Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,164,170 members, 7,856,704 topics. Date: Tuesday, 11 June 2024 at 04:52 AM

Richylaw's Posts

Nairaland Forum / Richylaw's Profile / Richylaw's Posts

(1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) (11) (12) (13) (of 17 pages)

Romance / Re: How do i Approach Girls Without Rejection? by richylaw(m): 4:28pm On Jul 04, 2007
I only realised that I instantly became a stammerer the very first time I tried it. Lost her for that moment but soonest I became a tutor myself.

Guard your heart,
never see her has someone who will say no ( even when it's most likely she will)
Assume what you are trying to express to her is as natural as what you do day to day
When eventually you fail, be determined to try again

He who fights and run lives to fight another day!
Romance / Re: Guys That Can Dance by richylaw(m): 3:36pm On Jul 04, 2007
luxoire:

@richy

its like u were d michael jackson of your viallge/town ohh,  grin

Well I don't class myself with MJ in dancing , he his stucked to a genre, I am not .
I learn new ones if the need comes.
Intercontinental dancer you said, grin
Culture / Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by richylaw(m): 2:05pm On Jul 04, 2007
Tafari kaabo o se alaafia ni o de.
Wahala wa ni ori oro re o.
Se alaye fun wa bi Mr Ferlie se je si e.
Culture / Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by richylaw(m): 12:07pm On Jul 04, 2007
Mishoo,

Iwo sa fi awe yen sile o,
''omode siwo lu iroko, o n boju wehin, ko mo wipe ki i se ojo ti a ba na oluwere ni oluwere n bu ni je!''
Culture / Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by richylaw(m): 12:08am On Jul 04, 2007
Abule Yoruba lo wa yi o ni ilu Nairaland ni ibi ti Oluaye Oba Seun ti gunwa, emi si ni Baale abule yi
Culture / Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by richylaw(m): 9:03pm On Jul 03, 2007
MIRACH:

howu risi lost panu de esinsin nbo,abi o tun fe pa ketekete ni,keke aburo re leyi nse

ADABA O NANI A NKUNGBE, INANJO EYE N LO ,KETEKETE KU ISO PIN
Culture / Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by richylaw(m): 7:27pm On Jul 03, 2007
Oponu eniyan gba ni o fun ohun ti o n se yi, ko si si iwa laakaye kan ni opolo re. Mo lero wipe o ni opolo ati oju lati ka iwe sha, se ibi je abala okun 'romance' ni? Abaniloju je eda. Itiju gba ni iru iwo yi je fun iran yoruba, ti o ba je okan ni o. Ki lode ti o fi je wipe awa omo adarihurun ko ni owo fun erohungba inu omo lakeji won, paapaa julo omo yoruba ode oni?. Bi o ba je wipe o ni onimoran ti o dara , mo mo wipe iru iwa alasise yi ko ni ti owo re se.
Mo mo gbangba gbangba wipe iwo na ni olutomiwa o kan pa oruko re da ni.
Joko ki o ronu ara re wo, iwa obo, eranko gbaa ni eleyi.

Koda o ti fihan gbangbagbangba wipe okobo ni o , iru awon aworan yi ni o si yan laayo lati mu ironu ailedide olomokunrin re kuro.
Iba san ki o lo si gbagede ibi ti won yio ti gba o towo tese pelu iwa palapala re.
Awa ko ni fi aye gba iru eleyi ni ibi o.

SI EYIN OMO YORUBA ATATA TI O TI  KA ESI MI TI O N BE LOKE YI , MO FE KI E MO WIPE  ARAKUNRIN  MIRACH TI YO AWORAN TI O GBE SI ORI AFEFE TELE KURO. ELEYI TI O DABI OBO NI ORI IBUSUN YI ATI OMIRAN TI KO FI IWA OMOLUWABI HAN NI. ELEYI TI O TI YO KURO GANGAN NI O MU MI KO ESI YI.
ESE PUPO
Art, Graphics & Video / Re: Damsel In Distress! by richylaw(m): 7:10pm On Jul 03, 2007
strykin:

Hullo!im workin on a project, sort of a year cd 4 an organizatn wit graphix,pictures,video clips,nd phaps background music.im NO cmputa guru bt i had some xperience wit swishmax a while back, a software wit graphics nd stuff, hweva,i don't know where 2 get d sftware anylonger, some sites r damn difficult wit dwnloads.anybody know hw i can get it,or alternatives?ild also appreciate hints, nd all xtras.THANX A MIL!!!

@ copy of swishmax was sent into ur mail box as provided on your profile but actually bounced back. If you still need it you can holla back.
Culture / Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by richylaw(m): 3:32pm On Jul 03, 2007
mr ferlie:

ese baale, eyin ara ilu, se efi owo si ki won fi mi je oye ni ilu wa yi?

