Richylaw's Posts
Nairaland Forum › Richylaw's Profile › Richylaw's Posts
1 2 3 4 5 6 7 8 9 10 (of 17 pages)
Mo gba fun o, omo ni o iwo l'oga ninu egbe re Nigba ti mo teti si oro iwuri ti okan ninu awon oguna gbongbo omo ile wa arabirin Dokita Ngozi Okonjo Iweala so , ori mi wu o si tun mu mi ri aridaju wipe ireti be , niwon igba ti a ba ti n ja fun eto wa ti a si n fiye awon alawo funfun wipe awa na kii se eni a n fowo re loju. I am proud of this woman, , we all have a message the world is waiting to hear. Negative images of Africa dominate the news: famine and disease, conflict and corruption. But Ngozi Okonjo-Iweala, the former Finance Minister of Nigeria, says there's a less-told story unfolding in many African nations: one of reform, economic growth and business opportunity. Find out from the video coverage of TED at Monterey California Conference at the URL stated below: http://www.ted.com/index.php/talks/view/id/127 ki e ni nice weekend. |
deezzle:YEAH , Black man Akeem Kareem |
nana:Ki lode Nana. Iwo ati tani e jo n ja? |
o ti o |
Doyin thanks |
There is this one I can't remember much of the lyrics now except the begining which goes like this: ole oleeee ole oleeee ( sure not thiefs thistime around) |
Yeah , Doyin . It's Mike Okri. I love the song. Anyone got it? |
Time na money o time na money use your time no waka, Money no dey come from heaven through better thing money dey come ![]() where is he, can't even remember the name |
aloib:This is 'The way Forward' by Sunny Ade and a host of other musician. Not really so old anyway I think it's a '90 song. No one has mentioned Papa Kennery Orlando Owoh - Yellow sisi, Ma pa mi iyawo asiko, Even Orlando Julius has some good old one- Nana, Ikoko ti o jata How about our famous evergreen song in Naija- Sweet mother by Nico Mbaga Yoruba music lover will appreciate the likes of old stuffs from Haruna Isola ( Baba ngani), Ayinla Omowura, Yusuf Olatunji, Ojindo don't mind me na ma granpa cause am Doyin13 That was a good job. |
Aloib ki lo tii fa ekun ninu oro yi, fi suuru ka yoruba yi daadaa , yi o ye o. Sebi awa omo iya re na ni a ko si le. Ni gba ti iwo ko tire awa na sa ka! Desorlah bawo lariya de se ma ke de ri loni ke? Ojo Eti miran tun leleyi o, je ki n fun e ni 'logo' ti o wa nisale yi ki o fi bere si se ajoyo Friday, emi na fe bo si enu ise ni akoko yi o.
|
Debosky ,O ti da be na nu, sugbon yio dara ki alagba Ayanjide fi ara mo wa dara dara ninu abule yi ki a to le mo iru eni ti won je gan. F'otun we osi, f'osi we otun , ki owo sa ti mo ni Isiwo iporo wo, ohun aba jo wo gigun ni gun Ogidimolaja , Ayanjide ti d'awo ile Ife loni o, kawo mo gbe awo nigbowo loku, k'awo mo ba te , k'awo mo ba ya Mishoo, o da mi loju wipe gege bii baale , n o ti jayo pa lati fun Nana ni iwe sowe dowo.Debosky oko re na o si binu si rara. O sa san ki a na owo fun eni ti o mo iyi re. Abi o ti gbagbe iyawo kekere ti a fe fun baale ni ojo kinni ana (Mukinatu)! awon da loni?Aini suuru ti mu won siyan lai duro gbobe ,owo ti o si ye ki a na fun iru won ni a pa ona re da si odo awon ti o mo iyi wura wonyi o. Se bi iwo na mo wipe ohun ti "agbalagba fi n jeko abe ewe lowa. Eyi ti o si fi ju omode lo, ko ni fihan, bi o ba fihan ko ni fi le lowo, bi o ba file lowo, ko ni ko bi yio se lo, bo ba situn wa ko wayi, ko ni fun lero re, amo sa o bi o ba fun lero re , ko wule ni fi ewe ti a fi n ki han tori ojo t'ewe o ba sun oko." Nitorina na agba t'emi o yo le da o Ko je bo ti je , eje ki a ma rin erin yanturu bi asa Ayanjide ![]() |
je ki o ma wu o mishoo Nana, iwo ma worry, baale ki na wo loju agbo, cheque e wa nibi yi je ki a jo tan! |
You only need to really see me dancing. Play the song and watch these guys dig it .Original ijoya level. JUST A PRE-FRIDAY JOLLIFICATION
|
