Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,151,098 members, 7,811,087 topics. Date: Saturday, 27 April 2024 at 11:04 PM

Ogun Awon Bàba Wa - Culture (8) - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / Ogun Awon Bàba Wa (326068 Views)

Asiri Aiye Siwa Lowo Awon Agba Woli / Asiri Ijinle Awon Woli Lailai / Asiri Ogun Awon Baba Wa (2) (3) (4)

(1) (2) (3) ... (5) (6) (7) (8) (9) (Reply) (Go Down)

Re: Ogun Awon Bàba Wa by Goldess: 12:23am On Feb 09, 2019
Moki gbogbo ile ooo, ewe aje ooo, ejoo no nilo Ogun ti awon omo yahoo le fi gba owo kia kia lowo oyinbo

1 Like 1 Share

Re: Ogun Awon Bàba Wa by jbblues24(m): 9:11pm On Jun 01, 2019
I want to learn this kind of texture! Teach me. embarassed
Re: Ogun Awon Bàba Wa by bolaji11121(m): 4:35pm On Jun 14, 2019
KINI WON PE NI (ASE OKA TABI ASE OKETE)
Re: Ogun Awon Bàba Wa by adigun98(m): 10:22pm On Jul 07, 2019
Iba eyin agbagba,Ejowo baba,moti lo oogun lorisisi tio si sise,eyi kejima ronu boya asiri siwa ni ile oodua abi kosimo,ise Yahoo nimon she Amon gbogbo nkan o lo botiye.....edakun eshanumi baba
Aboru aboye
Re: Ogun Awon Bàba Wa by adigun98(m): 1:35pm On Jul 11, 2019
ayokomi1010:
alafia fun Gbogbo omo odudua,e Ku a mojubami,a de Ku orugbe emi a laja o,eledunmare OBA abanise abawa se tiwa o Ase
Baba Ejowo mo nilo iranlowo yin,mo ti she ogun lorisirisi sugbon mio ri iyato, eyin mumi ma ronu gan lopo igba motun manro boya kosi ogun mo Nile oodua,Yahoo ni Mon she sire
Aboru aboye
Re: Ogun Awon Bàba Wa by Yolmite(m): 6:34pm On Oct 20, 2019
Baba àwọn alale aje o máa ju yin se.
Ejowo baba oogun Kokoro inu-eje t'odaju ni mofe sir.
Re: Ogun Awon Bàba Wa by dplanner: 8:33pm On Oct 25, 2019
E kale eleyi ni EBE ASINA AWON AGBA TO DAJU
OPOLO GBIGBE META , ODINDI ATARE META , A O KO SINU IKOKO , A O WA PA EPO OBO PEPE LE LORI , A O JO , A O LO KUNA , A O MA FI EPO PUPA LO SUN LALE . IWO TO BA SE AYEWO AKOSEJAYE ATI IRAWO RE ,KAN SI MI LORI 07067796292 TABI KO WHATSAPP ME DIRECT SUGBON OWO NI MO FI N BERE O OOO.
Re: Ogun Awon Bàba Wa by 08101646045atwp(m): 1:45am On Nov 07, 2019
Aku'ijometa ninu ile mimo yio, moki gbogbo eyin atonisona, ninu ile mimo yi, mosi tun nfi akoko yi Dr ayo ti won je oludasile ikanni yi wipe aku'atijo o, akoni sasise'o, Lori wipe awon eniyan nbere orisirisi ti won kosi ri enidawon lohun gege bi won se nfe, gege bia ti nse ni won odun meta seyin, mobe gbogbo ile wipe ki emabinu siwa, kamaparo, WhatsApp group lofa, sugbon ni oruko baba wa oludasile ikanniyi ayokanmi 1010, ohunkohun ti eyin eniyan wa ba nfe mofe kie mabere bai, Lati akoko di ipari odun, gbogbo eyi ti Olorun oba batifi agbara waka nibe niyio yanju patapata. Nitori wipe odaju wipe Olorunni alagbara. Ajuwase'o

2 Likes

Re: Ogun Awon Bàba Wa by kehnton(m): 7:56am On Feb 11, 2020
ff
Re: Ogun Awon Bàba Wa by Manpolo080: 1:48pm On May 08, 2020
Ejowo eku ojo meta o
Ejewo moni ipenija kan ni ,ejowo enikeni tobale ramilowo kojo .
Ogun ti ale lo fi WO arun staphylococcus ti won pe ni arun to maun daa ago ara eyiyan ru, ejowo ewe ama jeo
Re: Ogun Awon Bàba Wa by Nobody: 5:46pm On May 08, 2020
bolaji11121:
KINI WON PE NI (ASE OKA TABI ASE OKETE)

