Topsy25's Posts
Nairaland Forum › Topsy25's Profile › Topsy25's Posts
1 2 3 4 5 6 7 8 9 10 11 12 13 14 (of 14 pages)
IBK and my love, e fi omo ti won npe ni Ogbeni Kiraka yen sile jor. O fe ko yooba ni, e fun ni aye ![]() |
FL Gators:It means leave toyin alone ![]() Make d guy leave u for me abeg ![]() |
Moruru ni s'awo nile moruru, morere ni s'awo nile morere, oro ti okete ba ba ile so, ni ile ngba. Gbogbo eyin ota mi o, e maa wole beeeeeeeeeeeeeeeeeeeeeeeeeeeee ![]() |
jamace:Ologinni t'ajo de, gbogbo ekute ile e paramo Ipadabo abija re. Ode ti o ba gb'oju o gbodo duro de kinniun. |
IFELEKE:Awe o, we s'ore gidi o. Gbon 'ya mi re komi o ![]() |
FL Gators:Rara o Won ban mi o. Mi o mo bi ayoor se yo lori ise mi o ![]() Gbagbe nipa ifeleke ki o si f'ara mo mi. Ifeleke kan nparo fun o ni, o ti ni iyawo meji sile pelu omo meje ![]() |
FL Gators:Haba toyin Yeepa |
Fhemmmy:I agree with you 100% my friend. This is another case of someone seeking for the remaining 20% outside his/her marriage. From my own point of view, this woman is only looking for sympathisers and people that'll support her unholy affair with this new guy. Remember: "i cant imagine just to let him go like that". Dear Berit, you can make your marriage work. That your parents failed at theirs does not mean u will. Prayerfully talk with your husband and he'll come around. Shalom! |
FL Gators: Ye se wi si o fo mo ti l'oya Gbogbo awawi e yen o sise o, mo nife e, mo si fe fi e s'aya. Ti o ba feran mi bi mo se feran e, so fun mi maa si se bo se to |
FL Gators:Looking at your mouth, I know u'll like gaari Ijebu Hi NLs, I'm using this opportunity to inform you that come Saturday, 27th June, 2009; I'll be taking Toyinroyan (alias ebony) as my lovely wife in an holy matrimony. Venue: The Holy Cathedral, Ijan Ekiti or Iropora Ekiti (whichever we decide to use) Time: 10am prompt You're all invited. All other information will be duly communicated to you before the 'D' day |
I'm from Ondo state and happily married to a wonderful Ijebu lady. Though our decision to get married was met with some oppositions from my family, God gave us victory cos we carried Him along ![]() I was curious enough to ask some elders about the reason(s) for this tribal hatred (or whatever u call it). I was told that most Ijebu women have a way of dominating their hubands. The Ondo/Ekiti people also believe that once an Ijebu lady gains access to a man's home as the wife, she ensures the husband cut off any relationship he might have with his family including his parents. They even pointed to one or two families that such happened to. But my question is: is it good to generalize We shld strife to put an end to this Ekitis and Ijebus wahalases. ![]() |
FL Gators:We yoo p'aja lobo komi awe . Ko ba tia se temi, gbon ifeleke re. Me yoo b'omode kekere ni a du aya (ekiti kete) |
