Topsy25's Posts
Nairaland Forum › Topsy25's Profile › Topsy25's Posts
1 2 3 4 5 6 7 8 ... 10 11 12 13 14 (of 14 pages)
chamotex:Saa ma gbe iranu e de odo iyawo temi. Nitori ojo ti o ba dan wo, mo ma ge opa ase sonu ni. Abi ki n kuku ge nisinsinyi ni ![]() |
chamotex:Kamoteesi abi kini won npe o, se iyawo temi naa lo nwenu si beyen E wo ikoko dudu ti o npe ketu ni dudu. Iwo orobinrin dori yi ![]() Asewo buruku. Jabo jorrrrrrrrrrrrrrr ![]() |
IFELEKE:Iwo ti gbagbe ni wipe laiku egiri enikan o gbudo fawo e se gbedu. Mo wa laye o fe gbe'su lo s'ado; ko je je be. O dabi enipe o mo eni ti o nba du iyawo; ti o ba fe ki nfi bi mo se je won e, tete yaa jawo o. Bi bee ko, wa kan idin ninu iyo ![]() Asa re nwolugu, nwolope, o si fe kolu oruleee o ![]() |
JustGood:Exactly my thought!!! |
IFELEKE:Gbagbe nipa magun jorrrrrrrrrrrr Igbagbe lo se o, se o mo pe awon agba ma nwo magun soke ti wa se nkan ti won ba fe se. Leyin ti won ba ti gbadun ara won tan, won a wa da magun naa pada.Sugbon emi o ni se bee fun toyin o, mo maa fun ni ero ni ki magun naa ma baa se ni jamba ![]() |
chaircover:Gbam!!! |
dayokanu: ![]() |
dayokanu:daaaaaaayo, oni bara re nbole bo o. Kaka ki eku mi ma je eree toyin, yio fi sawadanu ni ![]() |
Si Toyinrayo, Ojo ketalelogun, osu kerin, Egberun meji odun o le mesan leyin iku oluwa wa. Ololufe mi owon, Inu mi dun lati ko iwe kekere yi si o ni idahun ibeere ti o bimi ninu leta ti o ko simi kehin ati lati je ki o mo bi ife re ti to ni okan mi. Lakoko, jowo mase binu pe mi o ni le si aso l'oju eegun fun o nisinsinyi; ti a ba foju kanra ni wa mo eni ti nbe nidi oro ti oro fi nke. Siwaju sii, dayo daruko ogbeni kan, o ni iwo ati onitohun ni nkankan papo, se ooto ni Irufe ore wo ni iwo ati e je gan an atipe kini o wa laarin yin? Jowo ma ko oju mi si oorun ale o nitoripe iwo gan an ni okan mi yan laayo Lakotan, iru ife ti mo ni si o ko se e fenu so, ife eleyele ni, ki ise ife adaba rara. O pe ti mo ti nri eye, sugbon lojo ti mo ri okin ni mo mo pe aye ku sibikan; o pe ti mo ti nri obinrin, sugbon lojo ti mo f'oju ri adumaradan ejiwumi temi, lojo naa ni mo mo pe mo ti de waasinmi |
dayokanu:Tani ni eni naa. Tani o to gbena woju ekun Ki onitoun sora o ki gbangba ma baa dekun; ki kedere ma baa be wo ![]() |
IFELEKE:Ebi npa mi ni, mo si fe mu oyan ![]() |
iice:Please note that marriage is much more than boyfriend/girlfriend relationship. Wait for ur time ![]() |
Between my wife and I, there is no secrets. She has the right to pick my phones and I have equal right. I believe both of us are one and we do things together. Basically, I believe if u dont have skeleton in ur cupboad, u wont prevent ur spouse from touching or using ur phones. |
*Toyinrayo:Haba! So we can u whatsoever we like with u, including beating ![]() |
*Toyinrayo:eleyi ti won npe ni morenike, ebony, toyinrayo, toyinroyan etc. ohun gan ni mo fe. Sigisigi aya e lo wu mi, pepe eyin oju e si ndami lori ru. Nitooto, ti dayo kunu o ba sora lodo omo yen; mo maa pa ni Se toyosi o to fun o ni Adumaradan mi owon, iwo saa ti se temi, ki o si fi eyi ti o ku sile fun mi |
tpia, emeka and udezue; una well so |
yusufade:You have a choice. don't u ![]() |
E jowo e ja mi si: won ni toyinroyan ni ojo iwaju gan ni Se ooto ni Won tun ni o ni apoti aje, o dudu bi koro isin Bi o ba je be; Ifeleke, toyin ni mo maa mu o |
ok o toyin royan nko ![]() |
Kunle, you or anybody else do not need to judge or critisize any pastor (real or so-called), what we need is real prayer for the country and christiandom. we really need God to deliver us from these angels of doom. |
these are the kind of leader we need in this country. the old and aimless ones shld be slaughtered. |
~Lady~:hello there!!! it seems u're not getting the poster's point here. The guy is not saying preaching the gospel on air is wrong or bad; but that it is unchristlike to beg for money via the preaching of the gospel. if you're truly sure that God sent you to preach the gospel via the TV, then you don't have to beg cos the God that sent you will surely provide the money u need to do His work in such a way that'll u'll know its the hand of God. Was He not the one that commanded raven to feed His prophet? x-tians have been charged to preach the gospel; but I never saw where begging for money was included in the instruction our Lord gave us. Freely have I given you, freely give. Jesus once asked: "if I come back to the earth, will I meet faith , "? And I wonder ![]() |
there is one adage in Yoruba which says: ayangbe aja ma ndun, " meaning well-roasted dog meat can be very delicious!!! (didn't finish the adage) If I should give every one of you trying to crucify those of us who eat dog meat a well-roasted one, I bet u'll beg me for more. Nonsense ![]() |
E pele nibi o Se daa daa le wa E jowo mo ni ibeere kan: mo nwa omobinrin ti o ba dun, adumaradan ati eleyin ege ti o si ni iwa daa daa. E jowo e je ki nmo boya iru omo bee wa ninu tireedi yio E se pupo |





Se ooto ni