The tail of a Gaboon viper and the tail of an African giant rat
Re: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(m): 6:33pm On May 15, 2020
E Ku irole o gbogbo ile eku ojo meta o,asiku ongbe emiwa a laja o,a de Ku ti cofidi 19,ao ni ba ajakale arun lo o,emi baba ayokomi1010 na ni mopada de o,gbogbo eyin ololufe Ogun awon baba wa,eku amojubami lehin number yi,bi enikeni ba gba Owo lowo re kise emi o,bamisoro labe aso Ki o to da enikeni loun,08075198871/08135072961,alafia arawa konidi fiafia o,gbogbo eyinti etije afani mi ninu ileyi ti e ma pemi ti e ma bere fun oun ti ko yeyin,tabi ti e ma dupe pe oun ti mo fisile sise fun yin,ati eyinti ema send card simi,eyinti e ma bere fun account number mi,timi Ki daun kise ti afojudi o,mo ko iwosi ni,oruko rere o sanju wura oun fadaka lo ni,kosi omo egbeyi ti o lewipe mo gba oun tabi lu oun ni jibiti,tabi mo bere Owo kan lowo oun,koda bi oro ayere ba need kojepe emi ni ma ba e se igbese,aniboseje kito sope ko send Owo o,ti o bade send Owo wa ri isere gba dandan botiwu Ki ilure jinna to,torina ema je Ki enikeni gba yin o,pe number mi kajo soro ni o,alafia fun yin[color=#990000][/color].
Re: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(m): 6:44pm On May 15, 2020
Eniti o bere pe kinije ase oka,or ase okete,iru ejo oka ni je ase oka,iru okete nije ase okete.
By baba Ayokomi
Re: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(m): 2:12am On May 17, 2020
OGUN AGADAGODO ELE
Iye igun,ihe aparo,ori atioro,ao jowon po pelu atare odidi kan,ao di ni owu Dudu ati funfun mo agadagodo,ao loran ni awo obo, omo atare 7,lama fipe,
Ohunre:-ise ni pa igun,osi nipa aparo,ile akogbe nipa atioro,aye obo kidara titi koma so ewon mo idi,jki aburu ati ajalu bayi majalu lagbaja.

OGUN ASEGBE
Ori asa,ori olongbo,awo ekun,odidi atare ao jopo,ao di lowu Dudu ati funfun ao ran ni awo ekun,
OHUN RE:-Imotu imojo imo enini Ki dale,toripe ti gbogbo eye ba ngbimo asa ti won ba foju kan asa imo won atuka,imotu imojo imo enini Ki dale,bi gbogbo eranko ba gbimo eku ti won bafi oju kan ekunn ekun imo won atuka,imotu imojo,imo enini Ki dale, bi gbogbo eku ba gbimo ologbo bi won bafi oju kan olongbo imo won atuka, Ki gbogbo aburu ati ibi ti won di ni tori mi tuka, gbogbo aburu ti nbe lona ko tuka.

ISORI NLA.AIPERI.
ao toju aso funfun opa kan,ao kun egbe kan ni osun,ao kun egbe kan ni aro,ao bu iyo si Lori ao fi igbin le,ti igbin ni bati je iyo yan ti o Ku,ao jopo ao ro sinu sere kan,ao mafi omo atare meje pe,ao gbe sinu ile wa,tabi kaso mo ile,
Ohunre:-ojo ti aso funfun ba foju kan aro ni ise re tan,ojo ti aso funfun ba foju kan osun ni isere baje, ojo ti igbin ba fenu kan iyo,ni yio gbona orun aiperi,gbogbo eniti o ba porimi nibi koma so lorun aiperi,ti a ba ti pe la o ma fi sere yan koja oriwa.

ETO BI ABAFE FE IYAWO LE IYAWO WA TI O TUKA.
Ao toju abela pupa kan,ao ko oruko iyawo ti o wa nile si,ao tan ina si,ao ma sa oruko yi,JAHURAHTAJAH-TUBIH 21× ELI LAH HAOLAH-SEMIRAH3×
ao gbadura Olorun orimolade gbogbo oun ti lagbaja omo lagbaja lo ti o fi tu oro iyawo ti mofe fe ka,Ki o baje lati oni lo.

