogun Awon Bàba Wa by Makapounse(m): 7:19am On Jan 03, 2016 |
ayokomi1010:se ibi ipade di ohun,abi ibi ase ase ase ni iwure yi ti pari ? |
Re: Ogun Awon Bàba Wa by Makapounse(m): 7:25am On Jan 03, 2016 |
ayokomi1010:se o le sise fun baba ijebu lotto |
Re: Ogun Awon Bàba Wa by Naturewonders: 6:32am On Jan 04, 2016 |
[quote author=ayokomi1010 post=41504908]ori eye Awo ni ti a tun peni etu[/quote.)Eseun pupo baba.Aku odun yi,emi wa ase pupo re lase eledumare.Yio ma ju yin se |
Re: Ogun Awon Bàba Wa by orunmila76(m): 10:07am On Jan 04, 2016 |
Oogun Eyonu to daju Eyin adiye sise kan, iyo die.aa da iyo yen sinu plate ,waa te Odu iwori meji si,waa fi eyin adiye naa lee Lori, waa gbe sinu orun di 12pm,waa lo gbe kuro ninu orun by 12pm,waa Bo ara e si ihoho ,waa gbadura,waa Bo eyin naa wa fi kan iyo naa,waa je eyin naa lodidi. Waa da iyo naa sinu omi fun wiwe. 4 Likes 1 Share |
Re: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(m): 6:36am On Jan 06, 2016 |
E karo gbogbo ile, A de ku aseku odun,odun a yabo fun wa o,Amin ase edumare, E jo ohun ti o je keri owo mi lori ikanni lati bi ojo meta nipe moni adua kan ti mo mase ni ipari odun si odun titun ohun lo fa,sugbon moti de pada bayi,ati pe se ogberi lo po lori ikanni yi ni tori enikan pere ni mori ti o sese fi Ogun ti e si ori ikanni yi lehin mi,se bi ani kajo yara wa logbon ni,enikeni lo le fi ogun si ori ikanni yi,sati je olododo,olodunmare abawa se o 1 Like 1 Share |
Re: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(m): 6:56am On Jan 06, 2016 |
OGUN EYONU TI A MALO LO SI ODE TAFI GBA IYIN NI BE ao fi epo pupa te ejiogbe si atelewo alafia,ao tun fi omi na te pelu iyo isebe,ao wa pe ohun yi si ao wa la,ao fi owo iyoku sa ori,kama lo sode na ao gba iyin nibe, ohun re:amo roro loruko ti won pe iwo epo,amayegun loruko ti won pe iwo omi,amuludun loruko ti won pe iwo iyo,omi kiti laye o,ejiogbe kiti lawujo ifa,ki emi lagbaja omo lagbaja gba iyin nibi gbogbo loni o. ejiogbe ! ! ! ! ! ! ! ! ogun yi dara gan ni o asegbayin la o ma se o ni ojojumo aye wa ao ni te lase edunmare 2 Likes |
Re: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(m): 7:00am On Jan 06, 2016 |
OGUN EYONU FUN KI WON MA FERAN WA ao toju ori ti afise obe,ao wa pa eje ako alangba kan le lori,ao po papo,ao ma fira ori idodo wa,o daju 4 Likes |
Re: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(m): 7:34am On Jan 08, 2016 |
OGUN FUN OBINRIN TI OKO RE KORIRA ao toju eyele kan ao pa eje re sinu Oyin ao ropo ki Obinrin mafi pa oju ara re ti won bafe Joni ajoseopo pelu oko re 3 Likes 1 Share |
Re: Ogun Awon Bàba Wa by ALIUDAVID: 9:56pm On Jan 11, 2016 |
EYONU AWON AGBA ATI APAMOWO OWO.. Ikoide meta, Alanbere meta, Odidin atare meta, Ao jo won po, ao fi sin gbere yii orun owo wa mejeeji, ao po eyi ti o ku mo ose dudu ao ma fi we... OGUN ATUDE TODAJU... Ewe tude, Egbo tude, Odindin atare, Ao jo po, ao lo kuna dada ao ma fi epo pupa lo. Iba eyin agbagba iba eyin to laye.. 3 Likes |
Re: Ogun Awon Bàba Wa by ADEWALE7777: 12:29am On Jan 12, 2016 |
Eku ise takuntakun lori ikanni yii oo...eledua a tunbo ma fun yin se e jowo e fi ogun oko lile si ori ikani yii fun wa...e jowo e ran mi lowo baba |
Re: Ogun Awon Bàba Wa by ALIUDAVID: 8:40am On Jan 12, 2016 |
ayokomi1010:'.. baba se osole yii ko le pawa lara tabi omo wa tabi ebi wa, se ko de tuni ewo... ese ise se agbewa. igba eyin agbagba. 2 Likes |
Re: Ogun Awon Bàba Wa by hibee4uall(m): 12:35am On Jan 15, 2016 |
