Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,151,778 members, 7,813,573 topics. Date: Tuesday, 30 April 2024 at 02:15 PM

.. - Culture (93) - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / .. (1828160 Views)

"We The Ewe People Of Ghana Are The Same As Yoruba"- Yewe2011.ewe Guy From Ghana / How Do U Spell (weed) In Yoruba, Is It Igbo? Or Egbo? / Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re (2) (3) (4)

(1) (2) (3) ... (90) (91) (92) (93) (94) (95) (96) ... (99) (Reply) (Go Down)

Re: .. by mercysamuelson(m): 11:57pm On Jul 12, 2017
Omo owo wo ni a ma ki bo ki si ni ero re?

sammyjay76:
Iba agba o, a ma juse o. Eku ise lada, edumare a ma ran yin se o. E dakun ape obinrin to lo ti ko si ni odo eyan mo to daju ejowo fi sita fun mi. Eseun fun awon dahun wonyi ooooo.
Re: .. by Divinedew: 4:12pm On Jul 14, 2017
Ago onile o, e jowo kini Yoruba un pe ni OJU WOWO. E se pupo.
Re: .. by Alibaba1981: 10:08am On Jul 16, 2017
moki gbogbo eyi baba alubarika pe aku ojumo ejo mo need ( Ogun asiri bibo fun inawo)
Re: .. by skysky05: 5:29pm On Jul 16, 2017
Ogbó ató oo. Ewe aje, egbo afò fun gbogbo jawe jawe rere ooo. E jowo mo nilo ogun ti eyan fi mu oti sugbon ti oti koni pa rara
Re: .. by Nobody: 6:15am On Jul 20, 2017
hello, this thread is for lovers of nature when it comes to health and other areas of our lives. This thread is also strictly for the Yorubas and those who can read and understand as the language here is going to be pure Yoruba and no translation will be allowed. Reason is that we are going to be revealing some Yoruba secret knowledge of the application of leaves and roots and we intend to preserve and guard these wisdom of our ancestors.

Please do not ask further question regarding my reason to keep this as a Yoruba affairs, it's my choice...but if you refused to respect this, I shall only dignify you with silence.

Aye wa fun o lati beere fun iru Oogun to ba fe sugbon ao ma ko awon orisirisi Oogun sita. Awon Oogun fun itoju aisan, akoya, ati awon Oogun fun isora/isori, awure, aworo, ati beebe lo. Sugbon kii se gbogbo Oogun ni a le fi sita lofe, awon eyi to ba ni agbara gan ni ao so wipe ki e kan siwa lori apo ifiwe ranse wa binaryteck@gmail.com fun ekun rere alaye.

E le dara po mo wa lori whatsapp pelu ero ibanisoro yi...08148398067...e fi gbogbo ibeere yin ranse, ao da yin lohun

Bi a ba ri inkan ti ko ye wa, e je ki a beere ibeere pelu alaye, ao si gbiyanju lati se alaye lekun rere.

Gbogbo Oogun ti a ba ko sita la ti dan wo, to de ni idaniloju wipe yio se ise ti a ba ran.