OSOLE ASINA TIPATIPA.
Ori oka NLA,ao fi tele inu isasun,odidi atare,ata ijosi,ao fi eso werepe bo mole,ao Jo kama fi oti lo,botiwu Ki ona di to yio la.mo
4r[/color][color=#990000]m President
Re: Ogun Awon Bàba Wa by Olaiya126: 1:44pm On May 17, 2020
Baba IFA a n ma je oooo.e jowo mi nilo ofo ti mo le fi gbowo lowo a won oyinbo client
Re: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(m): 6:07pm On May 20, 2020
Alafia fun yin o gbogbo omo egbe Ogun awon baba wa,ayo nitiyin o[sub][/sub]
Re: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(m): 9:19am On May 21, 2020
OSE TUDE ODO TI ONA ENIA BA DOJURU.
Ori aparo 1,odidi atare 1,aoyo gbogbo omoinure,ota inu iroko,egbo tude die,aogun gbogbo repo
mose iwe meje.....lilore
Ori ikunle laotiwe oseyii ,kankan meje laofiwe ose meje na....(Lilo fun eniyan kan)
....tested OK ...
4RM PRESIDENT OGUN AWON BABA WA.BABA AYOKOMI NA NI O.
AKU IMURA ODUN ODUN AYO LA O SE.
Re: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(m): 9:25am On May 21, 2020
E karo o,mope gbogbo eyin omo egbe Ogun awon baba wa, ati eyinti e tele wa ninu ikanni yi ,ejeki ari enia meji meta soro ti o ti Dan ise inu ileyi wo ti o si ba be,abi inu ileyi koni ihulo kankan fun wa,ejeki a so,mofemo awon ti o duro Dede fun inu ile yi,atipe e je afani mi,kini afani tiyin na ti e fe fise kuse koriya fun wa,e se pupo amo riri yio,aisan o ni da enikokan wa gunle o,Ogun aye o ni bori wa,ao lu aluyo o.
Re: Ogun Awon Bàba Wa by IAWAHAB(m): 12:07pm On May 21, 2020
Eku ise takun takun ti nse ,olorun yio man bukun agbara. Oduduwa yio gbewa.
Re: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(m): 12:11pm On May 27, 2020
E Ku ojumo o,aku iyaleta ao ri batise ao ri ona gbegba o,gbogbo omo egbe Ogun awon baba wa.emi Aree na ni mo kiwa o,gbogbo enia ti o je ojogbon ati omo Yoruba ibile ti o fe iranlowo mi si awon ti eledumare ranmisi Ki e bamipade lati wa sinu yara kan ti ma dasile loni fun afani yin Ogun awon baba wa,ni ori whatsapp,eyiti akoko dasile ni odun 2016 Lori whatsapp otikun fun opo enia,awon woli Alfa onisegun enia Dudu ati ti oyinbo nikan lada sile fun ositi kun ao gba enikeni wole sibe yan mo,toripe ati se ipade ojukoju nibe,atigbe kakiri ipinle ni orilede yi,
Sugbon eleyi ti ama dasile Lori whatsapp loni tise 27/05/2020.o mawa fun gbogbo enia ti o fe Ogun ibile awon baba wa, tabi o fe bami soro labe aso lati sise fun o lati Owo mi,
Lati ojoti moti da ikan niyi sile ni Nairaland kosi enikeni toleni mo lu oun ni jibiti,tabi ise ti a fisile ko sise fun oun,mode dupe fun eyin ti e ma send card simi fun data,ati eyin ti e ma bunmi lowo pe Baba ayokomi e gba, ina o ni tan lowo yin o,oju Owo koni pon yin.
Eleyi ni number Group na ti ama dasile loni ni whatsapp wa,Iwo ti o bati fe darapo wa kansimi pe omo egbemi ni e ni Nairaland Lori Ogun awon baba wa, made add whatsapp re sori group na
Re: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(m): 12:13pm On May 27, 2020
Number group na nisyi,ti o bari number Miran yatosi eyi kise baba Ayokomi o,majeki won gba e o
08135072961/08075198871
Re: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(m): 11:41am On May 29, 2020
E karo gbogbo ile o.
Re: Ogun Awon Bàba Wa by sharaff6(m): 10:28pm On May 31, 2020
ayokomi1010:
E karo gbogbo ile o.
ejo mo need ogun akokoro eyin didun to wun gan
Re: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(m): 8:20am On Jun 02, 2020
Ogun akokoro eyin
Ao bu petrol sinu cup kan,ao bu iyo sinure,kafi owu tutu kan si.