Baby baby Bolanle bebebi sisi alakada arewa fi wa sewa omodun bebebi olomoge duro na ire la n bawi danwo lo bi 'ya okere emi gangan ni baba okere o da wo mi ko tun mi wo baby mo dun mo tun re ni tun fi jo gbe mi wo bi jigi jigi jigi jigi baby mo ni ko fe mi wa wa gba p'ori loni fila wa tun gba p'ese lo ni bata baby surulere, o sa mo levels ti mo wa gbami gbami towo tese yi o, olomoge Baale has gone gaga and groovy okay dig it , dig it ![]()
|
o fi dudu je won bolanle o fi pupa je won bolanle o fi kebe je won bolanle Ibadi aran o bolanle Face of africa, he he Ajoma gbadun ni le yi o Bolanle please don't hold me I want to dance
|
tafari:Ko si ohun to bo nile ti , ile o gba o, apa oba ka ilu tepontepon. Sugbon nipa ti oye, je ki a mu dani si egbe kan na. Ise wa pa o ( and yours?) |
Tafari! oye ke lowo ta wa yi , je ki a so oro miran na ![]() |
tafari:Wayi okan mi bale |
Mishoo, ha ha aduru eleyi lo fe je tan, o si tun mu mi ranti itan kan ni igba lailai ti won n pe ni ' itan Ibenbe Olokunrun' walahi yio je ile run ![]() Segoye , mo ri wipe ile n dun gan ni sa , iwo sa ma jeun soke lo. Baba re lo ni ile Awon ara Ife Akoraye nko? You can get Jesse Kings album in Naija while you are there now, I got both the audio and the video in the traffic hold-up, the last time I was there. Maybe when you are back to Clapaham Common I can post you the video. Mishoo has been very sensitive to the richness of entertainment , culture and play of words in the album (kudos).Mishoo boya ko o ju ti 'Bolanle Olomoge' ati 'Mummy' si ori afefe fun wa. Desorlah awon orin re yen de n dun gan ni o, o da mi loju wipe ajo tiraka mole ni o ma n jo ijo re na. E ku faaji, opin ose lo tun de tan yio. Debosky, Debosky , oko Nana ti o ni rival, o to ojo meta, se alaafia ni. Awon olokada Onitsha nko, se won n pawo wa si ile? A o kere de ile o. Nana for real se e n to ju won? E ma je ki won wo ita o. Wunmi oloruko ti o fe amojuto, e ku miliki ati yotomi o, e ku ko le da taye n ba kiri. k'ade pe lori la n ki oba, ki l'eke pe lowo ni tawon ijoye, HELOO ! ni ki a ma ki iru yin o. Omoge Ko da o ti raji subu pelu orin re yen, , it was sang by Tunji Ogunlana ( I think)- such an old -new age song.In the days of 'Why worry for nothing' by Dr Akin LewisBo wo ba tan lowo alakowe Asi ma se kondu kiri Bosu ba ti loyun gbese awa di guguru perere epa perere guguru perere epa wom followed by slight instrumental In the same album he also had this track omo alakara wa jewe iya o omo alakara wa jewe iya o Towo mi ba te e o keran heeeeeen Bowo mi ba te e o keran o omo alakara o, a e omo alakara wa jewe iya se n ri ebun, ebun omo lara mi se n ri ebun, ebun omo lara mi, etc Keep on rolling them out , it brings about the nostalgic serenity of the past. Dblock so wa? abiodubade Se gbogbo awon ti e n gbabeski fun e? ![]() E gbona , ibo ni Alagba Tafari wa lati ojo yi, se ko si nkan o , o dabi eni wipe a o si iko nidi lati lo beere alaafia won wo.Se to ri wipe a o fun won loye nilu yi ni. Suuru lo laaye o ![]() Every one in da house wave to the air and say CHEEEEERRSSSS! |
mishoo:Eyin na ni ka ma bi o. Nigba to je wipe gbogbo awon obinrin ilu wa patapata ko lee bere oro lori okun yi ayafi ti won ba so Hello !. Emi si ti gba bi eni ti n gba igba, o dabi eni wipe ti mo ba ti fe soro , ma ya ma koko so wipe Hello ! |
ok guys, I will do that over the weekend |
Hello ! |
Copycats or not, at least we are copying good ones and by the way from the posters excerpts we have this: The Apprentice is one of the most globally recognized reality television franchises and the programme has, since it was launched in the US in 2004 by Donald Trump has been replicated in 23 countries of the world. so we are not the first to cling to it. Pray we have more good things to copy and utilise productively from the western world. |
Desorlah nkorin , Mishoo n ba gbe, Minute na n mi legbe lapakan. Ohun to n dun wa ninu ko ni di ibanuje fun wa o. Nkan ayo na ni a o ma ri o. E ku ikale. Minute aadorun?? o so wipe o ti i gbo ni odun yi. O n na lo de ti gbo yen o. Believe me that's what this thread is for , we are all learners and we will learn till we move to the next world |
