Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,153,507 members, 7,819,837 topics. Date: Tuesday, 07 May 2024 at 02:09 AM

If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! - Culture (94) - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! (376046 Views)

If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! / Do You Speak Yoruba? (2) (3) (4)

(1) (2) (3) ... (91) (92) (93) (94) (95) (96) (97) ... (167) (Go Down)

Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mishoo(m): 2:47pm On Aug 06, 2007
Dis Guy:

e kasan ni abule yi o, shey ehun gbadun summer yi?
Ekasan oo. A se eyin na ma n so Ede wa. E kaabo sinu abule yi !!

tafari:

mishoo, bawo ni o? se alaafia ni? ode o daa bi?
Tafari okunrin meta !!
Se oko o je epo !!
alafia ki ile wa bi??
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by tafari(m): 2:56pm On Aug 06, 2007
mishoo, ise, omo, iyawo nko?
e de ku miliki ilu wa yi.
nje baale wa ni aafin bi?
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by richylaw(m): 2:58pm On Aug 06, 2007
Mo tun ki gbogbo wa ku ikale leekan si o. Mo ki awon eekan oro bi Alagba Tafari, Disguy, Mishoo ati Nana o. E ku ko le da.
Mishoo, inu mi dun wipe o tu ile kan Ilu Oyotunji o.  I got to know about  Oyotunji about four years ago. Mo si tun ti ni ohun kan tabi omiran se pelu awon abenugo ti n je ki eye ke bi eye ni Oyotunji. Boya ti awon omo yanmirin ode oni ba tun n ri eleyi won yio le pe aro ati odofin inu won wa ile , lati ri wipe ede ati asa ti o lami laaka julo lori ile agbaye (Yoruba!) ko paarun . Alagba Mishoo , e ku afiyesi . E si tun ku afokantan.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by richylaw(m): 3:00pm On Aug 06, 2007
Alagba Tafari , mo wa laafin ninu ola nla mi o. Koko la ra ota n le.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by tafari(m): 3:02pm On Aug 06, 2007
baale, oro wa o. ma wa ri yin ni aafin ni irole
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mishoo(m): 3:11pm On Aug 06, 2007
tafari:

baale, oro wa o. ma wa ri yin ni aafin ni irole
Tafari, ko si ogba ti oro ki i si ni??
Se oo ti jawo loro oye yi na??
Amon a i san wo lo ile baale ooo.
Se o mo bee??
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by richylaw(m): 3:15pm On Aug 06, 2007
mishoo:

Tafari, ko si ogba ti oro ki i si ni??
Se oo ti jawo loro oye yi na??
Amon a i san wo lo ile baale ooo.
Se o mo bee??


grin grin grin grin grin grin grin

Ile gbogbo ilu ni afin oba je, yara awon olori nikan l'enikan o gbodo be ju wo a fi baba funrare grin. N o mo reti awon alejo mi bo ba d'ojoro
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by desorlah(f): 3:48pm On Aug 06, 2007
Hello! grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by richylaw(m): 4:00pm On Aug 06, 2007
HELLO GAN NA NI . Desorlah , ka a si bi? o pe die ka to ri yin loni
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mishoo(m): 4:02pm On Aug 06, 2007
richylaw:



grin grin grin grin grin grin grin

Ile gbogbo ilu ni afin oba je, yara awon olori nikan l'enikan o gbodo be ju wo a fi baba funrare grin. N o mo reti awon alejo mi bo ba d'ojoro

O ti dara. Mo gbo oo!! Sugbon ti eniyan ba poju laafin, bawo ni e o se mo eni ti oun yoju wo iyara awon olori

desorlah link=topic=48547.msg1362052#msg1362052 date=1186411712:

Hello! grin
Desorlah aya oloye, se alafia ni owa?? Ipade (date) yin nko?? Se o lo daradara.
E ku ikale oo!
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by richylaw(m): 4:30pm On Aug 06, 2007
Mishoo , se iwo o mo pe enikan ki gbe ina wo oju egun ni, enikan ki gbena woju ebora, a i je be ebora a bo laso. Iwo fi yen sile, je ki enikan wa danwo na. Onitohun o dan tan ni. he he he heh ehe he!
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by nana(f): 4:34pm On Aug 06, 2007
hm hm
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by richylaw(m): 4:44pm On Aug 06, 2007
nana:

hm hm

beeni mo so!
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mishoo(m): 5:13pm On Aug 06, 2007
nana:

