Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,152,757 members, 7,817,092 topics. Date: Saturday, 04 May 2024 at 04:46 AM

If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! - Culture (14) - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! (375902 Views)

If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! / Do You Speak Yoruba? (2) (3) (4)

(1) (2) (3) ... (11) (12) (13) (14) (15) (16) (17) ... (167) (Go Down)

Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by israelite(m): 10:39pm On May 26, 2007
gbogbo eyin ti en soro se emo abule yin, elomi ko mo agbole won eko mo pe omo OYO, OSUN, ONDO, EKITI, KWARA niyin oda ti elomo ile oooo, emi ti so temi
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mukina2: 10:40pm On May 26, 2007
Omoge yeah grin

ki lon sele cheesy
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by omogenaija(f): 10:41pm On May 26, 2007
o de so funmi angry
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by haywhy(m): 10:42pm On May 26, 2007
Muki ko dakan mo!
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by nazzyon(m): 12:01am On May 27, 2007
Etiregbo na. Kini awon omo Odua n se lo ri oro awon Ilu wa gan na.

Ti eba losi awon ilu kereje kereje ati jo ni awon ilu bi Enugu, Portharcourt ara orisirisi ni won ti n da si be. Sugbon kaka ki ilu wa ko gboro si otun n lagbara si ni.

Ki lowa de ti awon olowo inuwa ko ti le fe da nkan ari dun nu kale si ilu gan na. Aya fi ki won ma losi ilu okere (Ilu Oyinbo) lama se nkan mere mere si be.


Eyin ti eri jaje, eje kki aran awon ara iyoku lowo. Ko pa dandan ki eniyan kan ko fun eniyan ogorun ni nkan. Tori pe o benbe ko benbe ara ni yio da ni ile aye eni ti a se ni ore.

Eje ki a sa kiyesi eleyi. Edakun dabo, egbe oro yi yewo. KKo ma lo je pe ti ohun kan ba sele ni lu awa Yoruba ni yio fori fa.

Emi wi temi o.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by richylaw(m): 1:52am On May 27, 2007
Nite Angel
Ore wa ko ti i se tan lati se ohun ti mo ni ko se ni o. Eledua a je ki o le teti gbo.

Nazzyon
Ta a ni ko mo wipe iwa "bi isu eni ba ta a do wo bo" ni ogunlogo awon eniyan wa n hu, koda, mi o ro wipe mo le yo ara mi ati iwo olukowe gan sile!

Isrealite
Nje o da o loju wipe o mo ile, se loto ni o wa lati Imesi? ti o ba je be, ki ara re si ile ki a gbo ( emi ko beere oriki idile o, oriki orile re - Imesi ni mo n bere) ti o ba see eleyi n so ibi ti mo ti wa fun o

Mukinatu
Awo mi Haywhy so fun mi wipe o kago sile nigbati emi ko si nile. Ma binu wipe o  o ba mi o, mo lo si ipade awon ilu ni o , mo gba ibe ya si ti awon olomo ile, nigbati a pari ni be ni mo wa lo si ti elegbe awo. Mo lero wipe o o tun yoju siwa laipe. (your interpreter should be able to  give you  a prescise literary meanings to the above) wink

Omogenaija
Won leyin na be wa wo , e se o a n ri owo yin . Ao ma ri yin ba o
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by haywhy(m): 2:02am On May 27, 2007
Ago oni ile ooo!
Agba awo, o se mi naa ni kayefi ni igba ti nko ri yin, sugbon mo ti mo pe bi oro ilu yoo se dara le n ba kakiri!

Emi gan alara yoo fe fi stai bisi die lenu ijo meta yi, sugbon eti oba ni ile, eti oba ni oko nko ni se alai kan iyara awa omo odua paapa julo abala awa awo!

Mo lero pe enikankan o ya ju sawo oo! Ko je je be!
Ao ma rira oo, Ki eledua ki o ma ko atunri!
Ase oooooooooooooo
Ase koni se aise, to ri sise sise bayi oun ni ti ilakose
Odigba oooo
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by nazzyon(m): 2:05am On May 27, 2007
Lowo ti mowa yi mo n gbero lati pada losi ile eko ni. Owo ti mo n ri ni mo hun tele jo fun ile eko na.

Mii o toka si eni ti kkoi ti rije. Awon ti amo wipe won totan ni mohun so.

Ati wipe mio toka si eni kokan. Oye ki a gbimoran po ni, ko kin se wipe ka ma wa ohun ti yio pani lara kiri.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by haywhy(m): 2:22am On May 27, 2007
Emi gan alara n wa owo lati gba afefe ile Naijiria sori! Paapaa julo mo tun n wa asiko tori mo fi ibinu bisi lowo yi!
Igbagbo mi ni wipe eledua yoo ran gbogbo wa lowo ooo
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by ayefele200(m): 3:21am On May 27, 2007
eyin omo olukoso daaaaaaaaaaaaa
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by ikamefa(f): 3:28am On May 27, 2007
mukina o gbo nattin! grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by ayefele200(m): 3:29am On May 27, 2007
were, omo ale, tani iwo,
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by ikamefa(f): 3:32am On May 27, 2007
ayefele200:

were, omo ale, tani iwo,


right back atcha! a million fold


Kiss my ass cheesy oponu!

Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by damsol(f): 3:32am On May 27, 2007
enle ni ibi bayi o
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by ayefele200(m): 3:33am On May 27, 2007
oloribuku, omo iya ole, ko ni da fun awon iya ti obi iya laya baba laya momo re, o ni ji re, omo ABIKO, omo ofo,omo adanu,oloribobo
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by damsol(f): 3:36am On May 27, 2007
ewo lon shele ni ibi yi?kilofa eebu?
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by ayefele200(m): 3:37am On May 27, 2007
kin pun ni, gbeborun, OMO AKOGBA
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by damsol(f): 3:43am On May 27, 2007
hey hey ewo lo fa iranu?ti o ko ba fe kin wo e nile,ma ta si mi rara atiu rara ni
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by ayefele200(m): 3:44am On May 27, 2007
ko ni da fun eee, even awon ebi ee gan, aye iya re ko ni daa, wo mi le oloribu
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by damsol(f): 3:50am On May 27, 2007
any curse without a cause can never align.i cannot be cursed because who God has blessed,no man can curse,curses are for cursers and whatever you give shall be returned to u in hundred folds.am so sorry but i refuse to be cursed thats why i will have to say back to the sender in hundred folds.let every thing said about me and sent to me by u be returned to u in hundred folds.see ya around.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by ayefele200(m): 3:54am On May 27, 2007
ikan ti aba wi fun OGBO o gbo, ikan ti aba wi fi ogba o gba
so ri lati oni lo, o tun ri ikan rere mo, so ri OKO baba re yo pora ni, iwo omo abi ko yi,olofo omo adanu, so ri OBO iya re ,, yi ma so mi la to ni lo, OBO re gan fun ra re, yio di, iwo omo ti oni ri OJUMOMO ola yi, omo ale,omo ako gba
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by damsol(f): 4:05am On May 27, 2007
any curse without a cause can never align.i cannot be cursed because who God has blessed,no man can curse,curses are for cursers and whatever you give shall be returned to u in hundred folds.am so sorry but i refuse to be cursed thats why i will have to say back to the sender in hundred folds.let every thing said about me and sent to me by u be returned to u in hundred folds.see ya around.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by richylaw(m): 10:10am On May 27, 2007
Arabinrin Damsol ati Ayefele,

Se e mo ara yin ti ri ni ibi kan ni , eyi ma toju su mi o, ki lo ti i fa epe to bayi. Be e obinrin ni eyin mejeeji.Mo n fi asiko yi petu si eyin mejeeji nikun, ki e fi owo wonu o. A kini tan n je akini tan , a fini han n je afini han, ewo ni pele ara ijaye niwajude Ogunmola owe yoruba. Se eyin o mo wipe eyin lohun ni , omode siwo lu iroko o n boju wehin , o ro wipe ojo ti a a ba na oluwere ni oluwere n pa ni je ni owe yoruba. E jowo e jeki a siwo kuro ninu epe sise yi o. Ohun to ba iran yoruba de ibi  to wa loni re o. uhn
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by hotchic1(f): 10:48am On May 27, 2007
Eyin sisi wa,ki wo wa lo fa epe bayii,eyii omo da,omo Olorun ki ma sepe,ke ya ba ara yin soro ki e ki owo iwa palapala bi ilu apala yen bole ooooooooo.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by ijogbon(m): 11:13am On May 27, 2007
akika

abo oro la'n so fun omo lu'wabi ti'o ba de inu re a'a si di odi di.

Imoran re'e fun yin O. E se a ki'yesi.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by obonyunmi(f): 5:20pm On May 27, 2007
mo dupe pupo lowo eyin ti eba mi da si airi oko do mi - adura mi ni wipe - oluwa oba olojo eni yio fun yin ni edun okan yin - bo se oko ni - bo de se obo ni - igbabo yin yio fun yin ni nkan na ti e ba beere lowo oluwa.

Emi ti ri oko do leni ati lana - ni se ni oko okunrin nan gun bi ejo, oko na gun to bi wipe - ti oba lo mo ibadi e - yio ka yipo ni eemeji - sugbo - bi ose gun to na ni o dun to - gege bi adura mi - oluwa yio pese oko ati obo fun eyin omo Nigeria rere to ku seyin. Ni temi, adura mi ti gba.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mukina2: 5:24pm On May 27, 2007
bawoniiiiiiiiiiiiiiiiii
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by hotchic1(f): 5:37pm On May 27, 2007
daada ni.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by omogenaija(f): 5:59pm On May 27, 2007
ewo lo se ?
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Dapo4u(m): 6:45pm On May 27, 2007
O ga ooo!!! Oloopa ewo ni tepe? iru iwa palapala wo ni eyi? ha! ha! omo yoruba atata kii siwa wu,omo ti ekun ba bi,ekun ni jo.Nigba ti eki se osomaalo, ewo ni tepe? E mi ro wipe fooromu(Forum) ti a wa yio fun wa ni anfani lati se iranti ibi ti ati wa.O si wa ki epe monle bi eni wipe iwo gangan ni elepe ti ilu epe.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by hotchic1(f): 6:46pm On May 27, 2007
mo se t'Olorun ooooooooooo
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by hotchic1(f): 6:47pm On May 27, 2007
Dapo4u:

O ga ooo!!! Oloopa ewo ni tepe? iru iwa palapala wo ni eyi? ha! ha! omo yoruba atata kii siwa wu,omo ti ekun ba bi,ekun ni jo.Nigba ti eki se osomaalo, ewo ni tepe? E mi ro wipe fooromu(Forum) ti a wa yio fun wa ni anfani lati se iranti ibi ti ati wa.O si wa ki epe monle bi eni wipe iwo gangan ni elepe ti ilu epe.

Ko ye mi tooooo,bo ya ni gba ti ot bawon so nisin yi,won a je gbo.

(1) (2) (3) ... (11) (12) (13) (14) (15) (16) (17) ... (167)

Modern Traditional Attire Of Nigeria / Pictures Of Nigeria Traditional Attire / Igbo Names & Their Meanings

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 33
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.