Iwe iwulo ewe, egbo ati eranko ti wa fun tita bayi pelu owo kekere. Die ninu awon oogun to wa ninu iwe na niwonyi: 1. Oogun arobi nla, 2. Agbelepota, ebe agba to daju, 3, eyonu nla, 4. Osole tutu, 5. Ayeta, 6. Okigbe ada, 5. Oki igo, 6. Ki ota ma le yin wa lorun, 7, isuju, 8. Bi omo ba dabu sinu alaboyun, 9. Ki alaboyun bimo pelu irorun lai se ise abe, 10. Bi inkan osu obinrin o ba se deede, 11. Afeeri to daju, 12. Oruka aluwo oni yepe, 13. Asubusere, 14. Oogun arun ito sugar, 15. Oogun arun ogbe inu, 17. Oogun arun ogun oru, 18. Olubasiri, 19 awure nla ti a n pe ni fayegbami, 19. Oogun apesin, 20. Oogun afaro nla, 21. Oogun fun awon omo yahoo. 22. Oogun ohunmo, 23. Oogun ariran, 24. Oogun isoye. 25, oogun jedojedo. 26. Oogun roparose, 27. Oogun ajidewe. 28. Oogun awoka/eje dudu, 29. Oogun obinrin ti o n yan ale, 30. Oogun afose, 31. Awise, 32. Agadagodo nla, 33. Aforan to lagbara, 34. Orikosungbo/egbe, 35 ipese awon agba 36. Oogun idakole, 37. Oogun fun ato okunrin ti ko le di omo, 38. Oogun afato ti kii fi tete re okunrin lori obinrin, 39. Oogun fun igbega lenu ise. 40. Oogun fun oju rere lati odo gbogbo eniyan .....ati beebelo...awon orisirisi oogun to wa ninu iwe na le ni 500. Gbogbo re si je ojulowo oogun. Bi e ba fe ipin ninu iwe yi, e kan si wa fun account number ti e ma san owo si. Iwe yio te yin lowo ni ojo keta te ba ti san owo. E seun o, isese a gbe wa o! Ase.

Iwe yi ti wa ni tita nile Eko bayi ni Iju_ishaga.




Too, mo seba awon agbalagba awo ile aye, mo seba awon awo ode orun, mo seba awon Iya mi abeni...e juba o se o.

