NiteAngel's Posts
Nairaland Forum › NiteAngel's Profile › NiteAngel's Posts
1 2 3 4 5 6 7 8 9 10 (of 12 pages)
Too, bo ba ma fi pade de, emi a ti lo. Ife ngun o, nitemi okan mi fa s'ise, Okankan laa'ji |
Use spirit; 70% alcohol. Wig may be better. All the best. |
Oogun lo fe fi fa ni abi iwo na la'je? Mo beere ni o |
Why must you drag the Bible into every lame issue. If weaving your hair defines your culture, career, personality; go ahead and weave otherwise leave it for teens who are still striving to carve out who they are. |
Ma da Ayefele loun ThiefOfHearts, oun to moo je lo fe yo. Oti e ti yo koo to je. Omo to n mu siranran ko ti e wa si ni to si |
Rowlandwhy, point of correction; males (like you) who find time to make up, wear English costumes and make noise are simply defined as clowns! Arunruala! |
Ayefele, ife ti shu o loju? Wa ti e ni suru ka oju iwe ki o to ma beere "is that MINUTE?" |
Ki nto ma ba eto lo mo fe sre dahun si awon oro kan to kan mi. Ayefele ti Molete, lehin ti o se mi ni "DUHHHHHHHH" otun wa so wipe padi ni wa. Se oro pe nko mo itunmo 'duh'. Debosky, wi wole agbara kii se lati le lu ni pa o. Mo fi n m'ara ji pepe ni o. Ko ni da ki agba ara da mi l'owo ko ati f'omo yo. Mi osi fe di daddy lai ti d'arugbo. Gnature, eje ka ma fun Jesu lowo. Bawo lo se je wipe oun lo be finalize omo ti o fe fo mo'le nigbati ko f'ara mo agbere. Chiegemba, boo ba ma so Yoruba o nilo lati gba oluko to gbona, Yoruba e ku die kaa to |
Enle o. Ta ni nbe l'agbala o |
Agba ti o yo kun awin lo ni; sugbon bo ba poju aya re ma bere si ni pe o ni daddy o. Daju daju gbana gbe se re yo lara ayefele; bi o ba si ti gbana bawo n'iya eni se ma di eni ti ore eni fe gba, Otun d'ola |
Too mo ja'wo l'oro re. Oun ti o ba de ba bo wa ma fi to wa leti l'ojo 'waju. Al Raheem; jeje ni wahala joko to l'on f'igi to o. Ma pe mi nigbati won ba won seriya fun o o. E maa ba eto lo; mo fe wo'le agbara. Otun di ola. |
Ayefele Ayegbege ti Molete, boo ba ma ko Yoruba ko ko Yoruba ewo lade fi 'mi' ko 'me', |
Hmn iya re kekere to n'toju re? Oro po ninu iwe kobo. Oy'omo to n'sokun o si ye 'ya re ti nro l'ekun, |
Bo ba tie fe ta si MINUTE ibere ati gba iso ko ni lat pe ni iya re. Iya mo iye omo to bi o, |
E bere lowo re o, |
Rowlandwhy, if indeed you are a Nigerian then I pity your situation. What is the beauty in having to knot a tie forcing your gogogongo to undergo undue stress and wear tontirin trousers that gives your kini hassles. I'd rather enact a law to compel all leaders to wear traditional attires especially when in official functions and also a law compelling them to send their young children to Nigerian schools and receive medical attention in Nigeria. That way our economy will receive a boost. With the ban on clothe/material importation we have seen a boost in our ideas and by implication our clothing industry. Wake up man; today you need an identity to survive. |
ka'le o. Awon omo wo lo nbere o? |
O da bi eni wipe oro oye yi si ru mi l'oju bo ti le je wipe arabirin Desorlah s'alaye re fun mi l'ano. E wo tun ni ti Tafari to fe da'le se oti lile sile; nje aafin o ni gb'ole gb'ole bayi |
E kaale o. Bo tile je pe loruloru le mi fi n tana, mo ni ki nke si yin ki n le ba bale ji roro |
It means exactly what she said; return to see her when you can drive down or at least pay for a taxi. You two may have been on a face-lift relationship otherwise how you got to her place shouldn't matter. Hardluck brother. |
Funny Caustic, I'm sure the comment you responded to has to do with recent kidnappings of Whites in PH. Poster, congrats. Pay your tithe, be diligent and never become too sentimental to go for a better job. Don't be stagnant; your employment may be based on sentimentalism but your employers won't become sentimental enough to keep you when a better person is waiting in line; be productive. When you start thinking of moving the funds you see into your account then it's time to run. Achieve. |
Here, on this thread. I know that's hasty generalization but I have always believed that a present experience is indicative of the present situation. I'd speak to my friends and read more. I'd also have my friends in the print media look into it. |
Oun ni mo se so wipe ofo di meji. Bo ba je oyinbo, won le pe o sin win sugbon niwon pe o tie je dud yen; leyin ti won ba ye wo finifini boya ori olori lo gbe wo'le abi o f'ese rin wo'le ni; won o wa da seriya fun l'oju pali. Mo ri o na, |
Sun ke? Ile Angeli Oru sese mo ni. Lehin ti mo ba s'are loju kan die mo le pada wa; iyen to ba ma wa ni bi ti mo ba pada de. Aije be, otun di ola. |
Iyen le o, Ki olorun pe tu si awon ebi olopa ati ebi agunipa o; ofo di meji Ni bi to ti nwo'jule kiri (se kii sa se be lo se n ye awon ayaba wo, yi ye won wo o buro sa ma ye won wo de sa'le) mo ti npalemo o; mo fe lo wo le agbara (gym) ayounge lo l'aiye. |
Paga, ki lo ri l'obe to fi wa'ru s'owo? Ewon gbere ko lo k'owe si yen? |
O se wa wo si bi obe inu ikoko? E wo la ri gbo lati Luton o? |
Segoye2, ma gba o ni'moran ko ma f'ebi pa ra re o. Bi ebi ba n'pa o, bo s'ile dana lati wa ounje. A ko ni fara mo oloye to mu aya re leru o. |
Olalowo, mo se bi o wo'le ni. Ka to se'ju pere o si ti d'ategun |
Wa ri ke. Ma f'okan ba'le eti mi o si ni jina s'ile pelu. Bi oye ba ti nsunmo; ma tun ma kan si yin. |
I can't believe that this is still as pronounced as it was in the 40s and 50s. At times I wonder if Christianity has not been reserved for the church and formal occasions; isn't this what the power of Christ came to destroy? At times we wait too long for the whites to come in to take credit for what we know is barbaric. Like the killing of twins; I see an end in sight |
It means exactly what she said; return to see her when you can drive down or at least pay for a taxi. You two may have been on a face-lift relationship otherwise how you got to her place shouldn't matter. Hardluck brother.