hm hm
Nana, eewo ni hmm??
Se oun mi kanle ni tabi oro ohun o ye oo
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by omoge(f): 1:57am On Aug 07, 2007
@ Ob'Wunmi
lol i dey kampe paddy mi cheesy you are hilarious grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mishoo(m): 9:02am On Aug 07, 2007
obowunmi:

e ku dede asiko yi o,
e ku gbengbele,
e ku kole de ti gbogbo wa nba kiri o,
ko ni baje o,
ko baje lori awon asiwaju,
ko baje lori awon agba,
ko ni baje lori wa o,
omo araye o ni gbe sori wa o,
esu o ni gbe sori wa,
awa na o si ni fowo ara wa gbe sori ara wa o,
lase edumare.



pa segoye,se e gbadun eyi ti mo ko yi,
well emi o like e rara,nitoripe iru awon oro bayi o mo emi lara,
kosi iyo,ata,epo,iru,maggi,tomapep,ati awon eroja mi ninu re,infact ko dun rara,
its damn 2 boring,
anyway toba je be se fe niye,
ma fun yin,be se fe,lati le mu inu yin dun,
so,
praise the rod lord, grin grin
halleluya.


Talo bami ri @omoge?
e bami so fun pe ayun re yun mi o,
ara mi wa lona,
kowa fi mi lokan bale.



Ti omo eni ba se daada, oyo ka wi !!
Inu mi dun fun ogbeni ***Wunmi pupo pupo.
Ti a ba ma tie fi epo, ata ati alubosa si i
ki i se igbagbogbo, beeni kiise ni pipoju
ki o ma baa ja a.

Wunmi, a du e se ooo
Wa laale, oo ni lalele
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by satan: 1:50pm On Aug 07, 2007
Hello grin

Eyin ole lasan lasan
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by ayanjide(m): 3:01pm On Aug 07, 2007
@

DEBOSKY

o see pupo fun bi o ti pe akiyesii baale abule yi si oro mi. O dun mi pe o pe die ti mo ti yoju si aafin. Sugbon morii pe lai si n le mi aafin si n dun. Edumare o nii ba ise owoo wa je o. ASE

Sugbon nisinyi maa se akitiyan lati fara moo yin daada, ki a le baa fowowewo ni abule yi.


@
RICHYLAW
ooto ni, un o faramo yin daada nitori abule yi dun. A o nii p'edin, a o si nii te. E see gan ti e ko je ki oruko mi o pare labule yi
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by minute(f): 5:02pm On Aug 07, 2007
LOL.

LOVE MY NAIJA BROS AND SIS HERE.

LOL-----erin ni yanturu lol
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by debosky(m): 6:46pm On Aug 07, 2007
obowunmi oniyeye gidi ni o je o grin grin

eforious ati ilarious nikan ni? oma to ri gbegiricious ni si yin grin grin

alagba ayanjide, ekaabo si aafin o, adupe pe ko si jamba lona nigba ti e rin irin ajo wa

ni tooto mo mu oro yin lo ba baale wa ni aafin, won si wipe ti e ba bawa fowowewo bi o se ye ninu ilu wa yii, laipe laijina ipo lantulantu ninu aafin ni wo ma fi lo yin. inu mi dun pupo pe e ti pinnu lati fara mo wa patapata ni ilu wa yii, owo yin a ma roke o. Amin Ase

Baale wa ki ade pe lori ki bata pe le se o. osi ti to ojomelo kan ti mo ti ba oloye segeoye soro, abi Baale ti ran ni se lo si ilu miran gege bii oju ati eti aafin ni?
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by debosky(m): 7:07pm On Aug 07, 2007
amin jare 'wunmi

bawo ni awon iyawo e?

se won o je kio re ara sa?

nitori mo mo pe awon omo yen le pa eyan o! grin grin grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mishoo(m): 8:02pm On Aug 07, 2007
obowunmi:

kai,
tu danu,ma sobe mo,
o mo eni to nba soro ni?
abeg i,m a born again xtain o,
and for your info,
i,m also a deacon in my church,
so jo ma ma bami so iru awon oro to doti bayi o,
Jesus is comn soon,
so try lati fi aye e fun Jesu oluwa ati olugbala wa,
ki oluwa wa pelu re,
kunle ko je ka gbadura.