KAMOTEESI K'AGBAKO LODO ASEWO[center][/center] Awon yooba bo won ni: "afogbon ologbon sogbon o ni te boro". Owo awon agba yi ni mo ranti ti mo se pinu ati so itan kekere kan ti o sele si ogagun obinrin KAMOTEESI. Isele yi ni yio fi idi ti kamoteesi se feran obinrin mule. Ojo buruku esu gbomimu ni ojo ketala, osu kefa egberun meji odun o le marun-un lehin iku oluwa wa. Ni Irole ojo ti a nwi yi ni Kamoteesi ri omobinrin kan ni oju popo. Omobinrin yi dara, o pon, o singbonle o si lewa bii koro isin. Omo yi wo booda Kamoteesi loju to be gee ti won ni lati paaki oko ayokele won. Won se owo si omobinrin naa pe ko wa; ohun naa ti tele won wo oko lai beere ibi ti won nlo. Ni kete ti won te oko leti ni uncle Kamo ti beere oruko obinrin yi, o si dahun pe Blialu ni oruko ohun. Won fi oro jomitoro oro ki won to de ile booda wa Kamo. Bi won se wole, Kamo beere nkan ti Bilialu ma je tabi mu; sugbon omo naa ko oni ohun o je tabi mu. O ni ki Kamo wa se nkan ti o ba fe se (booda Kamo o fe se nkankan tele o, o kan fe mo omobinrin naa ni nitoripe isekuse o si ninu eje won). Sugbon yooba bo won ni: nkan ti o ba ma se eeyan ko gbo. Bi Kamo se gbo oro Bilialu ni kinni e gberaso, l'oba ki omo naa mole ti o si gbe wo iyewu lo. Won se ere ife fun bii wakati meta. Nigba ti o ya ni booda Kamo toro aye lati lo si ile iwe. Omo naa gba ni aye. Booda we tan, o si wo yara ibusun pada; sugbon Bilialu ti kuro ninu yara. O wo gbogbo ayika, o pe oruko re sugbon ko ri enikeni daa lohun. Eru baa o si pada si iyewu. Bo se de ori ibusun ti won se ti se ere ife, Iwe pelebe kan ni o ba ni ori ibusun naa. Bi o se mu iwe yi ti o si woo; ni o di letter ti Bilialu ko sii; ni ori re ba wu gboooooooo. O sinmi fun iseju kan ki o to ka letter naa. Ninu letter yi ni Bilialu ti so pe oku ni ohun, o tun soo siwaju sii pe Kamo o gbodo fi owo kan obinrin miran titi di ojo iku re pe ijo ti o ba ti dan an wo, gbogbo igba ni yio maa wu pe ki o ba obinrin sun, ti o ba ya, a maa ba eranko sun, bi o ba si pe die si, yio maa ba igi inu igbo sun. Booda Kamo duro fun odindi osu mefa ni alai ba obinrin sun. Igba ti won o le fi mo ara mo ni won ba lo si ile alasewo. Gbara ti won dide lori asewo yii ni o yira pada ti o si di Bilialu pelu erin muye lenu. Lati igba naa ni booda Kamo ti da bi won se da yi o ![]() |
dayokanu:Dayo, se iro ni mo pa mo e ni ![]() |
Eyin ara mi ninu tireedi yi, mo ni iroyin kan lati so fun yin o. Nipa dayokunnu ni. Nje e ti gbo Wipe kinni dayo fi ara pa ni ose ti o koja![]() Oro yi sele nigba ti dayo ati omo opelenge kan wo ile itura kan lo ni abule muwonleru. Awon mejeeji wa ninu iyewu fun odindi wakati mefa. Ni gbogbo wakati yi, ere gele ni awon mejeeji nse. Nigba ti won ti se ere yi fun bii wakati mefa ni dayo figbe ta wipe ohun gbe ooooooooo. O be opelenge titi sugbon iyen fi aake kori pe ohun si fe se ere sii. Ori ere yi ni won wa nigba ti a dede gbo: "puu". Aseyinwa, aseyinbo; kinni dayo ni o kan sinu kinni opelenge. Ni waransesa, ni a ti yo kuro ninu kinni opelenge ti a si ran an pada. Sugbon o seni laanu pe kinni dayo o dabi ti tele mo. Nitori naa kin TOYOSI ati TUBABIE ki won sora oooooooooooo. |
Yooba bo won ni: "agba o si mo, ilu bage; baale ile ku, ile d'ahoro". Se toripe mo fun ara mi ni aye ojo die ni toyin se fe ko oju mi si oorun ale Paga!!! o ma se ooooooo. "ologinni r'ajo, ile wa dile ekute" Se tori ise kekeeke ti omo ti won npe ni ifeleke yen so wipe ohun ko lo si ile egbon e (kii se ile daddy e o) ni o se wa nso wipe ohun ni o maa fe ![]() Emi o le maa ba ifeleke du iyawo o. Ti o ba fe se temi o mo bi o se maa ri mi ![]() |
chamotex:O maa takiti obo ni ![]() |
chamotex:Kamoteesi onisekuse, o kaabu omo odo rere Nibo lo salo lati iye ojo yi Mo ro pe ikan ninu awon omo elese tantirin yen ti fidi gbe e salo ni ![]() Laise aini aini, inu mi dun lati rii pe o ti pada wasi agbon awon omo yooba tooto. Ikilo Pataki: Gbogbo obinrin ti o wa ninu tireedi yi lo le we'nu si o, sugbon, sora lodo iyawo temi - Toyinroyan Bi beeko, , ![]() |