ayokomi1010: Iba agba o, baba ewe a maa je oo edakun se ao se eyin yen ni tabi ao fi din ebu yen. Edakun e fun wa ni atude to daju. 1 Like |
Re: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(m): 4:04pm On Jan 18, 2016 |
IYONU ASINA EBE AWON AGBA ATUDE Ao toju abo adiie olopipi,totobi ,ao wa wa opolopo imi gbigbe,ao gun ninu ile ni ihoho,lai ni si ohunkankan Lara wa,ao ta epo pupa yipo Odo ti a fi gun,ao si ma ta epo pupa diedie si inu re bi ase gun,titi ao fi gun kunna dada,ao wa po mo opolopo ose,ako sinu ikoko tuntun,ao mawe ni ago mejila si ago kan oru,kankan titun kokan ni ojo kokan,o daju. 2 Likes |
Re: Ogun Awon Bàba Wa by Baba2015: 7:14pm On Jan 18, 2016 |
esun baba ooo bawo ni ase leri afan awon iwe yin ni offa kwara state |
Re: Ogun Awon Bàba Wa by hibee4uall(m): 8:04am On Jan 20, 2016 |
ayokomi1010: awon to laye a maa fun yin se baba. Edakun ti eniyan ba nfi oju ko jankariwo kini eniyan lese si 1 Like 1 Share |
Re: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(m): 6:43pm On Jan 27, 2016 |
OSOLE OWO Okan maalu ti ko wo omi,omudun ewe akoko 101,pati omonigedegede,epo jebo,ao lo awon ewe yi,ao ge okan maalu yan si 16,ao se pelu epo iyo,ati ata ijosi,ti o ba tutu,ao da sinu Awo funfun,ao wo aso to dara,ao joko si aye to dara,ao pe Ohun re si,ao wa je obe na, Ohunre:- igbe nla ni eran nla ke,e ma GBE owo nla wa fun mi,enikan kiridi omonigedegede o,ki e wa Fi owo nla bemi nise loni. ao ma je obe na diedie fun ojo merin tabi marun,osise gan ni o 2 Likes |
Re: Ogun Awon Bàba Wa by ojukoro: 8:39pm On Jan 27, 2016 |
Ogun Isoye.Ewe oniyemiye,eye awoko,iwe newspaper ti ko ni aworan pupo, Igbo die, ao jo po, ao ma bu diedie si oyin igan.lila ni idaji.o da gaaaaaaa 2 Likes 1 Share |
Re: Ogun Awon Bàba Wa by Sobandemojisola: 1:04pm On Jan 30, 2016 |
E |
Re: Ogun Awon Bàba Wa by ALIUDAVID: 10:05pm On Feb 01, 2016 |
Ekale gbogbo ile ejo eni ti o ba ni ogun arobi todaju ko ju sita fun afani gbogbo wa... Iba agbagba iba eyin to laye.. |
Re: Ogun Awon Bàba Wa by admolfemx(m): 8:44am On Feb 14, 2016 |
ayokomi1010:Baba kie pe funwa ho, akoko iberemi niwipe ki ara alaisan na batiya tan se alegba orukana kuro lowore,elekeji adiye ohun se aleje abi ama junu ni, iberemi keta nipe e jo baba iru ogun woni alelo fun inurirun,tabi ki inu makanyan tabi ki inu eniyan ma gbona fun okunrin,e se pupo sir. 1 Like |
Re: Ogun Awon Bàba Wa by marv006: 1:26am On Feb 21, 2016 |
ayokomi1010: Iba Eyin agba o. Se ao fi aso funfun ti a ko ose ko si oke ni, abi a le fi si ibi to ba wuwa. |
Re: Ogun Awon Bàba Wa by 08101646045atwp(m): 2:20pm On Feb 24, 2016 |
ago'onile'o, fun eyin ti enbere ibeere nipa osu, tabi ti nta nso'oye, opolopo ntaso koseyin akose jaye, dida ara eni mo, iwadi nipa eto igbe aye wa, boba wa laye bi okoba da arare mo inira amawa ni igba kokan, tojepe bi oba se oogun gan koni sise, sugbon aje, oso, emere lama ndi lelori, bi akose jaye ba ndani laamun bi eyi tojepe eyan si aye wa ni, tori bore waju pabo ni, bore yin pabo ni, atotun atosi bi alai monse ni bi oro bari bai, owo Ori lati nbeere, tori ori eni lawure eni, ogun loni ojo iponju kafola fori tolojo gbogbo. fun iwo ti obafe lati wo akose jaye re onilati fi ojo ibi re ranse. ajuwase'o 1 Like |
(1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (Reply)
Meet The Most Beautiful People On Earth- The Fulanis / Post Pictures Of Traditional Weddings. / Modern Traditional Attire Of Nigeria
(Go Up)
Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 60 |