Oro iyawo ki i se nkan to buru rara oo
se apon ni eyin fe je dojo ale ni??
Bachelor for Life

Etete lo wa iyawo oo !!
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by minute(f): 8:05pm On Aug 07, 2007
LOL grin grin grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by debosky(m): 8:08pm On Aug 07, 2007
abi oju mi ntan mi ni??
obowunmi ti di deacon shocked shocked
iru asiko ti mo ma feran ki pastor haywhy yoju ni yii.
'wunmi jowo juwe adugbo ti soosi yii wa kinle wa ri alagba ijo yin.
iru oro ti o gba enu yin jade tele ko to si eni tio ba je decon ijo o
ko si laburu nipa oro iyawo o, sugbon ema je ki o ju eyo kan lo
afi ti ijo yin ba je ti catoliki ti awon priest o gbodo fe iyawo
oda o, mo ti kunle, deacon obowunmi e gbadura fun wa cheesy

egbon mi mishoo, se eyin maa nba eyan wa iyawo ni?
ti e ba mo iru ise yen se, ejowo e lo ba obowunmi wa iyawo o
emi o nilo iyawo miran sa, emi ti fe omidan nana tipe tipe grin grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mishoo(m): 8:12pm On Aug 07, 2007
Ti wunmi ba fe fe ju eyo kan lo, ko si laburu nibe. Sebi "me" lolorun wi !!
Ko si ewu ni egberun eko, afi aidun obe.
Se o sa ti lowo ati toju won
ko mo se pe awon ni won o ma toju e??
ti o ba si ti njeun daradara
a ma yo ikun si ni
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by omoge(f): 9:04pm On Aug 07, 2007
em em em em eh, ni bi wo ni mo stop sha now, oh mo miss road ni sorry chaps and ladies grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by debosky(m): 9:20pm On Aug 07, 2007
obowunmi:

mi o ni daruko ile ijosin wa fun yin,
idi ni wipe oru oganjoa ni a ma nse esin tiwa
ni ihoho omoluabi si ni a ma nse esin ohun,
ara orin ti a si ma nko to de je favourite song mi ni church wa ni,
e pana,e pana o,kolu kaluku ko wa mu ti e,
e pana, e pana o,kolu kaluku ko wa mu ti e,
praise the[b] rod[/b] lord,
halleluya,
iyin,okoooooooooooo ogooooooo

abalajo, oye ki mo ti mo pe ile ijosin onisekuse nikan ni o le fun iru omo obowunmi ni oye deacon grin grin
ki Olugbala ko yin yo ninu ese yin o, oo ni se Amin ni?
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by ayanjide(m): 6:55am On Aug 08, 2007
debosky e see mo dupe gan ni o. E de kuu ilaloye ti e n fun ogbeni debosky afi ki Oluwa ko ko won yoninu oro E PA NA, E PA NA ti won ko raa won si yii.


OBOWUNMI. e jowo kinni itumo oruko yin, se OBO bii VIRGI, abi OBO bii MONKEY nitori ko ye mi ni mo se beere o. E ma fi se 'binu rara o. eni beere kii sina. Nigba ti mo wa aso iboraa mi9 ti n korii mo pe nombaa yin 0900007777 wonni ko si lawujo awon nomba lorii gegele isoro alagbekaa mi. Se kii se p e e ko mo nomba yin lori? E MAA GBADUN LABULE YI O
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mishoo(m): 9:53am On Aug 08, 2007
E kaaro ninu abule yi oo!!
Abi ko si enikankan ninu ile ni??

Singing

Talo ninu ogba na
omo kekere kan ni
se ki n wa wo?
mo wa wo
iwo lo pa
iwo lo - - - - - - - - - -
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by tafari(m): 12:30pm On Aug 08, 2007
alagba mishoo, e mi wa ninu ogba o.
se oko o je epo o.
awon iyawo ati omo nko?
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by nana(f): 12:43pm On Aug 08, 2007
E kasan o
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mishoo(m): 12:52pm On Aug 08, 2007
tafari:

alagba mishoo, e mi wa ninu ogba o.
se oko o je epo o.
awon iyawo ati omo nko?

Tafari, okunrin meta !! Gbogbo won ni won wa daada oo!!
Adupe, Enu n gbe yangan !!
E si ku kokari !!
E ku ofinkin yi na!!


nana:

E kasan o
E kaabo oo !!
Surprised you aint Helloing us today
Alafia ki ile wa bi??

(1) (2) (3) ... (91) (92) (93) (94) (95) (96) (97) ... (167)

Pictures Of Nigeria Traditional Attire / Igbo Names & Their Meanings / Igbo Kwenu ! Kwenu Kwezo Nu ! Join Us If You Proud To Be An Igbo Guy/lady

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 62
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.