FL Gators:Toyin, ni odo temi iwo o ni orogun |
argent:Pele ore mi. Se o nbinu ni Ma beru, asiri e bu lodo mi ![]() |
Si iyawo mi adumaradan, Ojo kejila, Osu kefa, Egberun meji odun o le mesan Leyin Iku Oluwawa. Ololufemi owon, Inu mi dun gidigidi lati ko iwe kekere yi si o. Se daadaa lo wa gege bi mo se wa nihinyi? Emi ni igbagbo pe iru ategun alaafia ti o nfe simi ni ilu yii nde odo re. Bi o ba ri be, ope ni fun Olorun. Mo ko leta yi si o lati fi da e loju pe ife mi si o ko lakawe ![]() So fun bobo Ifeleke yen pe ere ti aja ba f'ogun odun sa, ko ni gba esin ni ojo kan. Bo ba wu, ki o fi gbogbo owo to ni laye ra isu fun baba, obi abata ati Ogede onigba omo ni mo maa fi gba e lowo e. Lakotan, itumo IJ City ni: Ijare City Ilu ti mo nmu e lo niyen Emi ni tire nitooto, Farotika ti won npe ni topsy |
debosky:Oro yi abi ominn, se toripe adajo ti o gboye dajo fun o lo se wa nfi obe eyin j'emi nisu Eni ani ko f'eni loju, ata niyen fi senu ![]() |
IFELEKE:Omo Ikun ekiti ni iyawo mi, nitooto, mo ti nmura ati lo gbe isu ati obi abata lo si ile popsi e ![]() |
debosky:Debo, debo, debo, eemelo ni mo pe o Ore mi ni o je o, o si dabi enipe o fe maa temi loju mole Se iyawo mi ni o npe ni elenu rirun ![]() Ijo ti o ba tun dan wo, o maa kan idin ninu iyo ![]() |
IFELEKE:Eh ehnnnn!!! iyeni wipe omo efon alaaye ni o ![]() wo, o o le ba mi du aya rara o, ti o ba gbiyanju lati bami du iyawo, efon ni mo maa ran si e ![]() |
FL Gators:Iyawo temi nikan, mo mo Ikun daadaa; koda, irin iseju die ni Ikun si IJ City. Jowo bami so fun baba pe ki won maa fojusona nitoripe laipe jojo emi ati awon molebi mi maa wa bawo lati wa toro e. Isu, epo, obi abata ati eran igbe ni a maa wa fi kan lekun lasan ![]() Ololufe mi tooto, emi naa ti misi re ju. Bi mo ba njeun, toyin ni, bi mo ba nsun, morenikeji ni, ti oga mi ba nba mi soro nibise, toyinroyan ni maa ma je lenu. Jowo tete kowale nitoripe oju mi ro mi o |
hi emeshot, this is my e address as per bulldog: toscotee2001@yahoo.com |
debosky:Debo, o ma se o, argent wa si ile odo me ni ale ana. O kunle pelu orukun e mejeeji o si be mi pe ki nma so asiri ohun fun e. O tun soo siwaju sii pe ohun maa fi gbogbo nkan ti mo ba fe te mi lorun ti nba ti le se nkan ti ohun nfe. Mo koko yari kanle, sugbon nigba ti o fe bere si maa sunkun, mo nilati gba fun pe mi o ni so fun e; mo si je ko ye pe ko si nkankan ti o le fi temi lorun nitoripe ko si nkan ti mo nwa lara obinrin ti toyinroyan o ni ![]() |
post pix: toscotee2001@yahoo.com |
argent:Ti o ba soro ju, mo maa tu asiri e fun gbogbo aye ni ![]() |
IFELEKE:Ife, ife, ife, eemelo ni mo pe o, ma je ki nbinu si o o. Gbogbo oruko ti fun iyawo mi nigba ti mo si nje oroko mi ni iwo npe eboni mi yiiiiiiii. Ma je ki nfi bi mo se je won e o ![]() Nipa ti ilu ria Emi naa rii pe ihuwasi awon ara ilu yen jo ara won pupo; sugbon mi o mo wipe Ekiti ni gbogbo won tele. Mo ma lo se iwadi finni finni lati fi idi oro re mule.Lakotan FI IYAWO MI SILE adie o ki nje ifun ara won o ![]() |
FL Gators:ebonyyyyyyyyyy, iyen nipe o ti gbagbe farotika oko e akoko Yooba ni: eyele o ni bonileje, ko bonilemu ki o dojokan iponju k'eyele o salo. Nje eyele tie o ti salo bayiiiiiiii ![]() |



gbon toyin re! 