Iba, iba, iba

Akoda iba

Aseda iba

Ile ogere a foko yeri

Alapo Iku

Olona ola, iba

Esu odara, iba

Irunmale olukotun

Igba imale olukosin

Iba gbogbo yin o

Ero osaju, ero eyin, iba

Adase ni ni wun omode

Iba ki wun ni o

Eyin to ni aye

E je sise mi o san mi

Emi lomo agba

E je owo a maa je fun mi o

Ada ki nmu, ki o ge eku idi e

Omo eni ki nburu,

Ki a gbe fun ekun pa je

E dari jimi, ki e fi owo mi wo mi

Emi lomo aie fepo we

Osoronga opiki elese osun

Ajefun jedo

Oriri aye

Ebo aye ni a ru o

Osoronga ni nba ni gbele aye

Aje ni npa eni

Osoronga gbigbe ni o gbe mi o

Aje ma pa mi lomo
Lomi ki o somo mi

Iya mi agba opiki elese osun

A woni maye

A woni loju re orun

Eje lepo ekuru won

Iya-mi aye elekuru pupa foo

O gberita jagun

O gbe origi ke kanran kanran

Fori jimi bi mo ba se

Fi owo re wo mi

Na ke kanran wonu ile mi

Iya-mogun alara

Bi igun jebo

Aje gbe ni nje

Bi akala jebo

Aje gbe ni nje

Gbogbo eyi a ba se

Asegben ni e je o je

Iya-agba alapo iku

Olokiki oru

Ki nfo o fara pa

Onile origi ki njebo

Ki ebo naa ma gun rege

A agba ki nfi abo bo eni

Ki Omo ara aye ma ri ami won Lara eni

A jefun jedo

Ki nje tire tan

Ki o ma fio na han eni

Iya mi toto aye

Fio na han mi

Bi o ba gbe ori igi ke

Ma ke ao mi

Bi o gbe orita ke

Ma ke pa mi

Kike ni ki o fi ike re ke mi

Omidan eleye oloju owiwi

A ri eni ko to pe eni

Omoran ologbon

Linmo riro ati w ri eda

Alapo iku olona ola

Iku ti nba nro nile mi

Re danu,Opiri eleye moran bi afefe

Arun ti nba nro nile mi

Ro danu

Iya-mi omoran eleye

A pani ma yoda

A mubo ti nbe laye mi

Re danu o

Eyin ti o ni aye

E fa mi mora

Aje eleye e fa mi mora o

Am Yoruba but I can't really read and understand Yoruba and I really really need ur assistance medically because I've some medical issues and i need medical attentions. how can I contact you on this? thanks looking forward for ur reply.
Re: .. by adeyenuwo: 9:46am On Jul 21, 2017
[/color]
janle:
AGBERO ONIFUNPA:- Ao wa akuko adie to ti nko daadaa, ao yo abaweku re, ao fi kudi tio luju kan sinu re, ao wa sa ti yo gbe daadaa, ao wa ra ni awo funfun. Akiyesi pataki. E maje ki nkan kan ibi ise yi tie ba npa lawo o. Pelu ogo olohun ti wo bafe lu wa tabi won fe fi nkan kan luwa apa won koni lo soke bi won ba ti ngbe yo ma ro won ni. Moseba agba ikanni yi.
[color=#990000]
janle:
AGBERO ONIFUNPA:- Ao wa akuko adie to ti nko daadaa, ao yo abaweku re, ao fi kudi tio luju kan sinu re, ao wa sa ti yo gbe daadaa, ao wa ra ni awo funfun. Akiyesi pataki. E maje ki nkan kan ibi ise yi tie ba npa lawo o. Pelu ogo olohun ti wo bafe lu wa tabi won fe fi nkan kan luwa apa won koni lo soke bi won ba ti ngbe yo ma ro won ni. Moseba agba ikanni yi.
janle:
AGBERO ONIFUNPA:- Ao wa akuko adie to ti nko daadaa, ao yo abaweku re, ao fi kudi tio luju kan sinu re, ao wa sa ti yo gbe daadaa, ao wa ra ni awo funfun. Akiyesi pataki. E maje ki nkan kan ibi ise yi tie ba npa lawo o. Pelu ogo olohun ti wo bafe lu wa tabi won fe fi nkan kan luwa apa won koni lo soke bi won ba ti ngbe yo ma ro won ni. Moseba agba ikanni yi.
ki lo nje abaweku ati wipe se owo eyo ni kudi ti e mean
Re: .. by 08101646045atwp(m): 11:02am On Jul 29, 2017
OSOLE OWO TODAJU FUN CONTRACTOR ATI OMO YAHOO
:-Okan maalu nla kan, iho merin lo nbe ni ara re, iho ti aarin ao ki ori eye osin kan si, iho keji oba owo tuntun kan ao bu ewe ola si ninu a o wee papo ao kibo iho keji, iho keta odindi atare kan la o ki bo, iho kerin eran NLA tutu ekiri kan la o ki bo.
Ao gbe si inu ape tuntun odi jijo ti aba joo tan ao ro sinu ado ide nla ti yio gba gbogbo ebu yen, a o wa mu akuko adie pupa to ti gbo daada ao pa, ao ro eje re si ara ado ide yen, a o fi iye re le ado ide yen lara.
a o wa se adie yen toritese re, lepo niyo niru, ti o ba jina!!

EEWO REE:- Akogbodo to obe yi woo....

ETUTU RE:- Ao fi ewe iyalode meta tele inu awo ipese nla ti o le gba gbogbo obe yen ao daa sinu awo ipese yi, ao se adua si daada bi a ti se nfe, a o gbe losi ikorita meta lagogo mokanla oru, fun awon iya mi osoronga.
Ti o ba di ojo keji a o lo mu awo yen

LILO RE:- To ba di agogo kan oru ao ma fi oti schnapp original lo ebu yen lati inu ado ide yen.
ao lo lojoojumo for 21days

EWO RE:- Ako gbodo sunmo obinrin fun 21days ti a fi loo'o lowo ba de!!!

