Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,162,677 members, 7,851,319 topics. Date: Wednesday, 05 June 2024 at 05:03 PM

Moni 'bere Ti Mo Fe Bawon Gbenugbenu Orileede Yi! - Politics - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Politics / Moni 'bere Ti Mo Fe Bawon Gbenugbenu Orileede Yi! (869 Views)

Mo Abudu Suspected To Be Amaechi's Girlfriend - Lere Olayinka (photos) / Buhari Receives Wang Yi, Foreign Minister Of China (Photos) / See The Prototype Of Niger Delta Money( Spot The Error In D Moni) (2) (3) (4)

(1) (Reply) (Go Down)

Moni 'bere Ti Mo Fe Bawon Gbenugbenu Orileede Yi! by oyinkinola: 6:57am On Mar 12, 2016
Nigba taa ba nigi woroko ti ndana ru, oun aaro kaaro tin dobe nun, ijo wo lao to se be jinna? imado iba se bi elede adaluru, beru bajoba eyaan ibati ku kan, eyin ojelu, tee selu fodun merindinlogun, tee ko tile ta, te tun wa so wipe, lebe o ponmo re!,o ye koju o gba yin ti, nitori ko sori le eede to le goke agba pelu iwa ole oun jeguujera ri, sa'ye si baje ole dajo, niru yin tun fi lenu oro lawujo, oro o dun lenu 'ya ole!
Re: Moni 'bere Ti Mo Fe Bawon Gbenugbenu Orileede Yi! by haffaze777(m): 7:08am On Mar 12, 2016
Omo Yoruba atata,Odua agbe e
Re: Moni 'bere Ti Mo Fe Bawon Gbenugbenu Orileede Yi! by godoluwa(m): 7:34am On Mar 12, 2016
oyinkinola:
Nigba taa ba nigi woroko ti ndana ru, oun aaro kaaro tin dobe nun, ijo wo lao to se be jinna? imado iba se bi elede adaluru, beru bajoba eyaan ibati ku kan, eyin ojelu, tee selu fodun merindinlogun, tee ko tile ta, te tun wa so wipe, lebe o ponmo re!,o ye koju o gba yin ti, nitori ko sori le eede to le goke agba pelu iwa ole oun jeguujera ri, sa'ye si baje ole dajo, niru yin tun fi lenu oro lawujo, oro o dun lenu 'ya ole!
Jowo daruko awon igi woroko ohun. emi ko ri eko kankan ninu oro apileko re yii tori gbogbo nkan ti o ko ni afojusun rara. ojo abameta l'oni, emi kii lo si ibi ise. mo ri aaye lati la o l'oye ati lati si o l'oju inu.
Re: Moni 'bere Ti Mo Fe Bawon Gbenugbenu Orileede Yi! by oyinkinola: 7:37am On Mar 12, 2016
haffaze777:
Omo Yoruba atata,Odua agbe e
eseun, ole o raye lawujo omoluabi, sugbon lode oni, oro ori bee mo, to ba se ilu tododo nba nsise, nje ko ye ka panupo bole wi kole lee mo paeda loun se,
Re: Moni 'bere Ti Mo Fe Bawon Gbenugbenu Orileede Yi! by DaBullIT(m): 8:12am On Mar 12, 2016
Awon olorii bu alai'lojuti

Won tun lenu
Re: Moni 'bere Ti Mo Fe Bawon Gbenugbenu Orileede Yi! by oyinkinola: 8:25am On Mar 12, 2016
godoluwa:
Jowo daruko awon igi woroko ohun. emi ko ri eko kankan ninu oro apileko re yii tori gbogbo nkan ti o ko ni afojusun rara. ojo abameta l'oni, emi kii lo si ibi ise. mo ri aaye lati la o l'oye ati lati si o l'oju inu.
...awo ole oloselu to fodun merininlogun kowo orile ede yi je ni igi woroko to danaru, eyin te nsegbe fun won nlaaro kaaro tin dobe nun!
Re: Moni 'bere Ti Mo Fe Bawon Gbenugbenu Orileede Yi! by oyinkinola: 8:29am On Mar 12, 2016
DaBullIT:
Awon olorii bu alai'lojuti

Won tun lenu

...beeni aye lo ba je lole ndajo, nile china won o ti yinbo paru won danu!
Re: Moni 'bere Ti Mo Fe Bawon Gbenugbenu Orileede Yi! by fyneguy: 8:31am On Mar 12, 2016
Hmmm Akiika. Oro sunukun; oju sunukun laafi nwo.

Aisolongini nile fun odun merindinlogun, lo difa fun ile to di ile ekute. Amo, ta ba wo didun akan, a ora de egun. E je a gbe ti segbe kan, ka sodi afiseyin tegun fiso, ka tesiwaju.

Oluwa yo ran wa lowo o.
Re: Moni 'bere Ti Mo Fe Bawon Gbenugbenu Orileede Yi! by oyinkinola: 9:29am On Mar 12, 2016
fyneguy:
Hmmm Akiika. Oro sunukun; oju sunukun laafi nwo.

Aisolongini nile fun odun merindinlogun, lo difa fun ile to di ile ekute. Amo, ta ba wo didun akan, a ora de egun. E je a gbe ti segbe kan, ka sodi afiseyin tegun fiso, ka tesiwaju.

Oluwa yo ran wa lowo o.
...oseun omoluabi, taabada tajaran fajaran ko ni sinmi aran jije, taa ba bole wi, ko ni mole pae da loun se! je a pole lole ko ye ise iibi ni sise, ko baa si mo niwo leyin nitori ojoola awon omo wa!

(1) (Reply)

Breaking News: Buhari Group In Crisis As Coordinator Resigns / Ben Bruce Says INEC Is Now Inconclusive Electoral Commission (snapshot) / Photos: See How Corp Members Slept After The Violent Re-run Election In Rivers

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 15
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.