Oran ataa e ma run nigba gbogbo yio lo
Re: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(m): 8:21am On Jun 02, 2020
Orin igi ata ni ema run si akokoro yan o,e rira lowo awon elewe omo.
Re: Ogun Awon Bàba Wa by sharaff6(m): 10:16pm On Jun 02, 2020
ayokomi1010:
Orin igi ata ni ema run si akokoro yan o,e rira lowo awon elewe omo.
Thank You sir God Bless You. Ese sir e jo ipari e ko ye mi shee le funmi ni number yin kele shaa laye e funmi
Re: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(m): 9:15am On Jun 21, 2020
Ogun asiri bibo.
Ewe omodun tagiri,ewe ati ododo tannaposo,epo jebo,ewe iyalode,ejeki a lopomo ata ijosin,ejeki a bo igbin kan kayo idoti re danu ka son komo dada kaju sinu isasun lodidi,ejeki ase leponiyo pelu awon eroja yan,ejeki aje,lase edunmare ao ri bibo asiri.

Ogun Awure owo
Ewe iyalode funfun ati pupa,erun Alamo,imi ojo,owo eyo kudi 10,ejeki a gun mo ose ka ju sibikan ninu yarawa laiko sinu ora tabi igba tabi ike,kama we larokutu oda owo koni da oluware.


Ogun nla tiobinrin fi ti ara okunrin la ati eyiti okunrin fi ti ara obinrin la,ati ise igbelu oyinbo fun fayegbami ati asikire wa ni ile fun eniti o bafe,
Kosi ilu ti o lewa ni Nigeria yi ti emi kifi ise ranse si,tiabati jo soro ti o funwa ni address re,ati phone number re,ti o siti sanwo wa,e bere mi tabi ko oro sile ninu gbogbo enia ti o je afani mi ninu ile yi emi oludasile Ogun awon babawa,enikeni o le pemi ni scam,Tori mi lu enikeni ni jibiti,Ade dupe iwon ba ore ti adaniwaye se fun wa,Ade dupe lowo awon tilo isewa boya yala eyiti afi owo arawa se fun won,tabi eyiti a fisile Lori ikanni yi,tio je fun won,ti won de send owo siwa ni idupe ati awon ti o send card simi,koda ni ijeta enikan tun jomi loju ti o fi 20000 si account mi,pe aisan ojo pipe ti awon ti nawo damu si,pe oun ri iwosan latari inu ileyi,Alh na ki olorun bami Lora emi yin ki ola yin ma wa le o,majeki won fi oruko mi lu o ni jibiti o,pemi si 08075198871 08135072961
Baba Ayokomi lomada e loun,kise pa mi tabi awon omose mi,ire o.
Re: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(m): 9:33am On Jun 21, 2020
OGUN IWOSAN AYE
ewe ela,ewe alupayida odidi atare kan, ao jo po ao da sinu omori isaasun ao wa ko oruka irin si,ao wa da epo pupa si ao ro po, ao wa fa Ogun yan si enu akuko adie,ni emeta,ao ma fi oruka ni si lenu ni okokan yio ma gbemi,ti o bawa di OJO keje ao pa adie na,ao lainure ao Ba awon oruka na,ao ko ao ma fun eniti Asian ba nse yio fi bowo re,aisan re yio San ni OJO na ase eledunmare ni,iba eyin agba o aiye mojuba o,mowole mo pa igbunmo o,mofori bale fun gbogbo ajunilo.


Moti fi ise yi sile ninu ile,lojoti o tipe oun ti o tun mumi mu padawa ni pe iseyi ni babawa Alh ti mosope olorun gbe dide Lori aisan ti oti to odun meji,ti won de bunmi ni 20000,toripe eniti a se lore ti kodupe o dabi ki olosa ko eru eni loni,mowa tun da ise yipada wa fun gbogbo omo egbe Ogunawonbabawa pe komaje afani e mafi ojudi ise yio.
Re: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(m): 4:38pm On Jul 06, 2020
E ku ojo meji meta o gbogbo omo egbe Ogunawonbabawa

(1) (2) (3) ... (5) (6) (7) (8) (9) (Reply)

Meet The Most Beautiful People On Earth- The Fulanis / Post Pictures Of Traditional Weddings. / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here!

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 46
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.