O ti o, Ferlie bi ti bawo, Tafari ni mo mo o. Ara awon iwa alumokoroyi ti a n so yen na re o. Yanana oro yi o, ba wo ni Tafari se tan mo ferlie?
Romance / Re: Guys That Can Dance by richylaw(m): 12:08pm On Jul 03, 2007
''Ijo la ni o jo o
Ko ma wule pose o''

Your posing makes no good, keep it down and dance it out.

It's my life and I hardly can do away with it. If life is not for females alone then real good dance should be part of a man as well. I will dance to anything the right way grin, makossa, soukous, salsa,tap dance, ceilidh, slows, even the traditional bata dance! name it, oh my God. Gone are the early school days when I do go for disco competion and also get paid because I go about dancing on stage for a reknown juju musician.

@ Poster
Yeah , ur observation is true, it is as well a good form of exercise
Art, Graphics & Video / Re: Is Maya The Best For 3d? by richylaw(m): 10:09am On Jul 03, 2007
Grafikdon , sure you've spoken well
Culture / Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by richylaw(m): 9:59am On Jul 03, 2007
Tafari , o ku iyanju o,fun wipe o tile dahun si okan ninu awon ibeere yi, gbogbo ohun to ku nisisiyi ni wipe ki awon ara ilu fi owo si oye re. Iwo funrarare ni o o si se ise yi,
Ba awon eniyan bi Debosky, Ayefele, Iyalode Ikamefa, Mishoo, Isrealite, Minutes, Nana, Segoye, Disguy, Desorlah ati awon eekan oro to ku ni ori okun yi soro. Ki won fi ote le igbese nla yi. Lehin eyi a o fun o ni oye. wink
IRE

IDAHUN SI I IDANWO TAFARI:
A. Pari owe yi:
1. Ailora ogongo, ko se fi we ti adigbonnanku
2. Datoro,datoro, datoro, agba ti o da toro, omi obe soro ni o mu
3. Idi ni iku igbin, ori ni iku alabawun (tortoise)
4. Onibaje ko won,eni rere lo won joju lo
5. A kii bara eni tan , ki a fa ara eni ni itan ya

B. Omo ilu wo ni o? O ti dahun wipe omo Iwo ni o
C. Fun wa ni ila maarun pere ninu oriki orile ilu tabi iseda ebi yin. Bi o ti le je ,wipe oriki Iwo ni o fun mi, apere yi se mu yangan
Art, Graphics & Video / Re: Editing Software by richylaw(m): 5:23pm On Jul 02, 2007
where do you live. I think I can be of help. Note that while premier and creative suite are available , After effects is yet to have a full scene release, sure you should understand this 'term'.
Holla to discuss
Art, Graphics & Video / Re: No One Is A Guru Here by richylaw(m): 5:19pm On Jul 02, 2007
Anyway sorry for the seemingly disappointment, but I personally did not come across your question, or maybe i had an over sight of it.
Nonetheless , I will be of the opinion that you should not condem anyone here, sure a good number of people do know bunch of stuffs. Timing might have been an hinderance to you having a comfortable response
Culture / Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by richylaw(m): 3:58pm On Jul 02, 2007
E seun o, eyin ara ilu,
Awon agba bo , won ni adan dorikodo o n wo se eye. E je ki a tun wo owo ti awe ti won n pe ni Olutomiwa yi , yio gbe ki a to da seria fun.

Mishoo nkankan grin
o ku atileyin o

Segoye, bi a ba ti so pe o ya , o ti ya na nu, yara ki o se kanmokanmo. E o ri owo alaago oba bi o ba ti di ale. Mo se ileri wipe iwuye yio ona kan pato leti jeki awon omo kaaro ojiire ti wo ti fe sonu si igberi okun ranti ile ki won si tun mo nipa awon asa ataye baye ti asa oyinbo ti fe bo mole

Tafari, lati ran o lowo, dahun eyokan soso ninu ibeere re. A o si fun o loye. Oni lati se ohun kan pato ti a o fi ri wipe ogidi omo yoruba ni o.
Culture / Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by richylaw(m): 2:10pm On Jul 02, 2007
tafari:

baale oko ilu, bawo ni oro wa?

O to ojo meta. Nje o ti setan lati je olotito eniyan , eni ti ki fi owo abetele gba oye tabi ipo bi?
Bi o ba je beeni, anfaani nla re fun lati dahun awon ibeere ojosi, mo n fi dao loju wipe yato si oriki orile re ti mo beere , fun mi ni idahun ti o pegede  si meji pere ninu merin to ku, iwo na yio si di oloye ni ojo kan na pelu Segoye.
Eyi ni esi lati enu awon igbimo ilu o.
Awon ara Iwo n ko , se o n gburo ile ?