Anfani situn wa fun eyin aworo sasa toje AWO, bii WOLI, ALFA, ati ISESE todarare loju, lati darapo Mon egbe awon ojogbon ti ati ngbe awon ise alagbara jade, ti ape orukore ni MAJEMU LAILAI ON WSP!
ele fi orukoyin sile si ori :- https:///6rRqiAC3Y2bHcFdinedWUS :- bere lati Omo ogbon odun losoke. 30 years above!
Jowo mafi number re si abe comment'o
Whala'oni payin'o
Add links yen si odo'e
Kede mura sile fun idahun si awon ibere wa Ni ekun rere.
Ajuwase o
Re: .. by lhordspy: 6:55pm On Jul 29, 2017
Ejo kini eyan lelo fun eyan to ni staph infection to ti pe lara
Re: .. by Sebiotife: 7:28am On Aug 07, 2017
[color=#990000][/color]
Redoil:
i agree with you on this.
Re: .. by adebayo111: 7:13am On Aug 09, 2017
kini mo le lo fun obinrin tio je wipe okunrin ti poju fun ( iyawo to nyan ale)
Re: .. by woletaiwo: 9:05am On Aug 10, 2017
Saw this in your write up

itose l’o l’Oyo, onibode l’o ni aafin’

Please, what is the meaning.

Thanks
Re: .. by 08101646045atwp(m): 7:39am On Aug 13, 2017
Moki gbogbo ile wipe ototo meta'o
Mofi asiri yi sile fun awon ti won wadi Ola, sugbon ti won ti kolu eewo towa ninu'e, ti won wa nba inu fuu'aya fuu kaakiri,
Ema bami kalo!
Ti aba seso ola ti asije eewo ti won ka ni eewo ni awon baba wa ma nse iseyi,
Ni akoko ao akoko se ado gbekude ti ao mu:- Igba ewe ape, igba obi abata, igba orogbo, igba atare, pelu ori akalamagbo kan. adi jijo pelu omo'owu toti sise lagbede daada ohun ni ao maafi ro Lori INA, nigbati abajo tan, ao ro sinu ado, kekere kosi iye ado ti akole rosi
Ao fi iye idi akalamagbo ha lenu tobaje Fifi korun ni afese,tobaje gbi gbe mi ni aofi ewe ape di lenu aogbe ado kekere na mi.

Ni elekeji
Ewe ayajo IFA ewe atibirokun, abamoda, alupaida, ewe roro, eku eliri kan, aojo ao po mose
Ao we fun IJO meje pelu ewe awede !

Iketa ni etutu inu ogbe irete!

Anfani situn wa fun eyin aworo sasa toje AWO, bii WOLI, ALFA, ati ISESE todarare loju, lati darapo Mon egbe awon ojogbon ti ati ngbe awon ise alagbara jade, ti ape orukore ni MAJEMU LAILAI ON WSP!
ele fi orukoyin sile si ori :- https:///6rRqiAC3Y2bHcFdinedWUS :- bere lati Omo ogbon odun losoke. 30 years above!
Jowo mafi number re si abe comment'o
Whala'oni payin'o
Add links yen si odo'e
Kede mura sile fun idahun si awon ibere wa Ni ekun rere.
Ajuwase o
Re: .. by mercysamuelson(m): 12:30pm On Aug 14, 2017
Ayokunumi24; Please, did you receive any help concerning the visa stuff?
e jowo baba, e jowo e fun wa ni ogun ti eyan yio fi ri visa gba?
Re: .. by Ayokunumi24(f): 11:39am On Aug 15, 2017
mercysamuelson:
Ayokunumi24; Please, did you receive any help concerning the visa stuff?

e jowo baba, e jowo e fun wa ni ogun ti eyan yio fi ri visa gba?