Enikan kan o ti de ibi loni. o da mo kan ni ki n se e n le be n ni o cheers all. |
Mishoo n je o ni so wipe temi ti wa poju bayi . Isu eni ni towo eni b'epo o. Beautiful Nubia ( Dr Segun Akinlolu) je ore mi pataki pataki, mo si je okan ninu awon ti o ma n se agbekale asa ati ede ni ede oyinbo ati yoruba (poetry) l'alaale ojo eti to ba gbehin osu ni Jazzville club, Yaba, ni ibi ti gbogbo wa ti ma n pade ti a ba ti wa le. O ti n to bi odun merin sehin nisisiyi. Such a good chap with high flare for culture and traditions even though he is a veterinary doctor who works and live in Canada! Je ki a gbo orin re waayi |
Mishoo nkankan , lagbara eledumare obinrin lo ma fe o , o ni fe okunrin . Mo feran orin awe Jesse yi kii se kekere. Bi ko ba ni ya o lenu igba akoko ti mo ma gbo ni ale ojo ti mo ni mo sun si titi ona Ibadan!, mo tan asoromagbesi inu oko mi ni mo n se faaji, Jesse King si je okan ninu orin ti mo gbo lale ojo yi. Nigba ti mo maa pada sii ilu oba , mo ri daju wipe mo ra 'ape akerusikun' (cd/dvd) fun sinima amohun maworan ati orin ori asoro magbesi ti ogbeni Jesse yi.Ohun ti o wa dun mo mi ju ni wipe , original carryable soul ni Jesse, may he continue to walk and never stumble ,ase As he laka stand, even we always know that lala toroko, ile lo m bo, shall he not obey law of gravity, ase Tika for you my songito, shall the holy water continue to mesmerize you in the realms of opekesis,ase And may you continue to be alase ekeji orisa among the opakasis, ase kosekose ni ti ila kose ASE. CARRYABLE SOUL IN DA HOUSE, EYIN DA? ONE LOVE IL YA DU KAKANFO.
|
Mishoo , you did justice as well. Segoye , make sure you enjoy yourself to the core in motherland. No place like home pal. The country changes every single secs and I pray the positive changes comes to superceed the negative ones soonest. I have been to Nigeria twice in the last ten months and all has been fun fun fun, except that I made a mistake of been on the Lagos -Ibadan express way on a day the Redeem camp and Mountain of Fire had a programme in one of my visits, I need not kid, I slept over on the road! got into it around 6pm on Saturday and found a way out around 5am on Sunday . It is still part of the fun after missing this madness for years. ![]() |
nana:ok here we go Nana Ojo ti omode naro ko ni rin, the milking baby does not start to walk the very first day he attempts to stand upright. Ojo agun ko la n kanrun. You don't get to touch the skies the very first day you shoot out into lime-light Bo ba pe titi akololo yio pe baba. Sooner or later the stammerer will succeed in pronouncing baba ( father) consider a stammerer this way; baaaaa b b b b a a bab bbab baba! ![]() Hunrunhunrun ni yio po, o didan ki elede de Oyo. The pig may strut and poke the muds along it's journey but it will definitely reach it's destination. All meaning that there was a beginning to an end and also an end to a beginning. cheers |
O seun jare Mishoo, O ku ayesi o. Nana, wetin be dat, tell me you can't read that. That is yoruba for you in the medium order ![]() |
Chiori:That' s true, but what do you expect, Ron is old . I was opportune to be part of his concert/ birthday last year December (06/12/06) when he turned 62!. Such a blessed man |
dblock:Ojo ti omode naro ko ni rin, Ojo agun ko la n kanrun. Bo ba pe titi akololo yio pe baba Hunrunhunrun ni yio po, o didan ki elede de Oyo dblock Iwo sa ma so lo, sebi yoruba ni? La enu re ki o si ma so ![]() |



Awon ara Ife Akoraye nko? You can get Jesse Kings album in Naija while you are there now, I got both the audio and the video in the traffic hold-up, the last time I was there. Maybe when you are back to Clapaham Common I can post you the video. Mishoo has been very sensitive to the richness of entertainment , culture and play of words in the album (kudos).