Ire
Culture / Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by richylaw(m): 2:03pm On Jul 02, 2007
Segoye ati Desorlah, e ku akitiyan ati oro ilu yi . Won ni Satide ti o ba da, Alamisi re la a ti mo, mo fe ki e mo daju wipe, omimi kan o le miyin. E so fun awon ti won ba n gbe mu si yin wipe

Bi omode ba dari so apa
apa a pa
Bi omode ba dari so 'roko
Iroko a ko
Ojo ti omode ba dari so oruru
won a ti oko ruku e wa le.
opipi baramu baramu
adifa fun segbende awo okini
won ni igba oko
igba ada
won boke sote
oke oje oke omu
oke n bori won porogodo.

E ma soro , ki e ma yan fa n da

*singing* iwo lo loro ma so lo
oluwa lo foro si e lenu
iwo lo loro ma so lo

*still singing*
Ati moloye yi je iwo n na
iwo n papa
iwo n na

MUSO , MUSO , MUSO, MUUUUUSSSSOOOOOOOOOOOOOOOOOOOO!

Gbogbo ohun ti o n sele ninu aba ni mo n ri , mo kan fowo leran ni lati wo esin onisokuso eniyan ni o! Iyalenu nla lo  je fun mi lati ri wipe arakunrin yi tun lo fi ara re han ni  awujo awon omo igbo wipe ohun ni asoju yoruba. A bani l'oruko je eniyan. A mu ni bu ni eran Ibiye.
Mo duro digbon sehin yin mo wa n le fun enikeni ti ko ba fe mo iwon ara re.
Lehin ti o ti han daju wipe iyanse lodi ti de opin alagogo oba yi lu agogo kaakiri ni asale oni , wipe ojo Abameta ( ojo marun oni ni iwuye yin o)
Ire
Culture / Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by richylaw(m): 1:44pm On Jul 02, 2007
Olutomiwa
Awon agba bo won ni ohun ti o n wu ni lo n po loro eni, sugbon bi i ti oro arakunrin alasete ti won n pe ni Tomiwa  yi ko rara, Mo fe ki o mo wipe ohun ti a ma n se niyi na ni a ma n se te o. Se o mo wipe oro(word) ti o yo obi (kolanut) ni apo (pocket), o n na ni o n yo ida (sword) ni apo (scabbard). Fi akiyesi ati imo joko ki o ronu ara re wo daradara, mo fe  ki o se ayewo finifini lati oju iwe kini okun oro yi titi ti o fi de oju iwe kokandinlaadorun, ki o si so fun mi ibi ti o ti ri iru awon aworan alufansa ti o gbe si ori afefe yi.Asin de orun de. Bi iwo ko ba ni iberu eniyan , sebi o ye ki o mo wipe iberu olorun ni ipilese ogbon. Apara orisirisi ni a ti n se ni ori okun oro yi sugbon pelu oye , ogbon ati imo ti o ni laakaye ninu ni. Asa ominira oro ko gbehin sugbon pelu ikora eni ni ijanu ni. Omo Oodua toto ki i huwa bi eyi rara. Bi o ba je akiyesi ni o fe wa fun ara re , iba san ki o ro ona miran o.
Ajegbodo n we ni kun ra, oro re ti di ''dabi mo ti da ti n kole ewe ti paanu''. Mo le fiye o wipe bi o ko ba ro oro yi jinle daradara, ki o si yipada o le se okun fa fun o lati kuro ninu ilu yi, ati ni paapaa julo padanu eto re ni ile Nairaland.
Mo lero wipe bi aja ba n siwin o ye ki o mo oju olowo re o.
Abata loro eleyi o , bi a ba si na ni papa o di dandan ki o ta ba eniyan. Jowo fi oro mi se ogbon.