No
Re: .. by Nobody: 2:19pm On Aug 18, 2017
08101646045atwp:
OSOLE OWO TODAJU FUN CONTRACTOR ATI OMO YAHOO
:-Okan maalu nla kan, iho merin lo nbe ni ara re, iho ti aarin ao ki ori eye osin kan si, iho keji oba owo tuntun kan ao bu ewe ola si ninu a o wee papo ao kibo iho keji, iho keta odindi atare kan la o ki bo, iho kerin eran NLA tutu ekiri kan la o ki bo.
Ao gbe si inu ape tuntun odi jijo ti aba joo tan ao ro sinu ado ide nla ti yio gba gbogbo ebu yen, a o wa mu akuko adie pupa to ti gbo daada ao pa, ao ro eje re si ara ado ide yen, a o fi iye re le ado ide yen lara.
a o wa se adie yen toritese re, lepo niyo niru, ti o ba jina!!

EEWO REE:- Akogbodo to obe yi woo....

ETUTU RE:- Ao fi ewe iyalode meta tele inu awo ipese nla ti o le gba gbogbo obe yen ao daa sinu awo ipese yi, ao se adua si daada bi a ti se nfe, a o gbe losi ikorita meta lagogo mokanla oru, fun awon iya mi osoronga.
Ti o ba di ojo keji a o lo mu awo yen

LILO RE:- To ba di agogo kan oru ao ma fi oti schnapp original lo ebu yen lati inu ado ide yen.
ao lo lojoojumo for 21days

EWO RE:- Ako gbodo sunmo obinrin fun 21days ti a fi loo'o lowo ba de!!!

Anfani situn wa fun eyin aworo sasa toje AWO, bii WOLI, ALFA, ati ISESE todarare loju, lati darapo Mon egbe awon ojogbon ti ati ngbe awon ise alagbara jade, ti ape orukore ni MAJEMU LAILAI ON WSP!
ele fi orukoyin sile si ori :- https:///6rRqiAC3Y2bHcFdinedWUS :- bere lati Omo ogbon odun losoke. 30 years above!
Jowo mafi number re si abe comment'o
Whala'oni payin'o
Add links yen si odo'e
Kede mura sile fun idahun si awon ibere wa Ni ekun rere.
Ajuwase o


E jowo

Kini itumo eran NLA tutu ekiri kan?
Tabi ka nipe iru eran wo gan ni?

Abi eyi ti mo nro ni!!
Re: .. by horlakunmy: 8:05pm On Aug 19, 2017
osole owo NLA kan reooo koni ipalara rara .

foroforo olokun ,eyele funfun,ESO baka,ewe aje ewe sawerepepe,omi agbon,igba olomori tuntun ,ao gun gbogbo awon nkan wanyi papo pelu eyele ,ako gbogbo gun APA eyele mejeji man wan,APA eyele mejeji lao fi tele igba ti afe ko ose si,ao pa eje eyiele yen si ara igba ,aofi iye eyiele Le ara igba yen,omj agbon laofipo ose yen ,ako gbodo fi omi Miran po ose nan ,osole yi damiloju pupo ,fun alaye epemi sori number MI ,07087774041 or 08091466676
owo akoko ti osole yi ba gbewa ,aofi die se Sara nibe .iba olohun..iba a won to koko jawe ,iba awon iyami osoronga
Re: .. by horlakunmy: 8:28pm On Aug 19, 2017
Osole akeesu ,ojojumo ni ao man mu owo tuntun ni apo WA ,gbogbo igbati aba ti nilo owo ni aoma mu owo ninu apo WA,mofi olohun bura,eni toba se ise odi dandan kodi olowo ni,

afoman botuje,afoman Lara ,afoman igi mangoro,pelu oga oye ,owo 1000 tuntun pelu ,gbogbo awon kini wanyi gungun nio ,koise jijo,ao koko pa eje oga yen sori a won nkan eroja toku ,ao koko jeki oga yen GBA awo owo 1000 yen ,ti aba gun tan ,ao Sa tiyio GBE ,ao ri wipe ori lubulubu bi elubo ,ao da si ona meji ,toba di ojo alaruba , ao sofun a won alfa Oni hantu kiwanbawa han ayayi si ona meji ototo.
aya na niyi
انما امره اذا اراد شيءا ان يقول له كن فيكون 70 times
ao hansi ona meji ototo
toba wadi oru ale Wednesday eyi tinse oru majuma Thursday ago kan ,ao mu hantu alakoko Peru did a idakan Ogun ti apinsi ona meji sinu hantu na ,ao gbemu toba tunwa di ago kan osan Thursday ao tun fo hantu ikeji pelu dida Ogun kan toku sinu ohun na ..


akiyesi, omi ojo laofi fo hantu na ,aso funfun ni aowo ni ojo Thursday...


osole yi damiloju pupo ,fun
alaye epemi sori number MI ,07087774041 or
08091466676
owo akoko ti osole yi ba gbewa ,aofi die se Sara
nibe .iba olohun..iba a won to koko jawe ,iba
awon iyami osoronga


osole owo NLA kan reooo koni ipalara rara .
foroforo olokun ,eyele funfun,ESO baka,ewe aje
ewe sawerepepe,omi agbon,igba olomori tuntun
,ao gun gbogbo awon nkan wanyi papo pelu eyele
,ako gbogbo gun APA eyele mejeji man wan,APA
eyele mejeji lao fi tele igba ti afe ko ose si,ao pa
eje eyiele yen si ara igba ,aofi iye eyiele Le ara
igba yen,omj agbon laofipo ose yen ,ako gbodo fi
omi Miran po ose nan ,osole yi damiloju pupo ,fun
alaye epemi sori number MI ,07087774041 or
08091466676
owo akoko ti osole yi ba gbewa ,aofi die se Sara
nibe .iba olohun..iba a won to koko jawe ,iba
awon iyami osoronga
Re: .. by horlakunmy: 8:30pm On Aug 19, 2017
Osole akeesu ,ojojumo ni ao man mu owo tuntun ni apo WA ,gbogbo igbati aba ti nilo owo ni aoma mu owo ninu apo WA,mofi olohun bura,eni toba se ise odi dandan kodi olowo ni, afoman botuje,afoman Lara ,afoman igi mangoro,pelu oga oye ,owo 1000 tuntun pelu ,gbogbo awon kini wanyi gungun nio ,koise jijo,ao koko pa eje oga yen sori a won nkan eroja toku ,ao koko jeki oga yen GBA awo owo 1000 yen ,ti aba gun tan ,ao Sa tiyio GBE ,ao ri wipe ori lubulubu bi elubo ,ao da si ona meji ,toba di ojo alaruba , ao sofun a won alfa Oni hantu kiwanbawa han ayayi si ona meji ototo. aya na niyi ﺍﻧﻤﺎ ﺍﻣﺮﻩ ﺍﺫﺍ ﺍﺭﺍﺩ ﺷﻲﺀﺍ ﺍﻥ ﻳﻘﻮﻝ ﻟﻪ ﻛﻦ ﻓﻴﻜﻮﻥ 70 times ao hansi ona meji ototo toba wadi oru ale Wednesday eyi tinse oru majuma Thursday ago kan ,ao mu hantu alakoko Peru did a idakan Ogun ti apinsi ona meji sinu hantu na ,ao gbemu toba tunwa di ago kan osan Thursday ao tun fo hantu ikeji pelu dida Ogun kan toku sinu ohun na .. akiyesi, omi ojo laofi fo hantu na ,aso funfun ni aowo ni ojo Thursday... osole yi damiloju pupo ,fun alaye epemi sori number MI ,07087774041 or 08091466676 owo akoko ti osole yi ba gbewa ,aofi die se Sara nibe .iba olohun..iba a won to koko jawe ,iba awon iyami osoronga
Re: .. by horlakunmy: 8:26am On Aug 23, 2017
Ogun owo tikoni ipalara ,ewe owu akese oojo ,ESO Lara pupa,ao gun man ose dudu ,sosorobia ni aofi po ose na ,ao GBE eja ojiji aye tele igba ti ao ko ose na si ,so bere si we ose na leyin 16days ,eje ako eyeiele funfun laopasi ara igba ose na,,,,,fun ekunrere alaya pemi sori number yi......07087774041 or 08140444773.