Baale Yoruba Thread.
Art, Graphics & Video / Re: Software Used For Animated TV Commercials? by richylaw(m): 1:11pm On Jul 02, 2007
Guess my previous post addresses more of the editing,
flash is okay
but Toonboom, max and maya with specified plug-in may achieve it as well
Art, Graphics & Video / Re: Software Used For Animated TV Commercials? by richylaw(m): 1:08pm On Jul 02, 2007
here are some high end stuffs capable of doing it.

after effects
Final cut pro
Shake ( though almost being dropped)
houdini
Culture / Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by richylaw(m): 5:26pm On Jun 28, 2007
ikamefa:

Baale Oko ilu mo waa oh! and you?

se e ti ri aworan oyan ragbada yen sha? shocked

I'm fine,
Oju abore kii ri ibi o, mo sare fi "sun shade" si oju ni bi mo se ko firi awon aworan afoniloju yen o. Ki Olorun ma ke de gba wa ke lowo bobo Olutomiwa yi ke!
Culture / Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by richylaw(m): 3:24pm On Jun 28, 2007
desorlah:


You guys need to see how wet i am now

Desorlah , oti o, ko tii ye mi daadaa. Se o da ice cream sara ni abi omo oni pure water lo ja ora omi si e lara ni, abi baba olowo fi moto ta omi si e lara. La oro yi kunnakunna o.
Culture / Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by richylaw(m): 3:20pm On Jun 28, 2007
Iyalode Ika , ewo ni toju, ki lo n sele, so wa pa?

Desorlah, mo wa ninu olanla ti Oluwa fi fun mi o, o ni ki n gunwa ki n si ma pase.

Je n soke Babe.
Culture / Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by richylaw(m): 2:14pm On Jun 27, 2007
Desorlah, I dey kampe o. A de tun ku bi oju ojo se ri o. Ma gbadun
Culture / Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by richylaw(m): 1:32pm On Jun 26, 2007
minute:

how do u say im bored in yoruba anyway?

grin mo bo 'bore' na ni! oniyeye eda
Culture / Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by richylaw(m): 1:36pm On Jun 25, 2007
ibinu kan o si. Se alafia ni o wa o. Ise nko? Se iyanselodi awon osise ti n ro le diedie
Fashion / Re: Are Hair Products Made Under-seas? by richylaw(m): 12:06pm On Jun 25, 2007
Let me laugh at this time grin, and later I will come back
Culture / Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by richylaw(m): 5:02pm On Jun 24, 2007
E ku irole o gbogbo eniyan, mo ki yin nitesoteso, mo kiyin ni tologun tologun o. Bawo ni ojo isinmi oni. Ati eni ti ko lo si church ati eyi ti o n ba brother Judas soro ayo kan na ni gbogbo wa n fe o. Eku faaji.

@ Dis Guy ,
Ta lo so fun o wipe yoruba ko ni 'h' ninu abd?. O wa o

A B D E E  F G GB H I J K L M N O O P R S S T u W Y

as highlighted 'E' has a dot underneath, so also is 'S' (pronounced 'sh') 'H' is pronounced as low tone 'i'.
PLEASE NOTE THAT I DON'T INTEND TO BE A TUTOR ON THIS , JUST A POINT TO NOTE AND HELP YOUR FUTURE YORUBA PHONETICS

@ Segoye

Akigbe Oba ti n sise re, gbogbo ara ile ni yio gbo ojo oye titun laipe.
Culture / Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by richylaw(m): 12:43am On Jun 22, 2007
Segoye , ti o ba ti fi ohun sokan pelu iyawo re tan ni ki o je kii n gbo o. mo n duro laafin.
Culture / Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by richylaw(m): 7:14pm On Jun 21, 2007
Isrealite, ni agbara olorun gbogbo wa , awon lobaloba ati awon ijoye yio ba o keye de imesi lojo oye re na. Oye a mori o ase
Culture / Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by richylaw(m): 7:13pm On Jun 21, 2007
Isrealite, eniti a ko fe nile re n jina. Atemi ati gbogbo awon lobaloba toku ti o je ore mi ni a jo de okemesi wa ba o keye o. oye a mori o ase.
Culture / Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by richylaw(m): 7:07pm On Jun 21, 2007
Oloye titun segoye ,e ku akitiyan o . Gbogbo bi yio se da na la n ba ka, bi a o se  alejo awon lobaloba ati awon eekan ilu ti o bo fun oye re yi na ni a n se o. Nipa ti sisun ojo oye siwaju , nitori iyanse lodi awon osise je ohun kan ti o se pataki. Maa fe ki iwo ati iyawo re ro daadaa ki e si je ki n mo ki ile ola to mo o. Ki a le mo bi a o se se eto.Boya o fe ki a sun siwaju ni tabi beeko.

Mo se akiyesi  iwe ifi pe eniyan ti o te, ko si oruko baale nibe o, ki lode de. Ha ha bi o tile je wipe Oba Seun ni oluaye (oba apapo), Sebi oba Richylaw lo sa n fi o joye abi o ti gbagbe wipe Abobajiroro ni o je ni , le ti yoruba  fun nairaland. E jowo e se atunse o.

Gbogbo ile , eku ikale o. Se enu n gbe yangan?

(1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) (11) (12) (13) (of 17 pages)

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 53
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.