Re: .. by dplanner: 8:49am On Aug 23, 2017
Osole owo nla fun enikeni to daju gan......... A o han suratul yasin lona 9, eye onbe 9, okan malu ti ko womi kan, a o lo eye onbe yi lubulubu, a o fi omi ojo fo hantu yi ti a o fi okan malu yi je lepo niyo ise to daju ni iwo to ba Fe se ise yi kan si mi ni ori ero ibani soro 07067796292, 07055595911.
Re: .. by horlakunmy: 8:57am On Aug 23, 2017
Ogun eniti oro re ko lojutu ,asina tipatipa,ewe ajeobale to rele 16,omudun re 16,eyi tofe jabo tiko kanle 16,iyere 16,Ata ijosi 16,eyin adie mefa,isasun tuntun,aseje ,ojo Thursday tabi Tuesday or Monday or Sunday. call me 07087774041 or 08140444773.

Re: .. by horlakunmy: 8:59am On Aug 23, 2017
if u have red or white liquid MECURY contact me 07087774041...
Re: .. by horlakunmy: 9:00am On Aug 23, 2017
to change your red or white liquid MECURY contact 07087774041
Re: .. by horlakunmy: 9:03am On Aug 23, 2017
for your red or white liquid MECURY ,we don't sell oo ,contact 07087774041
Re: .. by horlakunmy: 9:04am On Aug 23, 2017
need operator for red and white liquid MECURY..07087774041
Re: .. by horlakunmy: 9:06am On Aug 23, 2017
did u have red and white MECURY ?08087774041. no play oo
Re: .. by horlakunmy: 4:06pm On Aug 24, 2017
Ogun owo gbewa to dami loju gidi ,,eja ojiji aye meji ,afoman laali,afoman Lara,afoman obi abata ,ewe aje tutu,ewe owu akese , lofinda Bintu Sudan original,Ao gun gbogbo kiniyi papo pelu eja ojiji kan ,ao kowan man ose funfun,lofinda yen laofipo ose yan,eja keji laotele igba taoko ose si ,ao pa akuko funfun kan fun ose na,aofi adie nase Sara,eni tiyiolo ise kogbodo lo nibe ,leyin ojo meje laofi bere sifi ose yi,,,call me if u have any question , 07087774041....08091466676
Re: .. by dplanner: 11:30am On Aug 27, 2017
ise fatiah fun iso ati arisiki ti a mo bo mole to daju o n bo lona laipe .
Re: .. by fredo360(m): 9:02pm On Sep 01, 2017
ekun deede asiko yi o oruko mi no Taye eejo kini eniyan le lo ti nkan omokunrin ba kere ju ojo orie lo. ejowo mo fe kii edami lohun ki oju maba timi oooh
Re: .. by Opeexy(m): 11:54pm On Sep 17, 2017
Baba ejowo kini itumo lilopo ti a o fi pa eyin adie na lara
Re: .. by Whitty1992: 9:38am On Sep 24, 2017
Harjibode:


E jowo
Kini itumo eran NLA tutu ekiri kan? Tabi ka nipe iru eran wo gan ni?
Abi eyi ti mo nro ni!!
Re: .. by fatus2210: 3:17pm On Oct 03, 2017
tundebadmus:
ewo wo ni oni eje ka mon ewoye ki atoda owole,ewe yio maje o
ejo ewo WO ni ise yi ni

(1) (2) (3) ... (90) (91) (92) (93) (94) (95) (96) ... (99) (Reply)

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 57
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.